Ohun méje tí Bíbélì sọ nípa jijẹ òbíÀpẹrẹ

7 Things The Bible Says About Parenting

Ọjọ́ 4 nínú 7

Jíjé òbí jé ohun tó sòro, tí kò le ati tó rorùn.Ó rorùn fún wa láti fi tìdùnnú-tìdùnnú rànti àwon omo wa nígbà tí wón ń dàgbàbí,bí wón se kéré tó àti bí wón se fani mọ́ra si,sùgbón ó sòro gidi-gan láti ràntí bí wón se jé ìbúkún tó ní ìrọ̀lẹ́ ojọ́ ìsẹ́gun kan tí wón kígbe ní kòrò, tàbí nígbà tí a ñ sáyípadà ohun tó fé dà bí ẹgbẹ̀rún ìtẹ́dìí ọmọdé ní ojó kan!

Àmó, nípasè àìfaroro jíjé òbí, 1 Tẹsalóníkà 5:16-18 lè ràn wa lówó láti rí i kedere àti fí ojú tuntun wo nípasè àwon ìgbà àìfararo.

Kún Fún Ìdùnnú Nígbà gbogbo

Má ṣe sọ̀rètí nù ní àwon àkókò tó sòro yen. Ràntí pé jíjé òbí jé ìpè ọlọ́kàn títọ́ àti èyí tó bòwò fúnni, àǹfààní tí Olórun tí fún wa, àti òkan tí a yóò rí àwon èso wón ní ojó kan, kódà tí kò bá dá bí bée lónìí. Wé mó ohun ìdájú gan-an pé Olórun fún wa ní olá yìí.

Má see Síwọ́ Gbígbàdúrà

Kò sí ohun tí àwon omo wa ní-lò jù wíwàníhìn-ín Kristi lo nínú ayé wón. Nítorí náà, ohun tó se pàtàkì jù lo tí a le se gégé bí òbí ní láti wè àwon omo wa sínú àdúrà. 1 Tẹsalóníkà 5:17 so fún wa láti se lemólemó nínú àdúrà jálẹ̀ ojó—kódà nígbàtí ó bá dá bí gbogbo nñkan ń yí biiri yípo wa.

Kún Fún Òpe

Kíkún fún òpe fún àwon omo wa ń rorùn ní àwon ìgbà kan àmó nígbà mìíràn ó má le. Sùgbón ní àwon ojó tó le, ràntí pé o kò dá wà nìkan. Nígbà tí ó sáré lo tó ñ sòfo, èyí jé ọ̀kan lára àwọn àkókò tó dára jù lọ láti wà sọ́dọ̀ Olórun nínú àdúrà. Béèrè lọ́wọ́ Rẹ̀ láti so ìdúnnú rè dòtun, àtipe dúpé lówó Rè fún àwon omo rè. Ó lè àtipe Máa fún ó lókun, ìdúnnú, àti ìmoore tó ní-lò. Àti tí a bá kó láti simi le Olórun ní àwon ojó tó sòro tí jíjé òbí, a kò le ṣe ìrànlówó ṣùgbón dúpẹ́ fún àwọn ọmọ wa!

!

Casey Case

Aṣáájú Àtìlẹ́yìn Tí YouVersion

Ìwé mímọ́

Ọjọ́ 3Ọjọ́ 5

Nípa Ìpèsè yìí

7 Things The Bible Says About Parenting

Itọju ọmọ jẹ ohun tí o le púpò, pàápàá nínú ipò ti o dára jùlọ. Nínú ètò ọlọjọ méje yìí, àwọn òbí - ti wọn tún jẹ oṣiṣẹ ní YouVersion - pin nípa bí wọn se nlo ẹkọ nínú ọrọ Ọlọrun fún nkan tí o se pàtàkì yìí. Ètò ojoojumọ wá pẹlu ẹsẹ Bíbélì alaworan tí yíò ran ọ lọwọ láti pin nípa ìrìn àjò jíjẹ òbí n'itire.

More

A fé láti dúpe lówó YouVersion fún ìpèsè ètò yìí. Fún àlàyé díẹ si, jọwọ lọ sí: http://www.bible.com/reading-plans