Kristi Ọgbọn ati Àgbàrá ỌlọrunÀpẹrẹ
Ohun Tí Jésù Dà Fún Wá
Nipa àṣàyàn ti Ọlọ́run a pè wá sí inú Kristi. Kii ṣe nipa imusẹ wa tàbí nipa fifi àrà mọ ijọ kan ṣugbọn a ṣe Kristi ni Ọgbọn fún wà:
'Ọgbọn' nipa ìyí tí a fi ni ìmọ ati oyè Ọlọrun ti o ran wa lọwọ láti lè sọ nipa Kristi ati lati lè jẹ ẹlẹrìí sí ìhìnrere Rẹ fún awọn ti ko mọọ tabi gbagbọ.
Kristi tún di 'Òdòdó' fún wà, nipa eyi awa dí "òdodo Ọlọrun" nipasẹ Kristi. Torí eyi Ọlọrun O ri wà ninú ẹṣẹ wa to ti kọja, àṣìṣe wa tàbí òdodo ti àrà wá ṣugbọn O ri wà láti in ú Kristi.
Nipasẹ Kristi a ni ìwẹnumọ́; nipa Ọrọ Rẹ a ya wa sí mimọ.
Ni ìparí, nipasẹ Kristi ani ìràpadà, a ra wa pẹlu oyè kan, Kristi lò sán oyè nà nipa ikú rè. Kristi dá fún wa ohungbogbo ti a olè dà nínú Ọlọrun.
Siwaju kika: Genesisi 14:1-16, Jóṣúà 6:2-5, Awọn onidajọ 6-8, 2 Kíróníkà 20:1-24
Adura: OLUWA, Mọ yọnda àrà mí fún ipè Rẹ lati ṣe òhún to fẹ kín ṣe.
Ìwé mímọ́
Nípa Ìpèsè yìí
Ìgbé ayé ninú Kristi láìsí iyemeji tayọ ìgbé ayé ẹlẹran àrà, ẹsìn tabi aṣa bi ìwà mimọ ati titẹle òfin. Ṣugbọn o jẹ ìgbé ayé àgbàrá ati Ọgbọn, ìgbé ayé tí a ni lati inú iyé ainipẹkun Ọlọrun. Kristi wà sáyé láti gbé 'nú rẹ àti lati fi ìyè hàn onigbagbọ nínú rẹ, onigbagbọ nínú Kristi jẹ alabapin àyè yìí nipasẹ dídì Atunbi ati Ẹmí Mímọ t'in gbé inú wọn.
More
A yoo fẹ lati dupẹ lọwọ Kristi Ọgbọn ati Àgbàrá Ọlọrun fun ipese eto yii. Fun alaye diẹ sii, jọwọ ṣabẹwo: https://www.facebook.com/gideon.adeoye?mibextid=ZbWKwL