Kristi Ọgbọn ati Àgbàrá ỌlọrunÀpẹrẹ
Ọnà Ọlọrun Tayọ Tiwa 2
Ìlépa lati mọ Ọlọrun nipa ọna ìmọ ìjìnlẹ̀ ati iwadi fún awọn ẹlòmíràn ti yori sí iyemeji, ero ati ìmọ àiní Ìgbàgbọ ninu Ọlọrun, èyí to ti lè wọn jìna sí Ọlọrun.
Asán kan na lotin jasi lati ìgba dé ìgbà, èyí to jẹ ẹri pé Ọlọrun ki nṣe ohun ijinlẹ afojuri tí alè fi sí abẹ ìsàkóso wa tàbí ẹrọ kọmputa ati jigi iwadi nkan.
Ìmọ ìjìnlẹ̀ dara nínú iwadi ohun tí Ọlọ́run á ṣugbọn ko ni àṣẹ nínú pipinu pé Ọlọrun lo da gbogbo agbayé. Ohun ibà wu ko jẹ, bóyá àmì tabi ìmọ ìjìnlẹ̀ ni a nwa, Titobijulo Ọlọrun dúró, òsì nṣe awọn ohun tí onṣe ni ọnà to fi ogo fún
Ìwàásù ìhìnrere jẹ ifihàn eleyii. Ọlọrun o bati Yan ọ̀nà mii to dára jùlọ fún ìwàásù ìhìnrere pẹlu Ohun gbogbo ni ikawọ Rẹ ṣugbọn o Yàn ọnà to rọrùn to dàbí ọnà òmùgọ ṣugbọn eleyii ni ọnà nikan to yọrí sí ìgbàlà.
Siwaju kika: Iṣe 10:1-5, 17:23-26
Adura: OLUWA, Mo gbagbọ ninù ona ìhìnrere ti O ti Yan.
Ìwé mímọ́
Nípa Ìpèsè yìí
Ìgbé ayé ninú Kristi láìsí iyemeji tayọ ìgbé ayé ẹlẹran àrà, ẹsìn tabi aṣa bi ìwà mimọ ati titẹle òfin. Ṣugbọn o jẹ ìgbé ayé àgbàrá ati Ọgbọn, ìgbé ayé tí a ni lati inú iyé ainipẹkun Ọlọrun. Kristi wà sáyé láti gbé 'nú rẹ àti lati fi ìyè hàn onigbagbọ nínú rẹ, onigbagbọ nínú Kristi jẹ alabapin àyè yìí nipasẹ dídì Atunbi ati Ẹmí Mímọ t'in gbé inú wọn.
More
A yoo fẹ lati dupẹ lọwọ Kristi Ọgbọn ati Àgbàrá Ọlọrun fun ipese eto yii. Fun alaye diẹ sii, jọwọ ṣabẹwo: https://www.facebook.com/gideon.adeoye?mibextid=ZbWKwL