Kristi Ọgbọn ati Àgbàrá ỌlọrunÀpẹrẹ

Kristi Ọgbọn ati Àgbàrá Ọlọrun

Ọjọ́ 4 nínú 7

Àgbàrá ati Ọgbọn Lati Jogún Ayé Fún Kristi

Ìhìnrere l'aini ṣe pẹ̀lú iyasọtọ tabi iṣẹ inunibini ẹyà, íkoritá Orílè-èdè, àṣà tabi iyatọ ẹsìn ati iyasọtọ to tile dá kalẹ làrin awọn eniyan, laini ṣe pẹlú bi awọn eniyan ti ṣe ri, gbàà tàbí dójú kọ.

Ṣugbọn, koja àkókò ẹgbẹrun meji, ìhìnrere kan nà ti wọ awọn ibi tí o léwu ti a ro wipe ole dé, awọn ènìyàn ti o jẹ jagidijagan ati aṣòdì sí ìhìnrere ati itẹsiwaju ti wa sí oyè Kristi ati ìgbàlà rẹ.

Kinidi? Kristi to jẹ aworan ìhìnrere ti an wàásù ni Ọgbọn ati Àgbàrá Ọlọrun nipa eyi a jogún ayé yí fún Kristi ati ìjọba Rẹ¹

Tobẹ ti àwọn tó fi igban kan jẹ idojukọ ìhìnrere ti di oludari ati olú f'aya Rán ihinrere wọn ṣe agbatẹru rẹ dè awọn orilẹ-ede. Ọlọrun pe ọ lati dára pọ itankalẹ to lagbara yi, ṣe wàá dahun sí ipè yi?

Siwaju kika: Ifihan 11:15-17, Orin Dafidi 2:1-12

Adura: OLUWA, Mọ yọnda àrà mí bi irinṣẹ lati ròhin Ọgbọn ati Àgbàrá Rẹ káàkiri Ayé.

Ìwé mímọ́

Ọjọ́ 3Ọjọ́ 5

Nípa Ìpèsè yìí

Kristi Ọgbọn ati Àgbàrá Ọlọrun

Ìgbé ayé ninú Kristi láìsí iyemeji tayọ ìgbé ayé ẹlẹran àrà, ẹsìn tabi aṣa bi ìwà mimọ ati titẹle òfin. Ṣugbọn o jẹ ìgbé ayé àgbàrá ati Ọgbọn, ìgbé ayé tí a ni lati inú iyé ainipẹkun Ọlọrun. Kristi wà sáyé láti gbé 'nú rẹ àti lati fi ìyè hàn onigbagbọ nínú rẹ, onigbagbọ nínú Kristi jẹ alabapin àyè yìí nipasẹ dídì Atunbi ati Ẹmí Mímọ t'in gbé inú wọn.

More

A yoo fẹ lati dupẹ lọwọ Kristi Ọgbọn ati Àgbàrá Ọlọrun fun ipese eto yii. Fun alaye diẹ sii, jọwọ ṣabẹwo:  https://www.facebook.com/gideon.adeoye?mibextid=ZbWKwL