Kristi Ọgbọn ati Àgbàrá ỌlọrunÀpẹrẹ

Kristi Ọgbọn ati Àgbàrá Ọlọrun

Ọjọ́ 1 nínú 7

Ìhìn Rere Àgbàrá

Sisọrọ nipa agbelebu ni sisọrọ nipa ohun tí Kristi ṣe; iṣẹ ìgbàlà ati ìràpadà ti o ṣe la ṣepe, ìdí tí o fi wí lori Àgbélèbú pé "oti pari".

Báyìi, ìwàásù nipa ìhìnrere ni ìwàásù àgbàrá Ọlọrun sí Ìgbàlà ati Ìràpadà ti o yọrí sí iyipada ayé awọn ènìyàn. Eleyii jẹ iyanu ainiye ti o ṣe ṣàlàyé ṣugbọn to ṣe fojú ri.

Njẹ ìhìnrere Kristi yíò ṣe gbagbọ kíákíá ti o bá nisè pẹlu àṣà irubọ ati ètùtù ni íkoritá kan? O lè ri bẹ̀, ṣugbọn O ṣe gbogbo rẹ nipa igbagbọ kí alè mọ pe Ìgbàgbọ ni ohun tí a nilo lórí ohun tí Kristi ti ṣe ni ọpọ odún sẹyin.

Eléyìí dàbí ohun to dára jù láti jẹ òtítọ, ẹtan ti o ṣe gbagbọ fún ọkan to kún fún àgbéyẹ̀wò, lọrọ kan "ọrọ òmùgọ". Iṣẹ Ọlọrun nígbà gbogbo amáa tayọ ero Iwadi eniyan, láì ribẹ ko ni jẹ Ọlọrun. Ohun to nbere fún ni ko nigbagbogbo.

Siwaju kika: Romu 1:14 -18

Adura: OLUWA, mo gbagbọ ninù àgbàrá ìhìnrere Rẹ sí ìgbàlà ati ìràpadà.

Ìwé mímọ́

Ọjọ́ 2

Nípa Ìpèsè yìí

Kristi Ọgbọn ati Àgbàrá Ọlọrun

Ìgbé ayé ninú Kristi láìsí iyemeji tayọ ìgbé ayé ẹlẹran àrà, ẹsìn tabi aṣa bi ìwà mimọ ati titẹle òfin. Ṣugbọn o jẹ ìgbé ayé àgbàrá ati Ọgbọn, ìgbé ayé tí a ni lati inú iyé ainipẹkun Ọlọrun. Kristi wà sáyé láti gbé 'nú rẹ àti lati fi ìyè hàn onigbagbọ nínú rẹ, onigbagbọ nínú Kristi jẹ alabapin àyè yìí nipasẹ dídì Atunbi ati Ẹmí Mímọ t'in gbé inú wọn.

More

A yoo fẹ lati dupẹ lọwọ Kristi Ọgbọn ati Àgbàrá Ọlọrun fun ipese eto yii. Fun alaye diẹ sii, jọwọ ṣabẹwo:  https://www.facebook.com/gideon.adeoye?mibextid=ZbWKwL