Kristi, Ifihàn Ọlọrun Baba sí WáÀpẹrẹ

Kristi, Ifihàn Ọlọrun Baba sí Wá

Ọjọ́ 7 nínú 7

Ìgbé Ayé Iṣẹgun

Iriri ifihàn Ọlọrun amáa mu ìyípadà tó pé wá nínú èèyàn. Lati irisi bíbélì fún àpẹrẹ Isàiá, a fọọ mọ, ni àpẹrẹ ti Mósè Ògo Ọlọrun bá lè tí ntàn tíó sí ṣe rí. Bori gbogbo rẹ, yóò mú ọ wá sí iwájú òtítọ Ọrun", tíó mu kiõ máa rí àti máa dúró lókè ni iṣẹgun.

Ifihan Ọlọrun sí ọ afi ọ sí ipò anfaani fún iṣẹgun. Wàá rí àwọn ohun T'ọrun, wa gbé ìgbé ayé Ọrún. Ifihàn Ọlọrun yíò mú ọ wọnú imọlẹ, yíò sọ ọ ji nipa tẹmi, yíò fún ọ ní òmìnira, ominira kuro labẹ ẹṣẹ ati ìjọba ẹṣẹ ati ẹran ara. Ẹṣẹ yóò sọ agbára nú lori re, awọn iṣẹgun iyokù yóó tẹle.

Kiyesii pe àwọn angẹli jẹ àrà ìpèsè Ọlọrun lati ràn ẹ lọwọ gẹgẹbi ajogún ìgbàlà Rẹ fún imuṣẹ ètò Ọlọrun fún iṣẹgun rẹ. (Vs. 14), Ṣugbọn Ogbọdọ ṣetan lati fi ara rẹ fún igbẹ ayé ijiroro nínú ọrọ Ọlọrun, ìjọsìn, ádùrá, ati wíwá ni irẹpọ pẹlu Ẹmi Mimọ.

Ti a ba nsọ̀rọ nipa awọn ẹni nla nínú Bíbélì ohun kan lo so wọnpọ, wọn jẹ́ ọkùnrin àti obìnrin ifihàn pẹlú Ọlọrun.

Kika siwaju: Efesu 2:4-6, 2 Korinti 3:16-18, Isaiah 6:1-7, Romu 6:13, Exodus 34:29 -30

Adura: Óluwa mú mi wọ inú yàrá ifihàn Rẹ.

Ìwé mímọ́

Ọjọ́ 6

Nípa Ìpèsè yìí

Kristi, Ifihàn Ọlọrun Baba sí Wá

Bíbélì jẹ iwe èto itan bi Ọlọrun ṣe fi ara rẹ hàn fún ẹdá ènìyàn. Ojẹ àlàyé bi Ọlọrun to fẹran iṣẹda rẹ, pẹlú ipò ìṣubú wọn, síbẹ o nọwọ rẹ lati fi kanwo, lati gb'awọn lá, wo wọn sàn ati tuwọn ni ide Kúrò lọwọ ikú ati iparun ayérayé. Èrò idi fún ẹkọ yi ni lati ran wa lọwọ ki ale mọ̀ Ọlọrun baba lati inu Kristi Ọmọ.

More

A yoo fẹ lati dupẹ lọwọ Adeoye Gideon fun ipese eto yii. Fun alaye diẹ sii, jọwọ ṣabẹwo: https://www.facebook.com/gideon.adeoye?mibextid=ZbWKwL