Kristi, Ifihàn Ọlọrun Baba sí WáÀpẹrẹ
Pàtàkì Ìwà Mímọ
Ọlọrun amā farahàn lati ṣiṣẹ ni agbegbe òdodo. Ti Ọlọrun bá fi àrà Rẹ hàn ni agbegbe aisododo ãjẹ fún ìdájọ tabi iparun ni. Ìwà òdodo jẹ òkùnfà fún ifarahan Ọlọrun ninu ati ni àyíká wá.
Lati isihin ti obá fẹ ri ifihan Ọlọrun nínú ayé rẹ fún ojú rere, O gbọdọ ṣe tán láti pa ofin ìwà òdodo mọ. Ìwà òdodo pọn dandan fún ifarahan Ọlọrun, ẹṣẹ amáa di ìfihàn Ọlọrun láti di mímọ ní àrin wá. Õle máa gbáyùn nínúẹ̀ṣẹ ki omãa reti ki Ọlọrun ma pọsi fún ọ.
Kini Bibeli sọ nípa iwa ódodo ni ìbámu pẹlú ifihàn Ọlọrun?
awọn oninu-funfun nwọn ó ri Ọlọrun". awọn ẹniti ebi npa ati ti ongbẹ ngbẹ sipa ododo: nitori nwọn ó yó".
Ọlọrun dá Àyè atí Ọrun lori ipilẹṣẹ Òdodo. Pipa ofin yi mọ yíò pàwā ati agbègbè wa mọ, Nigba ti a ba sí kọ ofin òdodo yì silẹ ohun ti yíò yọrisi ni ikú ati iparun fún wa àti ayé tí a tèdó sí lori.
Kika siwaju: Matteu 5:6, Matteu 5:8
Adura: Oluwa rán mi lọwọ láti fẹràn ati máà gbé ìgbé ayé òdodo.
Ìwé mímọ́
Nípa Ìpèsè yìí
Bíbélì jẹ iwe èto itan bi Ọlọrun ṣe fi ara rẹ hàn fún ẹdá ènìyàn. Ojẹ àlàyé bi Ọlọrun to fẹran iṣẹda rẹ, pẹlú ipò ìṣubú wọn, síbẹ o nọwọ rẹ lati fi kanwo, lati gb'awọn lá, wo wọn sàn ati tuwọn ni ide Kúrò lọwọ ikú ati iparun ayérayé. Èrò idi fún ẹkọ yi ni lati ran wa lọwọ ki ale mọ̀ Ọlọrun baba lati inu Kristi Ọmọ.
More
A yoo fẹ lati dupẹ lọwọ Adeoye Gideon fun ipese eto yii. Fun alaye diẹ sii, jọwọ ṣabẹwo: https://www.facebook.com/gideon.adeoye?mibextid=ZbWKwL