Kristi, Ifihàn Ọlọrun Baba sí WáÀpẹrẹ

Kristi, Ifihàn Ọlọrun Baba sí Wá

Ọjọ́ 2 nínú 7

Ogo Tia Fihàn

Ọlọrun fi àrà Rẹ hàn tunmọ si wipé o fẹ ki ariòún, gbọọ, ki asi mọọ li ọna a ofi sunmọọ lati ri ifẹ Rẹ̀ latile fẹ ati awọn eniyan ti o yiwaka.

Ni pátápátá Ọlọrun ṣe imusẹ eleyii nipa ríran Ọmọbibi Rẹ̀ kàn ṣoṣo ni àwọ ẹdá ènìyàn. Bẹ, Kristi wà sí ayé láti mú Ọlọrun sún mọwa.

Níbẹ, rírí Kristi ni riri Ọlọrun Baba nínúẹkúnrẹrẹ́ Ogo Rẹ; kinidi? Òún ní itanṣan Ògo ati àwòrán baba.Vs. 3

Kristi funrararẹ tẹnumọọ pe;"Emi li ọ̀na, ati otitọ, ati iye: kò si ẹnikẹni ti o le wá sọdọ Baba, bikoṣe nipasẹ mi".

Kristi ni aṣoju ẹkunrẹrẹ igbimọ Ọ̀run. Oba ikú, iji omi, awọn ẹmikẹmi sọrọ. Gbogbo Àṣẹ igbimọ Ọ̀run li ati fi fún láti ṣe àkóso ẹda gbogbo.

Ninu Orúkọ Rẹ ni at'ile ri Idáriji ati imúkuró ẹṣẹ nitori orukọ Rẹ̀ ju gbogbo orúkọ lọ Vs. 4b.

Kristi Jesu ni Ògo Ọlọrun Bàbá ti afi hàn wá.

Kika siwaju: Matteu 22:37-39, Johannu 1:14, Johannu 14:6

Adura: Oluwa ṣi mi loju kín le ri ọ ninu ẹkunrẹrẹ Ogo Rẹ.

Ìwé mímọ́

Ọjọ́ 1Ọjọ́ 3

Nípa Ìpèsè yìí

Kristi, Ifihàn Ọlọrun Baba sí Wá

Bíbélì jẹ iwe èto itan bi Ọlọrun ṣe fi ara rẹ hàn fún ẹdá ènìyàn. Ojẹ àlàyé bi Ọlọrun to fẹran iṣẹda rẹ, pẹlú ipò ìṣubú wọn, síbẹ o nọwọ rẹ lati fi kanwo, lati gb'awọn lá, wo wọn sàn ati tuwọn ni ide Kúrò lọwọ ikú ati iparun ayérayé. Èrò idi fún ẹkọ yi ni lati ran wa lọwọ ki ale mọ̀ Ọlọrun baba lati inu Kristi Ọmọ.

More

A yoo fẹ lati dupẹ lọwọ Adeoye Gideon fun ipese eto yii. Fun alaye diẹ sii, jọwọ ṣabẹwo: https://www.facebook.com/gideon.adeoye?mibextid=ZbWKwL