Kristi, Ifihàn Ọlọrun Baba sí WáÀpẹrẹ
Isọdọmọ
Kosi bi aṣe lé fẹ ṣe afẹri awọn angẹli to lati fi wọn sí ipò tí wọn Oyẹ fún, Oṣe kókó kíá ni ìmọ nípa ohun tí Bíbélì sọ nípa wọn kíá ma ba ṣubu sinu ẹkọ òdì tíó muwa ma bọ awọn angẹli tabi sọ wọn di Ọlọrun.
Awọn angẹli òsì nínú ìgbìmò Ọrùn, ẹdá ti Ọlọrun dá níwòn (ati Luciferi tíó di satani) wọn òní amuye Ọlọrun, iranṣẹ ni wọn, ati ẹmi ti a olè kan fojú ri.
Olùjọsìn li wọn. Láì kò yẹ kí a bọ wọn.
Pẹlu pe wọn jẹ ẹmi wọn koni anfaani pé agba wọn bí Ọmọ Ọlọrun (Ẹsẹ. 5) Eleyii yíò ran wa lọwọ láti mọ pàtàkì pé Ọlọrun sọ wa di ọmọ nínú Kristi Jésù tó jẹ akọbi. Eleyi jẹ ìgbésẹ ìfẹ tí ọgá lat'ọdọ Ọlọrun.
Nitorina, ikan ninu àṣeyọrí Kristi to gajulọ nínú iṣẹ ìràpadà Rẹ n'ipe osọ wà di ọmọ Ọlọrun, òfún wa ni aanfani ti àwọn angẹli gbádùn. Oyẹki ama dupẹ fún ẹbùn isọdọmọ yìí.
Kika siwaju: Eksodu 23:20-23, Orin Dafidi 91:11-13
Adura: Jesu Oluwa rán mi lọwọ láti lè má gbé nínú ògún isọdọmọ yìí tí ofi fún mí.
Ìwé mímọ́
Nípa Ìpèsè yìí
Bíbélì jẹ iwe èto itan bi Ọlọrun ṣe fi ara rẹ hàn fún ẹdá ènìyàn. Ojẹ àlàyé bi Ọlọrun to fẹran iṣẹda rẹ, pẹlú ipò ìṣubú wọn, síbẹ o nọwọ rẹ lati fi kanwo, lati gb'awọn lá, wo wọn sàn ati tuwọn ni ide Kúrò lọwọ ikú ati iparun ayérayé. Èrò idi fún ẹkọ yi ni lati ran wa lọwọ ki ale mọ̀ Ọlọrun baba lati inu Kristi Ọmọ.
More
A yoo fẹ lati dupẹ lọwọ Adeoye Gideon fun ipese eto yii. Fun alaye diẹ sii, jọwọ ṣabẹwo: https://www.facebook.com/gideon.adeoye?mibextid=ZbWKwL