Kristi, Ifihàn Ọlọrun Baba sí WáÀpẹrẹ

Kristi, Ifihàn Ọlọrun Baba sí Wá

Ọjọ́ 4 nínú 7

Angẹli

Awọn angẹli jẹ iranṣẹ ẹmi tí Ọlọrun ran niiṣe pàtó. Awọn iṣẹ ti wọn ṣe jẹ iṣẹ tó pamọ sí Ojú ati eti ti ará. Ẹni tó dá àwọn angẹli Rẹ ni ẹmi. Vs.7

Njẹ oti kiyesi, idi ti Ọlọrun oṣe fi ìṣàkóso ìhìnrere sí ọwọ àwọn angẹli (eleyii oni won o ni ipa nínú ihinrere). Iṣẹ́ Ìhìnrere jẹ iṣẹ awọn ọmọ Ọlọrun gẹgẹbi bi àti ríi nínú ìgbé ayé Kristi Jésù nínú àwọn àkọsílẹ̀ awọn ìwé ìhìnrere; Matiu, Maku, Luku ati Jòhánù, lati gbè ìjọba Ọlọrun kalẹ nínú òdodo.

Ìwàásù ìhìnrere jẹ iṣẹ iwalaye Kristi ati Ẹmi mimọ nínú ayé Onigbagbo (kiyesii; awọn ti o gbagbọ tori olè wàásù oun ti õ gbagbọ. Jòhánù 7:38).

Ni akotan, máṣe sọ awọn angẹli di òrìṣà tàbí ọlọrun láti máa bọ wọn.

Kika siwaju: Iṣe 10:1-7, Johannu 7:38

Adura: Óluwa ràn mí lọwọ láti má ṣubu sinu aṣiṣe bibọ angẹli.

Ìwé mímọ́

Ọjọ́ 3Ọjọ́ 5

Nípa Ìpèsè yìí

Kristi, Ifihàn Ọlọrun Baba sí Wá

Bíbélì jẹ iwe èto itan bi Ọlọrun ṣe fi ara rẹ hàn fún ẹdá ènìyàn. Ojẹ àlàyé bi Ọlọrun to fẹran iṣẹda rẹ, pẹlú ipò ìṣubú wọn, síbẹ o nọwọ rẹ lati fi kanwo, lati gb'awọn lá, wo wọn sàn ati tuwọn ni ide Kúrò lọwọ ikú ati iparun ayérayé. Èrò idi fún ẹkọ yi ni lati ran wa lọwọ ki ale mọ̀ Ọlọrun baba lati inu Kristi Ọmọ.

More

A yoo fẹ lati dupẹ lọwọ Adeoye Gideon fun ipese eto yii. Fun alaye diẹ sii, jọwọ ṣabẹwo: https://www.facebook.com/gideon.adeoye?mibextid=ZbWKwL