Jíjẹ Olubori Lori Ògùn Ẹ́ran ÀràÀpẹrẹ

Jíjẹ Olubori Lori Ògùn Ẹ́ran Àrà

Ọjọ́ 1 nínú 7

Bibori Ẹran Àrà

Ọrọ na, "ìṣẹ̀dá to kún fún ẹṣẹ" tọka sí ìṣẹ̀dá àìlera ati idibajẹ ti a jogún nipa ìbí. Gbogbo wa la bi sínú ìṣẹdá to kún fún ẹṣẹ yii. Nipa bẹ Bibeli wípé; "Gbogbo wá ti ṣẹ asi ti kùnà Ògo Ọlọrun.

Eleyii pọn dandan pé agbọdọ di atunbi, sugbon lẹyin iriri pé àdí atunbi, ìgbésẹ itẹsiwaju kan ṣi wa,èyíi to jẹ "Rìnrìn nínú Ẹmi" , eleyii to jẹ wíwá nínú irẹpọ, idapọ pẹlu Ẹmi Mimọ ati titẹle ìdarí Rẹ. Ni kukuru "Biba Ọlọrun Rìn". Kiyesii pe Ẹmi Mimọ jẹ ọkan nínú igbimọ Ọ̀run to sunmọ ọ jù, ti a fi ṣe ileri fún gbogbo onigbagbọ nínú Kristi Jésù.

Imudagba rẹ niyii; óò wá ni àìní irẹpọ pẹlu ẹran àrà ti o bá ni irẹpọ pẹlu Ẹmi Mimọ ati ni idakeji,(Ogbọdọ ni ìpinu lórí èyí) òní láti bóri ẹran àrà, kí òsì ni iṣẹgun bóri ipá rẹ láti dárí rẹ sínú ẹṣẹ.

Àwọn ohun yii ni ai gbọdọ máṣe; níní ìtara lati sunmọ, imọ lára ati titẹle ìdarí Ẹmi Mimọ. Awọn eleyii oṣe ṣe pẹlú ọgbọn ti àrà, nibiyii, o gbọdọ di atunbi. O gbọdọ fi òkun fún ifọkansi nínú kíkà ati ṣiṣe àṣàrò nínú Bíbélì ati Gbigba adura ati ìgbé ayé ìjọsìn.

Siwaju kika: John 3:5-7, Acts 2:38-39, Joel 2:28-30, Romans 3:23, 8:13-14.

Adura: OLÙWÀ, fún mí ni ọkan to'n ṣe afẹri lati sunmọ Ọ nígbà gbogbo.

Ìwé mímọ́

Ọjọ́ 2

Nípa Ìpèsè yìí

Jíjẹ Olubori Lori Ògùn Ẹ́ran Àrà

Dídì Atunbi túnmọ̀ sí wiwà sínú ìwà ẹdá títún, eleyii tí a nilo lati mọ ati lati ni òye rẹ. Igbe ayé otun to ni àgbàrá pẹlu idayatọ imudagba lati mọ dènú. Yíó jẹ yiyọ ayọ ìṣẹgun aitọ jọ lori ẹṣẹ nigba tí a di atunbi laiti ni ijinlẹ oyè nínú "rìnrìn pẹlú Ọlọrun" èyí ni yíò jẹ irin àjò wá fún ọjọ́ méje yi, dé amure ijókó rẹ dáadáa.

More

A yoo fẹ lati dupẹ lọwọ Adeoye Gideon fun ipese eto yii. Fun alaye diẹ sii, jọwọ ṣabẹwo: https://www.facebook.com/gideon.adeoye?mibextid=ZbWKwL