Jíjẹ Olubori Lori Ògùn Ẹ́ran ÀràÀpẹrẹ

Jíjẹ Olubori Lori Ògùn Ẹ́ran Àrà

Ọjọ́ 5 nínú 7

KIYESARA!!!

Ọnà kan lati di ẹni tí o bikita nipa ti ẹmi ni lati jẹki ìgbéraga fọ ni lójú. Ákilọ̀ èyí fún wa ni Vs.26,

àṣẹ Kristi to ṣe pàtàkì fún wá ni lati fẹràn àrà wà.

O ko gbọdọ̀ De íkoritá bi onigbagbọ ti yóò ni ero pe "mọ tito fún àrà mi" àti fún elòmíràn lati tò fún àrà wọn nã, eleyii yíò bi ìdíje ti ko lérè, idanilẹbí àti òwú jíjẹ. Rárá, eleyi o dà fún àrà Kristi.

Yálà, oyẹ kí ámā ṣe alōre fún àrà wà. Ti ẹnikẹni bá ṣubú sínú ẹṣẹ, gbígbé ìrù ẹni bẹ dide yẹ ko jẹ ajumọṣe nínú iwa ípẹ̀lẹ̀ Laisi ìgbéraga tàbí íjọraẹniloju, eleyii yíò fi hàn bóyá ajẹ ẹni ẹmi. (To'n rin ninú Ẹmí)

Àrà ìdí tí a fi ni awọn àpẹrẹ eniyan nínú Bíbélì ni lati kọ ẹkọ nínú iṣẹgun wọn nikan kọ ṣugbọn nínú ìṣubú wọn pẹlu. Máṣe ri àrà rẹ bi eni ti o lè ṣubu.

Siwaju kika: John 15: 12, 2 Corinthian 3:1-6.

Adura: Ẹmi Mimọ ran mi lọwọ láti máà ri ọ bi orisun tito mí.

Ìwé mímọ́

Ọjọ́ 4Ọjọ́ 6

Nípa Ìpèsè yìí

Jíjẹ Olubori Lori Ògùn Ẹ́ran Àrà

Dídì Atunbi túnmọ̀ sí wiwà sínú ìwà ẹdá títún, eleyii tí a nilo lati mọ ati lati ni òye rẹ. Igbe ayé otun to ni àgbàrá pẹlu idayatọ imudagba lati mọ dènú. Yíó jẹ yiyọ ayọ ìṣẹgun aitọ jọ lori ẹṣẹ nigba tí a di atunbi laiti ni ijinlẹ oyè nínú "rìnrìn pẹlú Ọlọrun" èyí ni yíò jẹ irin àjò wá fún ọjọ́ méje yi, dé amure ijókó rẹ dáadáa.

More

A yoo fẹ lati dupẹ lọwọ Adeoye Gideon fun ipese eto yii. Fun alaye diẹ sii, jọwọ ṣabẹwo: https://www.facebook.com/gideon.adeoye?mibextid=ZbWKwL