Jíjẹ Olubori Lori Ògùn Ẹ́ran ÀràÀpẹrẹ

Jíjẹ Olubori Lori Ògùn Ẹ́ran Àrà

Ọjọ́ 4 nínú 7

Awọn Òun To Nilo Lati Doku Sí Ẹran Àrà

Ọkàn nínú awọn ohun tí a béèrè fún lati fi èsó Ẹmí hàn ni iyanda àrà ẹni pátápátá sí ìdarí Ẹmi Mimọ láì fá òhún kóhun sẹyin.

Bi à ṣé tọka ni ẹsẹ 24, ni iyi ta sọ ṣaaju. O gbọdọ tẹle iṣisẹ Ẹmi Mimọ Títí to fí doku sí ẹṣẹ nipa kikan ẹran àrà mọ agbelebu ni igbadegba. Ni ọrọ míràn, oko gbọdọ fi yàrá tabi ànfàní sílẹ fún ẹran àrà lati ni gbòngbò tabi dagbasoke nínú rẹ.

Wa ni kiye sara fún ifẹkufẹ ẹran àrà nínú ayé rẹ, tẹri wọn bá, máṣe fún wọn ni yàrá tàbí ayé láti bisii, ìgbésẹ ti agbọdọ ni ìpinu lórí ni.

Ohun tí Kristi Jésù gbà wa níyànjú lati ṣe niyi; "Ema ṣọra ki ẹsi ma gbàdúrà kí ẹma ṣe ṣubu sinu idanwo.

Siwaju kika: Galatians 2:20, 1 Corinthians 9:27, Galatians 5:24, Mark 14:38.

Adura: OLUWA, mo gba ọrẹ ọfẹ lati lè tẹri ẹran àrà bá ni gbogbo ìgbà Títí ti maafi doku sí ẹṣẹ.

Ìwé mímọ́

Ọjọ́ 3Ọjọ́ 5

Nípa Ìpèsè yìí

Jíjẹ Olubori Lori Ògùn Ẹ́ran Àrà

Dídì Atunbi túnmọ̀ sí wiwà sínú ìwà ẹdá títún, eleyii tí a nilo lati mọ ati lati ni òye rẹ. Igbe ayé otun to ni àgbàrá pẹlu idayatọ imudagba lati mọ dènú. Yíó jẹ yiyọ ayọ ìṣẹgun aitọ jọ lori ẹṣẹ nigba tí a di atunbi laiti ni ijinlẹ oyè nínú "rìnrìn pẹlú Ọlọrun" èyí ni yíò jẹ irin àjò wá fún ọjọ́ méje yi, dé amure ijókó rẹ dáadáa.

More

A yoo fẹ lati dupẹ lọwọ Adeoye Gideon fun ipese eto yii. Fun alaye diẹ sii, jọwọ ṣabẹwo: https://www.facebook.com/gideon.adeoye?mibextid=ZbWKwL