Jíjẹ Olubori Lori Ògùn Ẹ́ran ÀràÀpẹrẹ

Jíjẹ Olubori Lori Ògùn Ẹ́ran Àrà

Ọjọ́ 6 nínú 7

Ẹ Máa Rú Ẹrù Ará Yin

Kristi Jésù wípé, émi ko wá láti gbá olododo là ṣugbọn mọ wá fún ẹlẹṣẹ (lati sọ wọn di olódodo), báwò ni àwa ṣe n'reti kí awọn èèyàn ti mọ nínú ìdúróṣinṣin kí wọ́n tó wọnú ipejọpọ tabi ile ìjọsìn wa?

Gbogbo wa ni Ọlọrun fún ni ẹbun òdodo nínú Kristi, sibẹ, a jẹ iṣẹ tóntẹsiwaju kòsí gbọdọ yá wá lẹnu ti ìṣubú ba ṣẹlẹ. Nigbà mi, kíákíá lamā kọ àwọn tó ṣubú sínu ẹṣẹ silẹ láì rò bóyá wọn tiraka là ti dàgbà.

Àrà ìdí lati kiyesi ìkìlọ na; "Máṣe ri àrà rẹ sí ẹnikan tọju nínú ododo, ajulọ rẹ o kọja iṣirò àrà rẹ (6:3)

Ó ni ipá láti ko nínú ìlànà Ìgbàlà ayé ẹlomi ati nínú ìrìn wọn pẹlu Ọlọrun, bẹ na ni elomiran ni ipá láti kó nínú tirẹ nà, máṣe Yan àrà rẹ jẹ nínú anfaani yii, fi ìrẹlẹ ọkan ni ipá nínú ayé ẹlomi, sì jẹki ẹlòmíràn ni ipá nínú tirẹ̀ na.

Siwaju kika: Mark 2:15-17, Matthew 9:10-13, Luke 18:9-14.

Adura: Ran mi lọwọ kín lè jẹ ẹnìkejì tòótọ́ fún àwọn ẹlomi ni ipò àìní wọn nípa ẹ̀mí.

Ìwé mímọ́

Ọjọ́ 5Ọjọ́ 7

Nípa Ìpèsè yìí

Jíjẹ Olubori Lori Ògùn Ẹ́ran Àrà

Dídì Atunbi túnmọ̀ sí wiwà sínú ìwà ẹdá títún, eleyii tí a nilo lati mọ ati lati ni òye rẹ. Igbe ayé otun to ni àgbàrá pẹlu idayatọ imudagba lati mọ dènú. Yíó jẹ yiyọ ayọ ìṣẹgun aitọ jọ lori ẹṣẹ nigba tí a di atunbi laiti ni ijinlẹ oyè nínú "rìnrìn pẹlú Ọlọrun" èyí ni yíò jẹ irin àjò wá fún ọjọ́ méje yi, dé amure ijókó rẹ dáadáa.

More

A yoo fẹ lati dupẹ lọwọ Adeoye Gideon fun ipese eto yii. Fun alaye diẹ sii, jọwọ ṣabẹwo: https://www.facebook.com/gideon.adeoye?mibextid=ZbWKwL