Jíjẹ Olubori Lori Ògùn Ẹ́ran ÀràÀpẹrẹ

Jíjẹ Olubori Lori Ògùn Ẹ́ran Àrà

Ọjọ́ 3 nínú 7

Awọn Eso Ìwà Ẹmí Mímọ

Bíbélì tọka sí wọn bí awọn "Eso Ẹmi", Ẹmi tí an sọ ni Ẹmi Mímọ, awọn "Eso Ẹmi" yii ni awọn ìwà Ọlọrun ti a nilo ìgbà lati mọ ati lati dàgbà nínú wọn bí o bá ṣe ngbé iṣisẹ nínú irẹpọ pẹlu ìwà láàyè Ẹmi Mimọ nínú rẹ.

Nigbeyin, ìlànà yi yíò ran Ọ lọwọ láti leṣe òdodo pẹlú gbogbo àmúyẹ ìwà bi Ọlọrun ni ifarahan nínú ayé rẹ to bẹẹ ti orúkọ Jésù yíò gbà Ògo nínu ayé rẹ gẹgẹbi onigbagbọ tòótọ́ nínú Rẹ.

Awọn ìwà Ẹmi Mimọ ti àkójọ ni Vs. 20-21. O kolè fi àgabagebe ni tabi ṣe wọn. Ape wọn ni "Èsó" torí wọn ti inú iwalaye àti iṣẹ Ẹmi Mimọ jáde wá.

Afi Ẹmi Mimọ fún ọ kín ṣe lati fún ọ ni ẹbun nikan ṣugbọn lati ran ọ lọwọ láti dàgbà nínú ìwà òdodo sínú ìṣẹ̀dá gangan ti Ọlọrun. Iwọntunwọnsi yii gbọdọ pé sínú ayé rẹ gẹgẹbi onigbagbọ nínú Kristi lati ni ẹrí idagbasokenipa ti ẹmi.

Siwaju kika: 1 Corinthians 12:3,6,

Adura: OLÙWÀ Rán mi lọwọ kín lè kẹkọọ ati faradà ohun to gbà latí dàgbà nínú èsó.

Ìwé mímọ́

Ọjọ́ 2Ọjọ́ 4

Nípa Ìpèsè yìí

Jíjẹ Olubori Lori Ògùn Ẹ́ran Àrà

Dídì Atunbi túnmọ̀ sí wiwà sínú ìwà ẹdá títún, eleyii tí a nilo lati mọ ati lati ni òye rẹ. Igbe ayé otun to ni àgbàrá pẹlu idayatọ imudagba lati mọ dènú. Yíó jẹ yiyọ ayọ ìṣẹgun aitọ jọ lori ẹṣẹ nigba tí a di atunbi laiti ni ijinlẹ oyè nínú "rìnrìn pẹlú Ọlọrun" èyí ni yíò jẹ irin àjò wá fún ọjọ́ méje yi, dé amure ijókó rẹ dáadáa.

More

A yoo fẹ lati dupẹ lọwọ Adeoye Gideon fun ipese eto yii. Fun alaye diẹ sii, jọwọ ṣabẹwo: https://www.facebook.com/gideon.adeoye?mibextid=ZbWKwL