Jíjẹ Olubori Lori Ògùn Ẹ́ran ÀràÀpẹrẹ

Jíjẹ Olubori Lori Ògùn Ẹ́ran Àrà

Ọjọ́ 2 nínú 7

Ifarahan Ti Ẹran Àrà

Ìṣẹ̀dá to kún fún ẹṣẹ ni awọn ìwà rẹ ti nṣe lati màà ṣe iṣẹ ibi, gbogbo ifarahan rẹ kó fará jo awọn ìwà tí Ẹmi ati ihuwasi ti Ọlọrun.

Gbogbo ifarahan ti ẹran àrà ni aṣẹ àkójọ ni ẹsẹ 19 ati 20 sùgbọ́n kókó ọrọ yii ni pé; tóò bá bikita lati ka ìrìn rẹ pẹlú Ọlọrun si, ẹran àrà yíò bóri láti mú ọ lẹru sabẹ ìṣàkóso rẹ.

Ẹran àrà yíì lè gbilẹ ti onigbagbọ bá kùnà lati mú ojúṣe rẹ nínú ṣíṣe eto ibasepọ rẹ pẹlú Ọlọrun ni ibì ikiyesi árà ati ádùrá. Onigbagbọ míràn ti rẹwẹsi sínú ẹṣẹ to bẹẹ, eleyii jẹ àmi jijọwọ àrà ẹni fún ẹṣẹ lati bóri.

Iṣẹgun lori ẹran àrà jẹ iṣẹgun tó ṣe pàtàkì ti a gbódò ni bi onigbagbọ láti lè ṣójú Kristi lẹkun rẹrẹ ni ayé àti ayé àìnípẹkun.

Siwaju kika: Mark 14:38, Revelation 3:5.

Adura: OLÙWÀ, somiji kí òsì fún mí ni àgbàrá lori ẹṣẹ ati ẹran àrà.

Ìwé mímọ́

Ọjọ́ 1Ọjọ́ 3

Nípa Ìpèsè yìí

Jíjẹ Olubori Lori Ògùn Ẹ́ran Àrà

Dídì Atunbi túnmọ̀ sí wiwà sínú ìwà ẹdá títún, eleyii tí a nilo lati mọ ati lati ni òye rẹ. Igbe ayé otun to ni àgbàrá pẹlu idayatọ imudagba lati mọ dènú. Yíó jẹ yiyọ ayọ ìṣẹgun aitọ jọ lori ẹṣẹ nigba tí a di atunbi laiti ni ijinlẹ oyè nínú "rìnrìn pẹlú Ọlọrun" èyí ni yíò jẹ irin àjò wá fún ọjọ́ méje yi, dé amure ijókó rẹ dáadáa.

More

A yoo fẹ lati dupẹ lọwọ Adeoye Gideon fun ipese eto yii. Fun alaye diẹ sii, jọwọ ṣabẹwo: https://www.facebook.com/gideon.adeoye?mibextid=ZbWKwL