Jíjẹ Olubori Lori Ògùn Ẹ́ran ÀràÀpẹrẹ

Jíjẹ Olubori Lori Ògùn Ẹ́ran Àrà

Ọjọ́ 7 nínú 7

Gbá Ojúṣe Rẹ Ṣe

Bi a ṣe nṣẹ alōre fún ará wà ti a sí nrú ẹrù ará wa, èyíi o yọ ayé kí olukulùku gbà ojúṣe ṣe, ṣe ìṣirò ati ìgbàpadà fún gbogbo ìgbésẹ.

Agbọdọ nígbà gbogbo máa ṣe agbeyewo ati iṣiro ará wa nínú imọlẹ òdodo Ọlọrun, lati mọ bí Ọlọrun lè lọwọ sí awọn ìgbésẹ wà. Ẹni to mbá Ọlọrun rìn a máà ṣe eléyìí déédé. Vs. 4.

Ẹmi Mimọ ati Ọrọ Ọlọrun a máa fi ọ hàn àrà rẹ bi o to jẹ gángan láì fàsẹhin ní itọka sí ibi tí o ni lò àtúnṣe ati ironupiwada nínú ìgbésẹ rẹ.

Ọkàn nínú èto to ṣe pàtàkì nínú rìnrìn nínú Ẹmí ní;mímọ aṣiṣe rẹ, ṣiṣe ironupiwada ati gbígbe ìgbésẹ atunṣe, ojúṣe yì wa ni ọwọ rẹ, o lè ré ètò yi kọja kí òsì wá ni irẹpọ̀ pẹlu Ẹmi Mimọ.

Siwaju kika: James 1:22-25, 2 Corinthian 13:5-8,

Adura: OLÙWÀ, sí mí ni Ojú lati ri ìbí tó yẹ kín dìde, ṣe ironupiwada ati lati tún ọnà mí ṣe.

Ìwé mímọ́

Ọjọ́ 6

Nípa Ìpèsè yìí

Jíjẹ Olubori Lori Ògùn Ẹ́ran Àrà

Dídì Atunbi túnmọ̀ sí wiwà sínú ìwà ẹdá títún, eleyii tí a nilo lati mọ ati lati ni òye rẹ. Igbe ayé otun to ni àgbàrá pẹlu idayatọ imudagba lati mọ dènú. Yíó jẹ yiyọ ayọ ìṣẹgun aitọ jọ lori ẹṣẹ nigba tí a di atunbi laiti ni ijinlẹ oyè nínú "rìnrìn pẹlú Ọlọrun" èyí ni yíò jẹ irin àjò wá fún ọjọ́ méje yi, dé amure ijókó rẹ dáadáa.

More

A yoo fẹ lati dupẹ lọwọ Adeoye Gideon fun ipese eto yii. Fun alaye diẹ sii, jọwọ ṣabẹwo: https://www.facebook.com/gideon.adeoye?mibextid=ZbWKwL