Ìtọ́sọ́nà Àtọ̀runwáÀpẹrẹ

Divine Direction

Ọjọ́ 6 nínú 7

Ìsopò

Nígbà tí mo rí i pé kì i se pé a dá mi láti sin nínú ṣọ́ọ̀ṣì nìkan, àmó láti sin àwon ẹlòmíràn gégé bí ìjo, ìsopò pèlú àwon ènìyàn dí ohun pàtàkì. O kò lè sin láìsi ìsopò. Àti ènì tí o bá sopò pèlú máa ṣàyípadà àwon ìtàn tó má so lóla. Èyí tí jé òtító jálè ìtàn. Sàgbéyèwò okùnrin tó kò jù ìdámẹ́ta lára májẹ̀mú titun lo, àpọ́sítélì Pọ́ọ̀lù.

Pọ́ọ̀lù, kì i sábà máa n jé Kristeni. Kí ó tó dí omoléyìn Kristi,o jé Sọ́ọ̀lù láti ìlú tí a pé ní Tásù , okùnrin tó n bínú tó n senúbíni sí àti pa àwon Kristeni, tí o kò bá féràn àwùjo Jésù, wa tí féràn tí Sóòlù . Àmó léyìn ìgbà tó gbèmí àwon tó gbàgbó pé jí Jésù dìde kúrò nínú òkú, Pọ́ọ̀lù, dí òkan lára wón fúnra rè.

Àyípadà rè tóbi, jé gbòygbò, ohun tó yí ayé ènì padà tójé pé Sòlù (ènì tí a yí orúko rè padà sí Póòlù) lésèkesè fé so nípa Jésù fún àwon ẹlòmìíràn. Ìsòro náà ní pé kò sí Kristeni tó fokàn tán an àti fún àwon ìdí tó hàn kedere.

Ìwé Ìṣe àwọn àpóstélì so ó ní sókí: Nígbà tí [Sóòlú] wá sí Jerúsálẹ́mù, o gbìyànjú láti dara pò mó àwon omoléyìn, àmó ẹ̀rù e ń bà gbogbo won, wón kò gbàgbó pé o jé omolèyín lótító. Acts 9:26 NIV. O kò lè débi fún àwon omoléyìn náà fún iyé méjì won. Mi kò ní fé kí okùnrin tó pa àwon Kristeni lósù tó kojá láti darí ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì mi! Ǹjẹ́ wàá fẹ́?

Póòlù nísòro kan. O ṣaláìní ìṣeégbáralé pèlú àwon Kristeni mìíràn. Nígbà náà Póòlù sapá láti so fún ẹnikẹ́ni tó máa fún un láǹfààní láti sàjopín ìfé rè tó sèsè rí.Ìpinnu Póòlù láti sopò kò kan sàyípadà ìtàn rè; o sàyípadà ìtàn akosílè. O rí, Póòlù ní láti ní òré kan láti yí ònà ìgbésí kádàrá rè padà. Àtipe òré náà ní okùnrin tí a pé ní Bánábà.

O lè ní láti ní ipò ìbániṣọ̀rẹ́ kan láti sàyípadà ìtàn rè.

Lónìí yóò ká nípa ìgbà tí Bánábà ewu ní mimú Póòlù lo sódó àwon àpóstélì yókù, àwon tó jé olórí àwon ènì tí Póòlù tí gbìyànjú láti pa ní ayé rè télè. Kí ló selè? Òré Póòlù tuntun Bánábà fi orúko rere rè séwu lórí Póòlù. Àtipe nítórí Bánábà, àwon omoléyìn yókù fún Póòlù láyè. Ìyókù jé ìtàn. O lè ní ipò ìbániṣọ̀rẹ́ kan láti sàyípadà ìtàn rè.

Òrẹ́ kan lo nílo láti sàyípaà ìgbéyàwó rè. Ìjéwó kan lo nílo láti borí g bárakú. Ìjíròrò kn lo nílò láti ní ìrísí tó tún dára. Agbaninímọ̀ràn kan lo ní láti lóye àwon èbùn rè àti dí olórí tó tún dára.

Bí ara rẹ léèrè: Kí ni mo ní láti sé láti sopò pèlú àwon ènìyàn tó dára? Sé enkéni wà tí no ní láti ṣèpínyà pèlú?

Ọjọ́ 5Ọjọ́ 7

Nípa Ìpèsè yìí

Divine Direction

Lójojúmọ́, a ma ńṣe àwọn àṣàyàn tó ń tọ́ ipa nínú ìtàn ìgbésí ayé wa. Báwo ni ìtàn ìgbésí ayé rẹ yóò ti rí tí o bá ṣe àwọn àṣàyàn tó dára? Nínú Ètò Bíbélì Ìtọ́sọ́nà Àtọ̀runwá, gbajú-gbajà ònkọ̀wé New York Times àti Olùṣọ́àgùntàn àgbà ní ìjọ Life.Church, Craig Groeschel, máa gbà ọ́ níyànjú pẹ̀lú àwọn ìlànà méje tí a fà jáde látinú ìwé Ìtọ́sọ́nà Àtọ̀runwá fún ìrànlọ́wọ́ láti ṣe àwárí ọgbọ́n Ọlọ́run fún àwọn ìpinnu tí à ńṣe lójojúmọ́. Ṣe àwárí àwọn ìtọ́ni ti ẹ̀mí tí o nílò láti gbé ìgbésí ayé tó bọ̀wọ̀ fún Ọlọ́run.

More

A fé láti dúpé lówó Àlùfáà Craig Groeschel àti Life Church fún ìpèsè ètò yìí. Fun àlàyé síwájú sí, jọ̀wọ́ lọ sí: http://craiggroeschel.com/