Ìtọ́sọ́nà Àtọ̀runwáÀpẹrẹ

Divine Direction

Ọjọ́ 1 nínú 7

Bèrè

Ní ojoojúmó la ñ se ìpinnu tó má se ìrísí ìtàn ayé wa. Kí ni ayé wa yóò dà bí tí o bá jé kí ìlànà Olórun samònà àwon ìpinnu náà? Fún òsè kan, a máa bèrè síṣàyẹ̀wò àwon ìlànà méje láti ìwéÌtọ́sọ́nà Àtọ̀runwá láti ràn e lówó láti wá ogbón Olórun lórí àwon ìpinnu ojoojúmó rè.

Tí enìkan bá béèrè lówó è láti so ìtán ayé rè, kì ni ó má so?

Ó lè béèrè pèlú ibi tá tí bí è àti bá se tó è. Ó lè dárúko ifé àkókó è. Bóyá wa soro nípa ìgbése ñlá tí ebí rè gbé tàbí nígbà tí o lo kọ́lẹ́ẹ̀jì.Tó bá ti se ìgbéyàwó, o lè sàpèjúwe bí o se padè oko tàbí aya rè. Ti o kò bá i ti ṣègbéyàwó, ó lè sàpèjúwe ìdí. Tí ó bá jé òbí, wo àwon àwòrán lórí fóònù àtipe fi ebí rè yagàn. Tàbí bóyá ó lè sàpèjúwe ònà isé rè. Kílo wa nínú ìtàn rè?

Òpò lara wa ní àkòrí tí a kàkà béè kò ni fé láti sàjopín wón pèlú enikéni. Bóyá o ti parí si ibi kan tó fé de láé. Ó kò fé to bà jẹ́, sùgbón o se. Ó se àwon ìpinnu kan tó mú o jìnnà jù bí o se ní lọ́kàn láti lo. O se àwon ohun kan to na e lowó jù bí o se ro pé wa san lo. Ó pa àwon ènìyàn lára. Ó tí fí àwon ìlànà rè bánidọ́rẹ̀ẹ́. Ó kò mú ìlérí rè sẹ. Ó se àwon ohun kan tó nímọ̀lára pé ó kò lè padàsẹ́yìn lórí wón.

Ìtàn rè kò i ti parí. Kò i ti pé jù láti sáyipadà ìtàn tóá so lójó kan.

Rere mbe: ìtàn rè kò tíì parí. Kò tíì pẹ́ jù láti ṣàyípadà ìtàn rè tó má so lójó kan. Ohun yòówù tó tí se (tàbí kò ì tì se), a kò i tí ko ojó òla rè sílè. Ó ní ìségun sí láti borí, òré sí láti pade, ìyátó sí láti se, ohun rere Olórun sí láti nírírí. Bóya tàbí ó kò féran ìwéwèé bayìí, pèlú ìrànlówó Olórun, o lè se ìyípadà ìtàn rè sí èyí tó má yagàn láti sàjopín rè.

Ònà kan re láti se ìyípadà ìtàn rè: bèrè ohun tuntun.

ohun yòówù ohun àìdánilójú, ìfòyà, tàbí hihá tó lè máa ń rí lára báyìí, ìtàn rè tè síwájú lónìí. Kí lo fé bèrè lónìí? Gbigbàdúrà lójoojúmọ́ pèlú oko tàbí aya rè? Kíkà ètò Bíbélì YouVersion lójoojúmọ́? Lilo fún ìmòràn láti yanjù òràn àríyànjiyàn? Gbigbé pèlú ìwà-ọ̀làwọ́ ñlá? Sínsìn ní ṣọ́ọ̀ṣì rè tàbí ládùúgbò? Nísinsìnyí ni àkókò tí ó dára jù láti ko sílè.Sí àwon ìwé rè àtipe se àkosílè àwon èrò rè. Má se ronú ju lórí èyí. Àmó lo àkòkó díè láti ko sórí ìwé. Ní gbólóhùn kan tàbí méji pere.

Béèrè lówó ara rè: Kí ni mo nílò láti bèrè síni se láti gbé ìgbésẹ̀ síhá irú ìtàn ayé tí mo fé so?

Ko sí nípa ìwé mi, Ìtọ́sọ́nà Àtọ̀runwá.

A mú ètò Bíbélì yìí láti inú ìwé,Ìtọ́sọ́nà Àtọ̀runwá, pèlú gbigba àṣẹ lọ́dọ̀ Zondervan. A yí Àkóónú padà fún kíkúrú.

Ọjọ́ 2

Nípa Ìpèsè yìí

Divine Direction

Lójojúmọ́, a ma ńṣe àwọn àṣàyàn tó ń tọ́ ipa nínú ìtàn ìgbésí ayé wa. Báwo ni ìtàn ìgbésí ayé rẹ yóò ti rí tí o bá ṣe àwọn àṣàyàn tó dára? Nínú Ètò Bíbélì Ìtọ́sọ́nà Àtọ̀runwá, gbajú-gbajà ònkọ̀wé New York Times àti Olùṣọ́àgùntàn àgbà ní ìjọ Life.Church, Craig Groeschel, máa gbà ọ́ níyànjú pẹ̀lú àwọn ìlànà méje tí a fà jáde látinú ìwé Ìtọ́sọ́nà Àtọ̀runwá fún ìrànlọ́wọ́ láti ṣe àwárí ọgbọ́n Ọlọ́run fún àwọn ìpinnu tí à ńṣe lójojúmọ́. Ṣe àwárí àwọn ìtọ́ni ti ẹ̀mí tí o nílò láti gbé ìgbésí ayé tó bọ̀wọ̀ fún Ọlọ́run.

More

A fé láti dúpé lówó Àlùfáà Craig Groeschel àti Life Church fún ìpèsè ètò yìí. Fun àlàyé síwájú sí, jọ̀wọ́ lọ sí: http://craiggroeschel.com/