Ohun Méje Ti Bíbélì So Nípa Àníyàn
![Ohun Méje Ti Bíbélì So Nípa Àníyàn](/_next/image?url=https%3A%2F%2Fimageproxy.youversionapi.com%2Fhttps%3A%2F%2Fs3.amazonaws.com%2Fyvplans%2F4538%2F1280x720.jpg&w=3840&q=75)
Ọjọ́ 7
Gbogbo ojó lo ṣeé ṣe fún láti gbé oríṣiríṣi ìpèníjà titun sínú ayé wá. Àmó o dọ́gba pẹ̀lú bí pé ojó titun kòòkan màa bùn wá pèlú àwon àǹfààní to yá gágá. Ní ojó-méje onífọkànsìn èyí, ọmọ-ẹgbẹ́ agbo òṣìṣẹ́ ni YouVersion ràn è lówó láti sílò òtítọ́ láti ínú òrò Olórun si ohun yòó wù ti ọ́ ń dojúko lòní. ífọkànsìn ojó kòòkan kún un ni Esẹ Bíbélì alàwòrán láti ràn è lówó láti ba o pín ohun ti Olórun n sọ̀rọ̀ sí o.
A se kikò àti ipèsè ètò yìí láti ọwọ àjọṣepọ̀ ní YouVersion. Sabẹ̀wò youversion.com fun àlàyé síwájú sí.
Nípa Akéde