Ohun Méje Ti Bíbélì So Nípa ÀníyànÀpẹrẹ
Bóyá o jé nítorí ìṣòro ìnáwó, ìdààmú ìbáṣepò tàbí ẹrù iṣẹ́ ńláǹlà àníyàn lè yọ́ ònà rè wọlé sínú ayé wá ní ọ̀pọ̀ ìrísí. Ó kan lè jé gbogbogbòò nímọ̀lára ti ìrora jákèjádò ní ọjọ́,ní alẹ́ ara àìbalẹ̀ pèlú àìsi oorun, tàbí àpapọ̀ ikọlu àníyàn.
Ti o ba jé Kristẹni tón kojú pèlú àníyàn, ọ̀kan lara àwon ohun tí ó lè nímọ̀lára ní ẹ́bi. “Ṣó yẹ kí n mà nímọ̀lára ní ònà yìí bí mo bá jé Kristẹni nítòótọ́?” o jé èrò to lè wọnú okàn rè lọ́pọ̀ ìgbà. Nínú Ìwé Mímó toni, Olùkọ̀wé Orin Dáfídì 55:22 so fún wá láti fún Olúwa ni àwon ẹrù ìnira wa, àtipe Óun yóò tọ́jú wa.
Ṣàkíyèsí ese Ìwé Mímó yen kò so fún wá pe ki a kan ṣàwárí ayé. Kò so pé a kò ní ìrírí àníyàn láé. Kàkà bẹ́ẹ̀, ó sowipé nígbà tí a ba se ní ẹrù ìnira ka fiwón fún Olúwa.
Ìròyìn ayo níhìn-ín: o ti wa lori òná náà láti sebe! Nípase kíkà ètò Bíbélì yìí, ó n fin hàn pé ò mọrírì pé ó kò lè nà àníyàn rè fún ara rè, àmó dípò o ní-lò ìrànlọ́wọ́ Bàbá rè ti ọ̀run. Ibi yòówù ipò rè, o jé ibi ńlá láti wa—sáré síhà Olórun.
Níhìn-ín ni ìpèníjà mi fún o lòní: gbé ìgbésẹ̀ kan si síhà fifún Olúwa ni àwon ẹrù ìnira rè. Níhìn-ín ní àwon èrò:
- lo ìséjú 5 lòní nínú àdúrà àtipe so fún Olórun ohun tón sàníyàn nípa.
- Ìwé kan nípa bí o se nímọ̀lára àti bí o n se nípa lórí rè.
- Kóra jọ pèlú òré Kristeni to fọkàn tán àtipe so fún wón nípa àníyàn rè.
Jordan Wiseman
YouVersion Media Strategist
Ìwé mímọ́
Nípa Ìpèsè yìí
Gbogbo ojó lo ṣeé ṣe fún láti gbé oríṣiríṣi ìpèníjà titun sínú ayé wá. Àmó o dọ́gba pẹ̀lú bí pé ojó titun kòòkan màa bùn wá pèlú àwon àǹfààní to yá gágá. Ní ojó-méje onífọkànsìn èyí, ọmọ-ẹgbẹ́ agbo òṣìṣẹ́ ni YouVersion ràn è lówó láti sílò òtítọ́ láti ínú òrò Olórun si ohun yòó wù ti ọ́ ń dojúko lòní. ífọkànsìn ojó kòòkan kún un ni Esẹ Bíbélì alàwòrán láti ràn è lówó láti ba o pín ohun ti Olórun n sọ̀rọ̀ sí o.
More