Ohun Méje Ti Bíbélì So Nípa ÀníyànÀpẹrẹ

7 Things The Bible Says About Anxiety

Ọjọ́ 2 nínú 7

Nígbà mìíràn àwon ohun máa ṣẹlẹ̀ ti a kò le darí tàbí sọtẹ́lẹ̀. Àníyàn máa ṣẹlẹ̀ nígbà tí ó ba lo àkókò láti ni ìdààmú ọkàn lori wón. Bóyá ó ni àníyàn nípa ìgbà ti ohun kan máa dópin tàbí ìtòlẹ́sẹẹsẹ ọjọ́ ìṣẹ̀lẹ̀ àjàkálẹ̀ ìyọnu nípase àsọdùn idààmú laisí ìdí kan pato, o kò dá wà nìkan. Kódà tí o kò bá le fojú inú wò, Olórun ní àkúnya ìrétí tí Ó tójú fún àwon to jé pé—láàárín rúkèrúdò—dúró pé tó láti gbó ohùn Rè.

Róòmù 15:13 jé àdúrà láti òdò Àpọ́sítélì Pọ́ọ̀lù sí àwon Kristẹni ní Róòmù, tó bá tẹ́tísílẹ̀, ó le gbó ohùn Olórun tó ń bá o sọ̀rọ̀. Pọ́ọ̀lù fara balẹ̀ yàn àwon òrò rè bí o se mẹ́nu kàn “Olórun onìrétí.”Ǹjẹ́ ó mú iyen? Ìrétí wa nínú é̩dá Olórun. Àmó Pọ́ọ̀lù kò bẹ̀ Olórun láti wulẹ̀ mú àníyàn wón kúrò. Ṣé Olórun le mú kúrò? Dájúdájú, sùgbọ́n ó mó pé àwon ara Róòmù yóò padà sínú o̩kò̩ kaánnà tí wón kò ba ṣàyípadà ìrònú wón. Kàkà bẹ́ẹ̀, ó bẹ̀ Olórun láti kún wón “pèlú gbogbo ìdùnnú àti àlàáfíà” nítorí nígbà tí ó ba wa ni kikún nítòótọ́ pèlú ìdùnnú àti àlàáfíà, kò sí àyè fún àníyàn.

Kò rọrùn síbẹ̀. Olórun le fi àwon ara Róòmù sínú ìpèsè àìnípẹ̀kun ìdùnnú àti àlàáfíà Rè, fikún ìkòkò èmí wón, àti laifi àyè sílẹ̀ láìkù síbì kan fún àníyàn láti sa pa mọ́. Sùgbón Olórun mó pé tí wón kò ba ṣàyípadà ìwà ọpọlọ wón, nígbà náà ìdùnnú àti àlàáfíà ní àsẹ̀yìnwá-àsẹ̀yìnbọ̀ màá fàyè sílẹ̀ fún àníyàn. Nítorí náà, Ó béèrè ohun kan kí Ó tó tú ìdùnnú àti àlàáfíà ti ọ̀run sílè apá tí ó tẹ̀ lé e gbólóhùn yen so pé “bí o gbẹ́kẹ̀ lé E.”

Ǹjẹ́ o rí i nisìnyí? Ìgbẹ́kẹ̀lẹ́ ní kó̩kó̩ró̩ ṣi ílẹ̀kùn to n fawọ́ ìkún-omi àlàáfíà àti ìdùnnú fọ́ yángá àníyàn sẹ́yìn.Ǹjẹ́ o gbẹ́kẹ̀lẹ́ Olórun? Kì í ṣe ìgbékèlé oréfèé,isé-ètè -sùgbón irú gbẹ́kẹ̀lẹ́ to fún ó láàyè láti mú owó ré kúrò ninù ohun yòó wù tí ó ń rò mó pẹ́kípẹ́kí.

Se ìgbẹ́kẹ̀lẹ́ jé búlẹ́ẹ̀tì onídán? OTI. Kò si búlẹ́ẹ̀tì onídán to le ṣèmúkúro ẹ́sẹ̀kẹsẹ̀ gbogbo àmì àníyàn gbòǹgbò gidigidi ohun alààyè. Sùgbón síbè Olórun ṣeé gbẹ́kẹ̀ lé. Àtipe nini igbẹ́kẹ̀ lé nínú Rè yorí sí pé ọkàn àti èmí ma ni ìwòsàn. Ó le jé àpáta ti o dúró le àtipe rọ̀ mọ́ bí o n se baa àníyàn jìjàkadì gbámú lara rè.

Olórun lo ye fún ìgbẹ́kẹ̀lẹ́ wa to jinlẹ̀. Nígbà tí a ba ìgbẹ́kẹ̀ lẹ́ E, O kún o pèlú ọ̀pọ̀lòpò ìdùnnú àti àlàáfíà pé wá túmọ̀ sí àkúnwọ́sílẹ̀ pèlú ìrètí. Ó le ma ní èrò bí o se rí lára, àtipe o le ma rọrùn rárá láti gbẹ́kẹ̀ lé Olórun. Sùgbón lájorí ìgbẹ́kẹlé ní jáde síta àti gbígba áyè nígbà tí ó kò mó ohun tó máa ṣẹlẹ̀ lẹ́yìn náà.

Se ò lè wá ígboyà bíi láti yo owó rè kúrò nínú àwon ohun ti ó ń rò mó pẹ́kípẹ́kí àtipe gbẹ́kẹ̀ lé Olórun lòní?

Michael Martin
YouVersion Web Developer

Ìwé mímọ́

Day 1Day 3

Nípa Ìpèsè yìí

7 Things The Bible Says About Anxiety

Gbogbo ojó lo ṣeé ṣe fún láti gbé oríṣiríṣi ìpèníjà titun sínú ayé wá. Àmó o dọ́gba pẹ̀lú bí pé ojó titun kòòkan màa bùn wá pèlú àwon àǹfààní to yá gágá. Ní ojó-méje onífọkànsìn èyí, ọmọ-ẹgbẹ́ agbo òṣìṣẹ́ ni YouVersion ràn è lówó láti sílò òtítọ́ láti ínú òrò Olórun si ohun yòó wù ti ọ́ ń dojúko lòní. ífọkànsìn ojó kòòkan kún un ni Esẹ Bíbélì alàwòrán láti ràn è lówó láti ba o pín ohun ti Olórun n sọ̀rọ̀ sí o.

More

A se kikò àti ipèsè ètò yìí láti ọwọ àjọṣepọ̀ ní YouVersion. Sabẹ̀wò youversion.com fun àlàyé síwájú sí.