Ohun Méje Ti Bíbélì So Nípa ÀníyànÀpẹrẹ
Àníyàn le lero pé kò seé sọ tẹ́lẹ̀. ìṣẹ́jú kan o dára. Ni tí ó tẹ̀lé e, ati gbá é sínú ìgbì àìsàn ìdààmú okàn àti rúkèrúdò ọpọlọ. Ó sí mí kanlẹ̀. Pa ojú rè dé.Se èsì iparọ́rọ́ ti ara tí wón kó è láti máa se nígbà tí àníyàn ba gbógun sí è. Àmó àníyàn kì í ni ipa lórí wá rara ni ti ara. O gba ìṣàkóso ohungbogbo.
Ìdí niyen ti a gbódò jé kí èsì ti ara wá jé alábàáṣiṣẹ́ pèlú òdodo tèmí to ràn wá lówó làti sún àfiyèsí wá. Okàn wá ní láti wa ni ìsimi. Bíbélì ràn wa lówó láti satúnse àti se iparọrọ okàn wa.
Èkíní, a ní láti gbé ohun ìjà ogun fún arawa pèlú Ìwé Mímọ́ nígbà tí àwa ní ipò ọ̀tún ti okàn pé nígbà tí àtakò bá wá, a ti múra tán láti jà. Há Ìwé Mímọ́ sórí pé o le lo gégé bí ohun ìjà nígbà tí àwon ìgbì ti àníyàn bá balẹ̀. Àwon ẹsẹ bíbélì rán wá létí òdodo nípa Olórun àti fi ojú wa kúrò lọ́dọ̀ ohun tón áájú wa lo sibi òkùnkùn.
Aísáyà 12:2 so fún wá pé a le gbẹ́kẹ̀lẹ́ Olórun láti gbà wá là, àtipe a kò ní láti fòyà. Báwo ni yen se lagbára to? a kò ní láti fòyà. A le gbẹ́kẹ̀lẹ́ Olórun. Òun yóò gbà wá là. Òun ní Olúwa. O borí ohun gbogbo, àtipe O le gbà wå sílẹ̀, kò sí bó o ṣe lè jìnà ti a lero pé a ti lo.Ó wà níbẹ̀.
Nígbà tí a ba kún okàn wa pèlú àwon gbólóhùn bí èyí, a yànda fún Olórun láti gbé erù okàn ìnira wa kúrò àti fún wá ni ìsimi. Àwon gbólóhùn tún fún wá ni agbára láti jà àti lé borí àwon ìjà to dojú kọ wa.
se àsọtúnsọ àwon gbólóhùn wọ̀nyí títí yóò ní mọ̀lára pé ìgbì àníyàn kojá nítorí sise àsọtúnsọ òtítọ́ tu wá sílẹ̀ láti owo àwon irọ́ àníyàn.
Olórun fé irú igbára lé èyí láti òdò wá. A kò ní láti dùrò dè ìṣẹ̀lẹ̀ ìjà adaniláàmú tí ọpọlọ láti máa sàṣàrò lori òrò Rè. Mo nígbàgbọ́ pé nígbá tí okàn mi gbájú mọ́ òtítọ́ tí Ìwé Mímọ́, àwon itanná ran tón fígbà kan wá pọ̀ lápọ̀jù lori mi agbára wón ti dín kú(see Romans 8:6).
Lọ sọ́dọ̀ Olórun nípase òrò Rè. Jé kí Ó ṣàkóso àwon èrò rè àti yanjú àníyàn nínú okàn rè to tẹ̀dó sí ábẹ́ the oréfèé lásán. Yan láti fún Ú ní èrù rè. Gbẹ́kẹ̀lẹ́ È láti gbà ó là.
Jessica Penick
YouVersion Content Manager
Nípa Ìpèsè yìí
Gbogbo ojó lo ṣeé ṣe fún láti gbé oríṣiríṣi ìpèníjà titun sínú ayé wá. Àmó o dọ́gba pẹ̀lú bí pé ojó titun kòòkan màa bùn wá pèlú àwon àǹfààní to yá gágá. Ní ojó-méje onífọkànsìn èyí, ọmọ-ẹgbẹ́ agbo òṣìṣẹ́ ni YouVersion ràn è lówó láti sílò òtítọ́ láti ínú òrò Olórun si ohun yòó wù ti ọ́ ń dojúko lòní. ífọkànsìn ojó kòòkan kún un ni Esẹ Bíbélì alàwòrán láti ràn è lówó láti ba o pín ohun ti Olórun n sọ̀rọ̀ sí o.
More