Ohun Méje Ti Bíbélì So Nípa ÀníyànÀpẹrẹ
Nínú ìwé tí Róòmù, Pọ́ọ̀lù so pé ní àsìkò tí ó jẹ́wọ́ Jésù ní Olúwa àti Olùgbàlà rè, ó tí wa nitẹ́wọ́ gbà sinú ebí Olórun, àtipe Ó tí di Bàbá Rè. Olórun kì í se Bàbá lásán. Bàbá rè tí ayé jé ènìyan àti èlesè, ó túmọ̀ sí pé ó tí já o kulẹ̀ sẹ́yìn rí…àtipe ó le já ó kulẹ̀ lọ́jọ́ iwájú.
Olórun jé pípé àti dára. Kò le já ó kulẹ̀ láé. Sefaniah3:17 ṣàpèjúwe ifé àràmàǹdà tí Bàbá rè tí òrun fún o: Ó wa pèlú rè, Ó ní inú dídùn nínú rè, àtipe Ó yọ̀ gidigidi lórí rè! Sefaniah so pé Olórun tun jé aláàbò rè àti onìtùnú rè.“Pèlú ifé Rè, Yóò fẹ̀sọ̀ sí gbogbo àwon èrù rè.”
Orin Dáfídì 139 so pé Olórun ti ń mbe pèlú rè láti ígbà tí o kọ́kọ́ bèrè sińi dagba ninú ìyá rè, àtipe Òun yóò wá pèlú rè níbikíbi to bá lo. Ìwo jé àgbàyanu iṣẹ́ tí ìsèdá Rè, àtipe Òun ní alátìlẹyìn rè tó tóbi jù lọ bí o se ṣàwárí àti gbé gbogbo Tó sèdá rè láti jé.
Ya àwòrán yìí: omo kan ń sùn lórí ibùsùn o sùn lọ nígbà tí ìjì líle oni mànàmáná tó ń yára gbilẹ̀ si ní igbóná janjan, bí òru náà seń bá a lọ.Ijá lulè òjijì tí mànàmáná àti ààrá ta omo náà gìrì láti ójú oorun, àtipe léyìn iké fún ìrànlọ́wọ́, bàbá onífẹ̀ẹ́ rè sáré lọ síbe àtipe lọ́ apá rè yí omo náà ká. Gégé bí òbí yen, Olórun fìgbà gbogbo wà lárọ̀ọ́wọ́tó sí ó.Nínú ifé Rè, Yóò fí iparọ́rọ́ si gbogbo àwon èrù rè.
Kylyn Hersack
YouVersion Android Engineer
Ìwé mímọ́
Nípa Ìpèsè yìí
Gbogbo ojó lo ṣeé ṣe fún láti gbé oríṣiríṣi ìpèníjà titun sínú ayé wá. Àmó o dọ́gba pẹ̀lú bí pé ojó titun kòòkan màa bùn wá pèlú àwon àǹfààní to yá gágá. Ní ojó-méje onífọkànsìn èyí, ọmọ-ẹgbẹ́ agbo òṣìṣẹ́ ni YouVersion ràn è lówó láti sílò òtítọ́ láti ínú òrò Olórun si ohun yòó wù ti ọ́ ń dojúko lòní. ífọkànsìn ojó kòòkan kún un ni Esẹ Bíbélì alàwòrán láti ràn è lówó láti ba o pín ohun ti Olórun n sọ̀rọ̀ sí o.
More