Ohun Méje Ti Bíbélì So Nípa ÀníyànÀpẹrẹ
Ní ayé, ìwo yóò ní ìdààmú. Nítorí é̩dá ẹ̀leṣẹ̀ wa àti àwon ètekéte òtá,a lè rí ìdààmú kárí ayé. Kò yẹ kó yà wá lẹ́nu nípa àwon ìdààmú wa; Jésù so fún wa gbàǹgbà pé a máa ní ìdààmú nínú ayé yìí. Kí nìdí to fi so be? Nítorí pé Ó jẹ́ olóòótọ́, àtipe Ó nífé wa. Nípase sise ìmúrasílẹ̀ wa ṣaaju, Jésù n ràn wá lówó láti yẹra fún iyèméjì àti èrù nígbà tí a ba rí arawa nínú ìgbà lilè.
Jésù fi ohun ti ìgbọràn onírẹ̀lẹ̀ dà bí hàn wa. Ó se ìgbọràn nípase àwon ohun tolè jìnà jú ti ọ̀pọ̀ nínú wa yóò kojú láé—kódà sí ikú lori àgbélébùú. Nìnsìnyí gan-an, Ó jókòó sí owó ọ̀tún Olórun Bàbá náà,tón bẹ̀bẹ̀ fún àǹfààní wa. A lè rí ìtùnú ní mímọ pé a ní ọ̀rẹ́ tón báni kẹ́dùn pèlú àwọn àìlera wa.
A lè ṣe ayẹyẹ ní mímo pé gbogbo àjò lile sún wa mọ́ sí Kristi àti ìjọba àìnípẹ̀kun Rè.. Èyí ní ìrètí: Jésù Kristi tí ṣẹ́gun èsè àti ikú títí láé. Ikú kò lè mú u dání, sàréè kò lè kún nínú Rè, agbára èsè kò lè borí Rè, àti òkùnkùn kò lè borí lòdí sí Rè!
Níwọ̀n bí isé Kristi to tí parí lorí àgbélébùú fàyè gba wa láti jé àwon ọmọ Olórun, awa lè tun borí èsè. Jésù tí borí ayé—àtipe iyen títí kan gbogbo ipò lile tí ó wà nínú rè. Nìsinsìnyí, a lè fojúsọ́nà sí ilé ayérayébwá pèlú Jésù.
Jacob Allenwood
YouVersion Web Developer
Ìwé mímọ́
Nípa Ìpèsè yìí
Gbogbo ojó lo ṣeé ṣe fún láti gbé oríṣiríṣi ìpèníjà titun sínú ayé wá. Àmó o dọ́gba pẹ̀lú bí pé ojó titun kòòkan màa bùn wá pèlú àwon àǹfààní to yá gágá. Ní ojó-méje onífọkànsìn èyí, ọmọ-ẹgbẹ́ agbo òṣìṣẹ́ ni YouVersion ràn è lówó láti sílò òtítọ́ láti ínú òrò Olórun si ohun yòó wù ti ọ́ ń dojúko lòní. ífọkànsìn ojó kòòkan kún un ni Esẹ Bíbélì alàwòrán láti ràn è lówó láti ba o pín ohun ti Olórun n sọ̀rọ̀ sí o.
More