Ìtọ́sọ́nà Àtọ̀runwáÀpẹrẹ

Divine Direction

Ọjọ́ 3 nínú 7

Dúró

Mo tí rò lópò ìgbà nípa bí ayé mi má se yàtò sí tí mba tí juwọ́ sílẹ̀ nígbà tí mo fé se. Ìtàn mi lè tí dí ohun kan bíi , “ Béèni, Mo máa ń rò tẹ́lẹ̀ péo ye kí jé àlùà, àmó mo gbìyànjú àtipe àwon ohun kò kése járí. Béè gégé gan-an lo se lo.”

Ó dá mi lójú pé ó ní láti jìjàkadì pèlú àwon ìpèníjà lẹ́ẹ̀kọ̀ọ̀kan nígbà òtòòtò ní ayé rè:ògá ibi isé tí o kò ro pé o lè fara mó lójó mìíràn, ìbáṣepọ̀ tó n ṣèpalára fún o lójijì,ìran tí àwọn ohun èlò è tán lo, ìgbésè tó kuná àwon ìretí rè.Nígbà tí ó bá kojú àwon ìsòro ,ìwà èdá ní láti ronú wò àwon ìpinnu ńlá tó l è mú àyípadà bá ìgbésí ayé ènì. O lè béèrè àwon ìbéèrè bíi wònyí

    Se kín gbé ìgbésẹ̀ eléwu, kí fi isus ílè,àti wà ohun mìíràn?
  • Léyìn oràn aya tàb oko rè—se àkòkó tí to láti máa lo?
  • li>Se mo tóótun láti bójú tó isé òwò? Se kí gé àwon àdánù mi kí àwon nñkan tó burú sí?< p>Nínú àpẹẹ rẹ of àwon kọ̀ọ̀kan wònyìí—àti pèlú òpò lájorí ìpinnu ìgbé ayé —o wa ní ìkóríta tô se pàtàkì lojú ònà, àtipe àkòkó tí to láti pinnu: se ki dúró tàbí ki yera?

    Sé mo fé yàn láti juwó sílè nítorí o jé ohun tó tóótun láti se tàbí nítórí o dà bí pé kikúrò jé ohun tó rorùn?

    Ìpinnu tó dára jù àti tí ó sì ń mú èrè wá jùlọ tó lè se ní láti dúró sí ònà ìgbésé kódà nígbà tí o má rorùn láti yíju padà àti yera kúrò. Mi o sò wipé o kò ní láti yera kúrò láé. Àmó kí o to se ìpinnu, béèrè lówó ara rè, “Sé mo n yàn láti juwó sílè nítórí o jé ohun tó tóótun láti se tàbí nítórí o dà bí pé kikúrò jé ohun tó rorùn?” Nígbà mìíràn ìṣe ìgbàgbọ́ tó dára jùlo ní jijé olóòótọ́, didúró sibi tí a gbin e sí. Odún sígbà ta wà yí o lè bojú wẹ̀yìn wo àtipe dúpé lówó Olórun pé o pinnu láti dúró nígbà tí o pè tí rorùn láti lo.

    Rántí, Olórun sèdá o ní àwòrán Rè àtipe Òun ní olùkọ̀wé àti alásepe ìtàn è. O kì i se ènì tón juwó sílè. Aláseparí ní e.

    Gbàdúrà: Olórun, Sé ohun kankan wà tí mo ń gbìyànjú láti yera fún ti E fé jé ki dúró àti parí? Sé E máa fún mi lókun láti tẹ̀ síwájú? Àmín.

Ọjọ́ 2Ọjọ́ 4

Nípa Ìpèsè yìí

Divine Direction

Lójojúmọ́, a ma ńṣe àwọn àṣàyàn tó ń tọ́ ipa nínú ìtàn ìgbésí ayé wa. Báwo ni ìtàn ìgbésí ayé rẹ yóò ti rí tí o bá ṣe àwọn àṣàyàn tó dára? Nínú Ètò Bíbélì Ìtọ́sọ́nà Àtọ̀runwá, gbajú-gbajà ònkọ̀wé New York Times àti Olùṣọ́àgùntàn àgbà ní ìjọ Life.Church, Craig Groeschel, máa gbà ọ́ níyànjú pẹ̀lú àwọn ìlànà méje tí a fà jáde látinú ìwé Ìtọ́sọ́nà Àtọ̀runwá fún ìrànlọ́wọ́ láti ṣe àwárí ọgbọ́n Ọlọ́run fún àwọn ìpinnu tí à ńṣe lójojúmọ́. Ṣe àwárí àwọn ìtọ́ni ti ẹ̀mí tí o nílò láti gbé ìgbésí ayé tó bọ̀wọ̀ fún Ọlọ́run.

More

A fé láti dúpé lówó Àlùfáà Craig Groeschel àti Life Church fún ìpèsè ètò yìí. Fun àlàyé síwájú sí, jọ̀wọ́ lọ sí: http://craiggroeschel.com/