Ìtọ́sọ́nà Àtọ̀runwáÀpẹrẹ
![Divine Direction](/_next/image?url=https%3A%2F%2Fimageproxy.youversionapi.com%2Fhttps%3A%2F%2Fs3.amazonaws.com%2Fyvplans%2F3670%2F1280x720.jpg&w=3840&q=75)
Dáwó dúró
Oókan lára ìpinnu tó dára jù tí a lè se nígbà tí a n bá nímòlára agbára ìsúnniṣe tàbí ń kojú ìsòro ñla dáwó dúró. Wá àkókò díè. Gbàdúrà fún ìtọ́sọ́nà. Fẹ̀gbẹ́ lélẹ̀ sùn lórí è. Gbà àwon ogbón Olórun láti òdò àwon ènìyàn tó fokàn tán àtipe ya àwòràn ohun tí ó ṣeé ṣe kí ó jẹ́ àbájáde. Léyìn náà, bí ara rẹ léèrè, “Ñjé èyí jé ohun tó yé kí ñ dáwó dúró pátápátá?”
Òpò lára wa ni àwon èrò tó dáa tàbí ó kéré tán ìdáláre kan fún àwon ohun tá ñ se. Àtipe ó dà bíi pé ó yà òpò lára wa lẹ́nu nígbà tí a bá ri ara wa ní ònà tó jìnnà láti ìtọ́sọ́nà tí a fé lo. Àwon ìyipada ñla nínú ayé wá—àwọn méjèèjì fé pé kí o jáde wá ṣáájú àti so fún mi gbogbo ohun tón selè tó dára tàbí ohun tí kò dára—kì í sábà selè láìsí orísirisí ìpinnu tón tó lórí ara wón àwon onítẹ́tẹ́-tí kó lópin.
Ǹjẹ́ o rí bí didáwó dúró lè jé oòkan lara ohun tó lè méso jáde jù lo tí a se? Nígbà tí ó bá dáwó dúró láti sàyèwò ibi tó wa àti ibi tó fé lo nígbà náà ó lè pinnu lórí bí ó má se gbéra lo síhá èbúté rè.
Ohun tó lè dáwó dúró láti lè sún mó ìtọ́sọ́nà àtọ̀runwá tí Olórun?
Se ó ñ se ohunkankan tó mú o síhá ìtósónà tí o kò fé lo (tàbí tí Olórun kò fé jé kí o lo)? Kí lo nílo láti dáwó dúró pátápátá? Bárakú sí ìkànnì àjọlò, otí àmújú, àwòrán oníhòòhò, àfowósí, tàbí isé? Ìbáṣepò tó léwu? Se ìwà onídájọ́ ni? Kí lo lè dáwó e dúró láti mú o sún mó sí ìtọ́sọ́nà àtọ̀runwá tí Olórun? Máa wo ìpinnu kọ̀ọ̀kan bíi pé òun ni òkúta àtẹ̀gùn tó tẹ̀ lé e síhà èbúté rè.
Nígbà tí ìwà tàbí ìbáṣepò mú wa sí ìtọ́sọ́nà tí a mo pé ó ñ sún wa jìnnà sií láti òdò ìtàn tí a fé, a ní láti dúró díè kii ṣe láti ṣàgbéyẹ̀wò àwon àbájáde nìkan àmó láti tún yàn láti dáwó dúró nínú rinrin ìrìn-àjò ìtọ́sọ́nà òdì. Ó lè jé pé ó tí gbò ó̩ró̩gbólóhùn “ ronú pìwà dà.” Òkan lára túmọ̀ ní ṣangiliti sí rè ni láti yí padà. Nígbà tí ó ba ronú pìwà dà, ó dékun láti forílé ìtọ́sọ́nà kan àti padà sí ódó Olórun àti ìpa ònà Rè fún ó.
Lọ́nà yìí, di dáwó dúró túmọ̀ sí gbígbé ìgbésè sínú ìtọ́sọ́nà tuntun. Ó lè ní láti gbé ìgbésè síhà àkọsílẹ̀, ìdáríjì, àwọn òrẹ́ tó yẹ, tàbi ibi tuntun láti gbé.
Bí ara rẹ léèrè:
1. Tí o bá se ìpinnu tí mo ñ jíròrò, ibo lo lè mú mi lo?
2. Kí ni mo lè dáwó e dúró kí ñ bá lè sún mọ́ ìtọ́sọ́nà àtọ̀runwá ti Olórun?
Nípa Ìpèsè yìí
![Divine Direction](/_next/image?url=https%3A%2F%2Fimageproxy.youversionapi.com%2Fhttps%3A%2F%2Fs3.amazonaws.com%2Fyvplans%2F3670%2F1280x720.jpg&w=3840&q=75)
Lójojúmọ́, a ma ńṣe àwọn àṣàyàn tó ń tọ́ ipa nínú ìtàn ìgbésí ayé wa. Báwo ni ìtàn ìgbésí ayé rẹ yóò ti rí tí o bá ṣe àwọn àṣàyàn tó dára? Nínú Ètò Bíbélì Ìtọ́sọ́nà Àtọ̀runwá, gbajú-gbajà ònkọ̀wé New York Times àti Olùṣọ́àgùntàn àgbà ní ìjọ Life.Church, Craig Groeschel, máa gbà ọ́ níyànjú pẹ̀lú àwọn ìlànà méje tí a fà jáde látinú ìwé Ìtọ́sọ́nà Àtọ̀runwá fún ìrànlọ́wọ́ láti ṣe àwárí ọgbọ́n Ọlọ́run fún àwọn ìpinnu tí à ńṣe lójojúmọ́. Ṣe àwárí àwọn ìtọ́ni ti ẹ̀mí tí o nílò láti gbé ìgbésí ayé tó bọ̀wọ̀ fún Ọlọ́run.
More
Awọn Ètò tó Jẹmọ́ọ
![Wíwá Ọkàn Ọlọ́run Lójoojúmọ́ - Ọgbọ́n](/_next/image?url=https%3A%2F%2Fimageproxy.youversionapi.com%2Fhttps%3A%2F%2Fs3.amazonaws.com%2Fyvplans%2F13048%2F320x180.jpg&w=640&q=75)
Wíwá Ọkàn Ọlọ́run Lójoojúmọ́ - Ọgbọ́n
![Gbígbé Nípa Ti Ẹ̀mí Mímọ́: Ẹ̀kọ́ Àṣàrò Bíbélì Pẹ̀lú John Piper](/_next/image?url=https%3A%2F%2Fimageproxy.youversionapi.com%2Fhttps%3A%2F%2Fs3.amazonaws.com%2Fyvplans%2F3841%2F320x180.jpg&w=640&q=75)
Gbígbé Nípa Ti Ẹ̀mí Mímọ́: Ẹ̀kọ́ Àṣàrò Bíbélì Pẹ̀lú John Piper
![Ètò Olúwa Fún Ayéè](/_next/image?url=https%3A%2F%2Fimageproxy.youversionapi.com%2Fhttps%3A%2F%2Fs3.amazonaws.com%2Fyvplans%2F11674%2F320x180.jpg&w=640&q=75)
Ètò Olúwa Fún Ayéè
![Àwọn Ádùrá Tí Ó L'éwu](/_next/image?url=https%3A%2F%2Fimageproxy.youversionapi.com%2Fhttps%3A%2F%2Fs3.amazonaws.com%2Fyvplans%2F18063%2F320x180.jpg&w=640&q=75)
Àwọn Ádùrá Tí Ó L'éwu
![Ẹnití a Yàn: Rán Ara Rẹ Létí Ìhìnrere Lójoojúmọ́](/_next/image?url=https%3A%2F%2Fimageproxy.youversionapi.com%2Fhttps%3A%2F%2Fs3.amazonaws.com%2Fyvplans%2F12737%2F320x180.jpg&w=640&q=75)
Ẹnití a Yàn: Rán Ara Rẹ Létí Ìhìnrere Lójoojúmọ́
![Àwọn Ìlànà Àńtẹ̀ẹ̀lé Fún Ìmójútó Àkókò Láti Inú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run](/_next/image?url=https%3A%2F%2Fimageproxy.youversionapi.com%2Fhttps%3A%2F%2Fs3.amazonaws.com%2Fyvplans%2F11397%2F320x180.jpg&w=640&q=75)
Àwọn Ìlànà Àńtẹ̀ẹ̀lé Fún Ìmójútó Àkókò Láti Inú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run
![Wiwá Àlàáfíà](/_next/image?url=https%3A%2F%2Fimageproxy.youversionapi.com%2Fhttps%3A%2F%2Fs3.amazonaws.com%2Fyvplans%2F13452%2F320x180.jpg&w=640&q=75)
Wiwá Àlàáfíà
![Ohun Méje Ti Bíbélì So Nípa Àníyàn](/_next/image?url=https%3A%2F%2Fimageproxy.youversionapi.com%2Fhttps%3A%2F%2Fs3.amazonaws.com%2Fyvplans%2F4538%2F320x180.jpg&w=640&q=75)
Ohun Méje Ti Bíbélì So Nípa Àníyàn
![Jésù: àsíá Ìṣẹ́gun wa](/_next/image?url=https%3A%2F%2Fimageproxy.youversionapi.com%2Fhttps%3A%2F%2Fs3.amazonaws.com%2Fyvplans%2F14894%2F320x180.jpg&w=640&q=75)