Ìmọ̀lára Mímọ́ - Èsì Látinú Bíbélì sí Ìpèníjà GbogboÀpẹrẹ

Holy Emotions - Biblical Responses to Every Challenge

Ọjọ́ 3 nínú 30

O dìgbà ti o bá gbà àgbàrá To ti ṣèdá fún e láti gbà ki o to di ẹnì Tó ṣèdá e láti jé. Mo lè jẹ́ ẹnìkan to máa ń nimọ̀lára gan-an to jé pe ǹkan ti mo máa n se lórí owó mi ni kí ń máa ronú nípa ará mi àti ìmọ̀lára mi. A kò dá o láti fí àwọn ìmọ̀lára e ti o kò lè kápá hàn, a dá ọ fún èso , fún isé réré, fún Ìjọba Ọlọ́run àti àgbàrá!

Gbólóhùn òrò wo tón yàtò wa nínú ìwé mímó tó ń yí ìgbésí ayé ẹni pa dà ti a máa ka lónìí tó máa gbe e lórí ípà ònà ayanmo èrò ìmọ̀lára e. "E yóò gbà àgbàrá," bóyá gbólóhùn tó fani lọ́kàn mọ́ra nínú gbogbo Májẹ̀mú títún. Ìwọ yóò gbà àgbàrá! O kò ni láti hùwà ẹhànnà nínú ayé pẹ̀lú ̀lú okun e! O kò ni láti ni ìtẹ́lọ́rùn pẹ̀lú àwọn ìmọ̀lára egbin àti erù ìrandiran! O kò lè lọ àsè lórí ìmọ̀lára eléwèlè àyàfi ti o ba gbà àgbàrá Èmí Mímọ́. Gbígbà àgbàrá Èmí Mímọ́ máa jé ki o da eni ti Olorun ṣèdá láti jé! O nílò àgbàrá Olórun ki o bá lè di witne ìṣẹ̀dá E ni irú àsìkò yìí nínú ìtàn. O máa gbà àgbàrá yóò si jé!

Yo kò lè eni ti Olórun fẹ́ fún o àyàfi ti o bá gbà àgbàrá E. Jésù mò pé a kò ni lè gbé ìgbé ayé òpò yanturu lórí ilé ayé yìí láìsí àgbàrá Èmí Mímọ́ O si pèsè àgbàrá yìí gan náà. Mo máa gbàdúrà yìí dáadáa nígbà mìíràn láìmòyè ìgbà lójoojúmo nítorí mo jé obìnrin to ń fé nǹkan lójú méjèèjì:

Èmí Mímọ́, kún mi pẹ̀lú àgbàrá E! Mo fé gbogbo nǹkan ti e ni fúnmi , Mo fé ẹ̀bùn E àti àwọn èso E. Mo fé àgbàrá E ju ohunkóhun lo lónì. Ti O ba fe je kin gbàdúrà fún isé ìyànú ati ìwòsàn, Mo máa se, tori náà E kà mi mo o! Mo fé gbogbo ohun te ni fummi mi. Mo fé sùúrù àti ìkóra-ẹni-níjàán ati àfikún àlàáfíà ìdùnnú pẹ̀lú ìfẹ́. Mo máa gbà gbogbo àgbàrá tí E sétan láti fummi sọ́dọ̀ mi .

Lẹ́yìn náà ki lo máa ṣe? O dáa ... nígbà náà o máa se ohun tí ẹnì ti èrò ìmọ̀lára e ti múratán korira láti máa se nítorí lẹ́yìn àdúrà yìí - o máa dúró.

Ìwé mímọ́

Ọjọ́ 2Ọjọ́ 4

Nípa Ìpèsè yìí

Holy Emotions - Biblical Responses to Every Challenge

Ọlọ́run dá ọ Ó sì fi ọ sí àyè tí o wà ní irú àkókò yìí, to love the unlovable, bii àlàáfíà nínú rúkè rúdò, kí o sì fi ayọ̀ tí kò ṣeé dẹ́kun nínú ìṣẹ̀lẹ̀ gbogbo. À ti ṣe bẹ́ẹ̀ lè jọ pé kò ṣeéṣẹ, ṣùgbọ́n o le è ṣeé tí o bá kọ́ oun tí Bíbélì sọ nípa àwọn ìmọ̀lára ọkàn rẹ gẹ́gẹ́ bí ènìyàn àti bí o tilè ṣàkóso wọn. Ètò ẹ̀kọ́ yìí dá lórí àwọn ohun tí a kò kà sí àti nígbà míràn awon ohun ìdojúkọ tí kìí ṣe lásán tí à ń bá pàdé lojojúmọ́, ó sì fún wa ní ìtọ́kasí ẹsẹ̀ Bíbélì láti ṣàkóso ìmọ̀lára wa ní ọ̀nà bíi ti Ọlọ́run.

More

A fẹ́ dúpẹ́ lọ́wọ́ Carol McLeod and Just Joy Ministries fún ìpèsè ètò yìí. Fún àlàyé díẹ̀ síi, jọwọ lọsí: www.justjoyministries.com