Ìmọ̀lára Mímọ́ - Èsì Látinú Bíbélì sí Ìpèníjà GbogboÀpẹrẹ
Nígbà tí a bá wà pẹ̀lú ara wa, Ó wá pẹ̀lú wá. Tí ó bá fẹ́ ló àsìkò pẹ̀lú Ọlọ́run, gbìyànjú ló ìrọ̀lẹ́ ọjọ kan pẹ̀lú àwọn ènìyàn tí ó ní ìfẹ́ Rẹ̀. Tí ó bá ní ìmọ̀lára pé ìwọ nìkan ní ó dá wà, ránsẹ́ pé àwọn ènìyàn díẹ̀ tí ó bá nifẹ sí àdúrà gbígbà àti pé Ta tún ní ó lérò pé yíò wọlé tọ̀ọ́ wá?
Ọlọ́run ń gbé ibi tí ó bá kún fún ìyìn tí ó sì lágbára. Tí ó bá fẹ́ kí ó fí bí ó ṣe jẹ́ hàn ọ àti pé kí ó di mímọ̀ fún ọ, nígbà yí ní ó ní láti ló ìgbé ayé rẹ láti máà jọsin fún wẹ́lẹ́wẹ́lẹ́. Ọlọ̀run a máà fí bí ó ṣe jẹ́ hàn nígbàtí ọkùnrin tàbí obìnrin tí ó bá mọ Ọlọ́run kò náà ni àwọn ohun ayé àti àyídáyidà rẹ ti wọn sì kún fún ọkàn ìjọsìn tí ó lọ́rìnrìn. Tí ó bá sì ń kojú ìdánìkànwà yí orin ìjọsìn rẹ sókè kí ó sì nà ọwọ rẹ sókè nínú afẹ́fẹ́ nítorí nibẹ ní Ó wà! Ìwọ kò dánìkànwà. Kọrin sókè kí ó sì jẹ̀ki ó ní agbára! Ó wà níbẹ̀! Ìwọ kò dánìkànwà! Kọrin nínú ọkọ ayọ́kẹ́lẹ́ àti ní ibalùwẹ̀ rẹ! Òun yíò sì wà pẹ̀lú rẹ. Nígbàkúùgbà tí ó bá pinu láti jọsin sì ì ṣe ni ó gbé ara rẹ sí iwájú Rẹ̀. Ìwọ kò dánìkànwà. Láì.
Tí mo bá tí jẹ́ oníṣègùn, àti pé mo rò pé mo jẹ kan..... mo jẹ oníṣègùn tí ẹ̀mí nítorí ìdí èyí jẹ́ kí nkọ ìwé ìlànà òógùn fún ìdánìkànwà. Kọ ìwé yí sì ẹlòmíràn ó kéré jù èrìmẹ́ta ní ọjọ́ kan. Ìdánìkànwà rẹ yíò rí àwòtán nígbàtí ó bá ní àníyàn díẹ̀ sí nípa bíbá àìní ẹlòmíràn pàdé jù ìgbé ayé rẹ nìkan lọ. Rẹ́rin sí ẹnikan nínú ilé itaja. Kọ̀wé sí ọrẹ rẹ àtijọ́ kan tí ẹ jọ jáde ìwé gíga kí ẹ sí jọ tẹ síwájú pẹ̀lú àjosepọ̀ yín. Má ṣe pá lọ́lọ́ tàbí kí ó joko sì ilé láti máà wo ẹ̀rọ amóhùnmáwòràn, nítorí ìwọ yíò rí pé fífi fúnni ní ó ńṣe àwòtán fún ìdánìkànwà.

Ìwé mímọ́
Nípa Ìpèsè yìí
Ọlọ́run dá ọ Ó sì fi ọ sí àyè tí o wà ní irú àkókò yìí, to love the unlovable, bii àlàáfíà nínú rúkè rúdò, kí o sì fi ayọ̀ tí kò ṣeé dẹ́kun nínú ìṣẹ̀lẹ̀ gbogbo. À ti ṣe bẹ́ẹ̀ lè jọ pé kò ṣeéṣẹ, ṣùgbọ́n o le è ṣeé tí o bá kọ́ oun tí Bíbélì sọ nípa àwọn ìmọ̀lára ọkàn rẹ gẹ́gẹ́ bí ènìyàn àti bí o tilè ṣàkóso wọn. Ètò ẹ̀kọ́ yìí dá lórí àwọn ohun tí a kò kà sí àti nígbà míràn awon ohun ìdojúkọ tí kìí ṣe lásán tí à ń bá pàdé lojojúmọ́, ó sì fún wa ní ìtọ́kasí ẹsẹ̀ Bíbélì láti ṣàkóso ìmọ̀lára wa ní ọ̀nà bíi ti Ọlọ́run.
More
A fẹ́ dúpẹ́ lọ́wọ́ Carol McLeod and Just Joy Ministries fún ìpèsè ètò yìí. Fún àlàyé díẹ̀ síi, jọwọ lọsí: www.justjoyministries.com