Ìmọ̀lára Mímọ́ - Èsì Látinú Bíbélì sí Ìpèníjà GbogboÀpẹrẹ
Idáníkànwà kan jé ìmọ̀lára pé kò sí ẹnì to bìkítà nípa e tàbí nípa ayé e. Idáníkànwà lè jẹ́ bóyáⁿ èrò ìmọ̀lára tóń páni jùlo lára gbogbo ìmọ̀lára. Ti Èṣù kò ba lè gbé o ṣubú pẹ̀lú àníyàn àti ìbẹrù, o ma gbìyànjú láti so e di àjèjì láti inú àwọn ìbásépò to dán moràn nítorí kódà Sátánì mò àgbàrá ẹnì méjì!
Bo ti lè jẹ́ pé o lè nimọ̀lára idáníkànwà, o gbọ́dọ̀ rán ará e létí pé o kò dáníkànwà lóòótọ́ nítorí Bíbélì ṣèlérí e. Èyí ní òkan lára àwọn àsìkò pàtàkì ayé nígbà ti o gbọ́dọ̀ má rán ará e léti pé àwọn ìmọ̀lára e kò lẹ́sẹ̀ nílẹ́. Nígbà tí ọkàn rẹ ba gbìyànjú láti sò fún e pé o dáníkànwà àti kò si eni tó bìkítà nipa e pẹ̀lú ayé e, ọkàn e ń ti bá ṣòrò pẹ̀lú Sátánì o sin fetí si àwọn ìró búburú e.
Tí a mba ṣòro nípa Idáníkànwà sí Bíbélì e kí o si fohùn ṣọ̀kan pẹ̀lú ó̀rọ̀ Ọlọ́run kìí se pẹ̀lú ìmọ̀lára e ti o káàánú fún un. Àwọn gbólóhùn òrò ìkẹyìn ti Jésù sò fún àwon ọmọ eléyìn E ní pé O rán wón letí pé bo ti lè jé pé wọ́n kò ni lè ri Òun mò pẹ̀lú ojú wón, pé Òun má wa pẹ̀lú wón nígbà gbogbo: "Mo wà pẹ̀lú yin nígbà gbogbo, kódà titi òpin ayé" (Mátíù 28:20).
Àkòrí òrò Jésù ni o kò ni dáníkàn rìn. Láé. Awon ìmọ̀lára wa nìkan ni àwọn ìró tí Èṣù n pá ń bá wi kìí se òdòdó ti èmí. Òdòdó Bíbélì ni pé à yí o ká pẹ̀lú ìfẹ́ Ọlọ́run àti ìtọ́jú ni gbogbo ọjọ́ ayé e. Kò sí nǹkan kan ti o lè yo e kúrò ninú ìfẹ́ Ọlọ́run;a ti yí o ká pẹ̀lú ààbò nínú ìtọ́jú ìfẹ́ Ọlọ́run nítorí Ó ti ṣèlérí e - ìró tó kún fún ìrira to burú máa pè òtítọ́ òrò Ọlórun ti kò láṣìṣe.”
níjá.”
Jésù jé ́òré e tímòtimò, torí náà bẹ̀rẹ̀ si ni gbé ìgbé ayé yen lónìí. Sò ọkàn e fún Jésù kí o sì fetí si bi o má se dáhùn si o. Fi gbogbo ìrólè e níwájú Rè pẹ̀lú orin ìjọsìn àti òrò Olórun. Kò létá ìfẹ́ to gùn ki o si kọrin ọkàn e tímótimó Si i nígbà ti o wà níwájú Rè. Nígbà ti o ba bẹ̀rẹ̀ si Jesus gẹ́gẹ́ bi o ma6se dáhùn si òré e, idáníkànwà e ma sálo, mo dá lójú e!

Ìwé mímọ́
Nípa Ìpèsè yìí
Ọlọ́run dá ọ Ó sì fi ọ sí àyè tí o wà ní irú àkókò yìí, to love the unlovable, bii àlàáfíà nínú rúkè rúdò, kí o sì fi ayọ̀ tí kò ṣeé dẹ́kun nínú ìṣẹ̀lẹ̀ gbogbo. À ti ṣe bẹ́ẹ̀ lè jọ pé kò ṣeéṣẹ, ṣùgbọ́n o le è ṣeé tí o bá kọ́ oun tí Bíbélì sọ nípa àwọn ìmọ̀lára ọkàn rẹ gẹ́gẹ́ bí ènìyàn àti bí o tilè ṣàkóso wọn. Ètò ẹ̀kọ́ yìí dá lórí àwọn ohun tí a kò kà sí àti nígbà míràn awon ohun ìdojúkọ tí kìí ṣe lásán tí à ń bá pàdé lojojúmọ́, ó sì fún wa ní ìtọ́kasí ẹsẹ̀ Bíbélì láti ṣàkóso ìmọ̀lára wa ní ọ̀nà bíi ti Ọlọ́run.
More
A fẹ́ dúpẹ́ lọ́wọ́ Carol McLeod and Just Joy Ministries fún ìpèsè ètò yìí. Fún àlàyé díẹ̀ síi, jọwọ lọsí: www.justjoyministries.com