Ìmọ̀lára Mímọ́ - Èsì Látinú Bíbélì sí Ìpèníjà GbogboÀpẹrẹ

Holy Emotions - Biblical Responses to Every Challenge

Ọjọ́ 15 nínú 30

Ọlọ́run ní ohun tí ó lè pá oró ọkàn tí ó rẹ̀wẹ̀sì. Ó tí fí ye wá pé "gbígbé nínú Òun" ní ó lè ṣe àwòtán ọkàn tí ó bá rẹ. Èyí tí ó ṣe ìdàkéjì ìrẹ̀wẹ̀sì nínú ẹ̀mí ní ìsọdẹ̀rọ̀ gbígbé nínú Kristi.

Á ní láti dúró nínú ìṣọ̀kan nígbà gbogbo àti ìdàpọ̀ tí kò lè já pẹ̀lú Jésù Kristi. Irú ìgbésẹ̀ báyì kì í ṣe èyí tí a lè ṣe ìbẹ̀wò sí lẹ́rìkan l'ọ́sẹ̀, ṣùgbọ́n a pé wá láti jẹ kí ìgbé ayé wa gbilẹ̀ yí àyíká Rẹ. Bí a ṣe nwọ̀ ìgbé ayé ọ̀tun yí túmọ̀ sí pé a ní láti wá ní iwájú Rẹ̀, kí á sì fí ibẹ̀ ṣe ibùgbé òótọ́. Bí a ṣe wà ní iwájú Rẹ̀ kò túmọ̀ sí pé à tì de ibi ìsimi kúrò lọ́wọ́ ìjì aiye tàbí ìsimi kúrò lẹ́nu isẹ, ṣùgbọ́n ó jẹ́ ibi tí a lè gbé ayé wa kà tí a kò gbọ́dọ̀ wẹ̀hìn rárá àti rárá. Nígbà tí ibùgbé wá títí láì wá ní iwájú Kristi tí a sì gbà láyè láti bá wà sọ̀rọ̀ ní kẹ́lẹ́kẹ́lẹ́ ọkàn wa ohun tí a ní láti ṣe ní ọjọ́ kọ̀ọ̀kan, wákàtí kọ̀ọ̀kan, àti àkókò kan pàtó ní ọjọ́ ayé wa, ní ìgbà yẹn ní èso ológo Rẹ̀ yio fí ẹ́wà rẹ hàn nínú ayé wa tí a tí bù omi rín dáradára.

Ọrọ náà "gbígbé nínú" ní èdè Gíríìkì ní a túmọ̀ sí bí "kí ó pẹ́ títí" tàbí "kí a fí ara dá". Nígbà tí a bá ngbe nínú Kristi lójojúmọ́ tí a sì nfi onjẹ ọrọ Rẹ̀ bọ̀ wà tí a sì ní ìtura pẹlu ìjọsìn tí ó l'árinrin, Èṣù àti àwọn ọgbọ́n àrékérekè kò ní lè borí wà. Ìwọ kì yíò jẹ arábìnrin tí a tí pọn l'ójú tí a sì dá l'ágara, ṣùgbọ́n ìwọ yíò dá bí àwòrán ìlera àti ìfẹ́ tí a gbìn bí ó ṣe ń gbé nínú Kristi.

Ìwé mímọ́

Ọjọ́ 14Ọjọ́ 16

Nípa Ìpèsè yìí

Holy Emotions - Biblical Responses to Every Challenge

Ọlọ́run dá ọ Ó sì fi ọ sí àyè tí o wà ní irú àkókò yìí, to love the unlovable, bii àlàáfíà nínú rúkè rúdò, kí o sì fi ayọ̀ tí kò ṣeé dẹ́kun nínú ìṣẹ̀lẹ̀ gbogbo. À ti ṣe bẹ́ẹ̀ lè jọ pé kò ṣeéṣẹ, ṣùgbọ́n o le è ṣeé tí o bá kọ́ oun tí Bíbélì sọ nípa àwọn ìmọ̀lára ọkàn rẹ gẹ́gẹ́ bí ènìyàn àti bí o tilè ṣàkóso wọn. Ètò ẹ̀kọ́ yìí dá lórí àwọn ohun tí a kò kà sí àti nígbà míràn awon ohun ìdojúkọ tí kìí ṣe lásán tí à ń bá pàdé lojojúmọ́, ó sì fún wa ní ìtọ́kasí ẹsẹ̀ Bíbélì láti ṣàkóso ìmọ̀lára wa ní ọ̀nà bíi ti Ọlọ́run.

More

A fẹ́ dúpẹ́ lọ́wọ́ Carol McLeod and Just Joy Ministries fún ìpèsè ètò yìí. Fún àlàyé díẹ̀ síi, jọwọ lọsí: www.justjoyministries.com