Ìmọ̀lára Mímọ́ - Èsì Látinú Bíbélì sí Ìpèníjà GbogboÀpẹrẹ
Ìwé ìtumò Bíbélì kan ṣe àsọyé Agara sì "ìrẹ̀wẹ̀sì", "lílò tán", "kí eniyan tí fẹ̀rẹ̀ dákú"; "kí nkan máa jẹ díẹ̀ díẹ̀" tàbí "kí nkan ti gbó"; rírẹ̀; àìsàn; tired, sick, ṣíṣú àti títàn ni sùúrù."
Ó ṣeé ṣe wípé ìwé ìtumọ̀ Bíbélì yìí ń ṣe àpèjúwe rẹ! Àmọ́ ṣá "ìwọ" tí ọ̀tá ń fẹ́ kí ó jẹ́ ní yí o. Sátánì ń gbìmọ̀, ó ń tàn ọ́ jẹ́, ó sì ń wá gbogbo ọ̀nà arekereke tí yóò fi mú kí ó su ọ ní ọ̀nàkọ́nà tí ó bá lè ṣe bẹ́ẹ̀. Ọ̀nà tí ó lọ sí ìrẹ̀wẹ̀sì kúrú óò sì dé ibi tí agara a ti dá ọ kíákíá.
Èṣù, tí ó jé ọ̀tá rẹ, ń fẹ́ kí ó rẹ̀ ọ́ kí o sì máa sá kìràkìtà ni gbogbo ọjọ́ ayé rẹ. Bi o ti ń jẹ ki ayé re kún fún ohun ìní, àti ìgbòkègbodò ó ń rẹrìn arin tàkìtì nípa rẹ nínú ìmọ̀ pé ohun tí borí ogun yìí.
Sátánì ń fẹ́ kí ó rẹ àwọn ẹni mímọ oga ògo pelu ìgbòkègbodò àti ìpayà ṣíṣe nkan ni kíákíá. Sátánì mọ wípé ìwọ yóò pàdánù gbogbo ogun tí ó bá dojú kọ ọ bí ohun bá lè mú kí ó rẹ ọ. Kini ìwọ yóò pàdánù? Kii ṣe ìgbàlà ayérayé rẹ o, rara, sugbon ìwọ yóò pàdánù ìfọ̀kànbalẹ̀ àti suru rẹ. O ó sọ iran ọjọ́ iwájú rẹ àti àlàáfíà ọkàn rẹ nu. O ṣeé ṣe kí ó sọ ẹbun ati ṣe dá nkan àti iṣẹ́ ojoojumo rẹ nu.
Eto ti Èṣù ni ni wípé kí ó mú kí ìgbòkègbodò wá pọ̀ tó bẹ́ẹ̀ gẹ̀ẹ́ tí ojú wa a fi kúrò lórí ohun tí ó ṣe pàtàkì láyé tí a ó sì máa gbé ìgbésí ayé tí kò wu ni dípò ìgbésí ayé ìyè àìnípẹ̀kun. Èṣù kò ní tán ọ je pelu ohun búburú sugbon pelu ohun tó o dabi ẹni wípé ó dara. Sátánì a lo nkan míràn tí ó dàbi ẹni wípé ó dà ní iseju a yà láti pé ọ kúrò nínú ètò tí ó dára julọ tí Olorun ni fún ayé rẹ. Kí ni ohun tí ó dára tí ó njẹ ki o fẹ pínyà pelu ohun tí ó jara julọ tí Ọlọ́run fẹ́ fún ọ loni? Good things may wear you down Ohun tí ó dára lè mú ọ rẹ̀wẹ̀sì, ṣùgbọ́n ohun tí ó dára julọ tí Ọlọ́run fẹ́ ṣe fún ọ a máa fún ọ ní okun a sì máa mú àlàáfíà wà sínú ayé re.
Ní ọ̀pọ̀ ìgbà ti o ba dabi ẹni wípé àárẹ̀ fẹ mú ọkàn mi, mo máa ń kéde fún èṣù àti àwọn ìsọ̀ngbè rẹ wipe, " O kò lè jẹ ki àárẹ̀ bo ọkàn mi- Ń ó borí rẹ pẹlu orin ìyìn àti ọ̀rọ̀ Ọlọ́run!" Lẹhin ti o ba ṣe ìkéde yìí tan, bẹ̀rẹ̀ si ni wó àwọn àṣàyàn tí ó lè mú lo láti ké òbìrìkìtì àárẹ̀ kúrò nínú ayé rẹ. Pinu lónìí wípé ó kó ni fi ara rẹ jìn fún ohun tí kò ní tọ́, sugbon pé óò fi ara rẹ jin fún àwọn ohun tí yóò wá títí ayé àìnípẹ̀kun, àti fún àwọn ohun tí ó ṣe pàtàkì julọ. Gba mi gbọ́ nigbati mo bá sọ fún ọ wípé àwọn àṣàyàn ìyípadà kọ̀ọ̀kan tí ó xxxc ni ó máa nílò láti ṣe kí ó lè fi àlàáfíà Ọlọ́run pípé rọ́pò àárẹ̀ ọkàn rẹ.

Ìwé mímọ́
Nípa Ìpèsè yìí
Ọlọ́run dá ọ Ó sì fi ọ sí àyè tí o wà ní irú àkókò yìí, to love the unlovable, bii àlàáfíà nínú rúkè rúdò, kí o sì fi ayọ̀ tí kò ṣeé dẹ́kun nínú ìṣẹ̀lẹ̀ gbogbo. À ti ṣe bẹ́ẹ̀ lè jọ pé kò ṣeéṣẹ, ṣùgbọ́n o le è ṣeé tí o bá kọ́ oun tí Bíbélì sọ nípa àwọn ìmọ̀lára ọkàn rẹ gẹ́gẹ́ bí ènìyàn àti bí o tilè ṣàkóso wọn. Ètò ẹ̀kọ́ yìí dá lórí àwọn ohun tí a kò kà sí àti nígbà míràn awon ohun ìdojúkọ tí kìí ṣe lásán tí à ń bá pàdé lojojúmọ́, ó sì fún wa ní ìtọ́kasí ẹsẹ̀ Bíbélì láti ṣàkóso ìmọ̀lára wa ní ọ̀nà bíi ti Ọlọ́run.
More
A fẹ́ dúpẹ́ lọ́wọ́ Carol McLeod and Just Joy Ministries fún ìpèsè ètò yìí. Fún àlàyé díẹ̀ síi, jọwọ lọsí: www.justjoyministries.com