Ìmọ̀lára Mímọ́ - Èsì Látinú Bíbélì sí Ìpèníjà GbogboÀpẹrẹ
Ni ìgbà tí bàbá mi àti ìyá mì ṣe ìgbéyàwó, àwọn òbí bàbá mi fún wọn ní àpótí kan tí a nko ohun ìṣ'aralọ́ṣọ̀ọ́ Àpótí yìí tí wà nínu ilé adìye wọn fún ogúnlọ́gọ̀ odun, ṣùgbọ́n ìyá bàbá mi ni ìgbàgbọ́ wípé wọn lé mú lo nínú ilé won. Ekuru bútubùtu ogúnlọ́gọ̀ ọdún, ìgbẹ́ àti ìyẹ́ ìrandíran adìye tí bo ó. Ìyá ńlá mi gbìyànjú láti wẹ̀ ẹ́ mọ́ ṣùgbọ́n kò ṣeé ṣe fún wọn, nítorí naa won dá oda aláwọ̀ ewéko tí ó nri ni lára bó ekuru tí ó ṣekú mọ́lẹ̀.
Àpótí aláwọ̀ ewé yí jẹ́ ohun ìríra tí ó jókòó ní yàrá ńlá tí ó ń bẹ lókè ni ilé olókè tí gbé ní ìgbà kékeré mi.
Màmá mi pinu wípé àwọn a pààrọ̀ ọ̀dà ara àpótí yìí. Wọ̀n gbé àpótí náà lọ sí ọ̀dọ̀ ọ̀rẹ́ wá kan ti ọ n ṣíṣe gbẹ́nàgbẹ́nà.
Màmá mi gbé lọ síbè ni àárọ̀ ọjọ́ kan, ní kánmọ́kanmo ni Ọ́gbẹ́ni C pè wípé kí wọn wá gbé e. O yà màmá mi lẹ́nu pé a lè parí iṣẹ́ ara àpótí yìí ni kíákíá wọn sì béèrè pé kini wọn ṣe páárì rẹ ni àárín wákàtí mẹ́rìnlélógún.
Ogbeni C ṣàlàyé, wọn wípé bí wọn tí ń ṣe ìwádìí lórí irú àpótí ìṣ'aralọ́ṣọ̀ọ́, won ṣe àkíyèsí wípé a kàn án ní àsìkò ogún iṣọ̀tẹ̀ o sì jẹ́ ohun àjogúnbá aláìníye lórí. Ọ́gbẹ́ni C tẹ síwájú wípé àpótí náà fi ara jọ irú àpótí tó wọn ṣe fún Ogbeni George Washington fún ra rẹ! O kọ̀ láti fọwọ́ kan àpótí náà o sì sọ fún màmá mi pé ní ìdíyelé, àpótí náà a tó ẹgbẹ̀rún mẹ́wàá dọ́là ni ìlọ́po.
Mama mi tẹnu mọ wípé Ogbeni C ni àwon fe ki o ṣe ìmúpadàbọ̀sípò àpótí náà. O gba Ọ̀gbẹ́ni C ni osu mélòó kan láti mú àpótí yìí padà sí bí ó ti rí ní ìgbà tí a kọ́kọ́ ṣe é. Nígbà tí Ogbeni C yọ ìdọ̀tí ara àpótí náà kúrò tán, ó ṣe ípalẹmọ́ rẹ̀ láti parí iṣẹ́ lórí rẹ̀ kí wọn lé kùn ún ní òróró.
Ìwọ ni àpótí ìṣ'aralọ́ṣọ̀ọ́ yìí - you were made to be valued and cared for a dá ọ pé kí ó jẹ ohun ti o ṣe iyebíye tí a sì ń tọ́jú. Ṣùgbọ́n dípò èyí, O yàn láti máa gbé nínú àgó adìye ayé tí ó sì ti pá ọ lára dá pelu ekuru bútubùtu ogúnlọ́gọ̀ ọdún, ìgbẹ́ àti ìyẹ́ ìrandíran adìye. Lẹhin èyí, àwọn olùkọ́ àṣà "ríran-ara-ẹni-lọ́wọ́" onínú're kan, tí kún ọ ní ọ̀dà irira. O wú Ọlọ́run láti yọ gbogbo èérí yí kúrò kí ó sì fi ìfẹ́ dá ọ padà sí ẹwà àdáyébá tí ìṣẹ̀dá rẹ. Ǹjẹ́ ìwọ yóò gbà á láyè láti ṣe bẹ? A dá ọ ní àwòrán ara rẹ̀ kí ó lè jẹ ara ètò rẹ̀ ni ṣáá tí a wà yìí.

Ìwé mímọ́
Nípa Ìpèsè yìí
Ọlọ́run dá ọ Ó sì fi ọ sí àyè tí o wà ní irú àkókò yìí, to love the unlovable, bii àlàáfíà nínú rúkè rúdò, kí o sì fi ayọ̀ tí kò ṣeé dẹ́kun nínú ìṣẹ̀lẹ̀ gbogbo. À ti ṣe bẹ́ẹ̀ lè jọ pé kò ṣeéṣẹ, ṣùgbọ́n o le è ṣeé tí o bá kọ́ oun tí Bíbélì sọ nípa àwọn ìmọ̀lára ọkàn rẹ gẹ́gẹ́ bí ènìyàn àti bí o tilè ṣàkóso wọn. Ètò ẹ̀kọ́ yìí dá lórí àwọn ohun tí a kò kà sí àti nígbà míràn awon ohun ìdojúkọ tí kìí ṣe lásán tí à ń bá pàdé lojojúmọ́, ó sì fún wa ní ìtọ́kasí ẹsẹ̀ Bíbélì láti ṣàkóso ìmọ̀lára wa ní ọ̀nà bíi ti Ọlọ́run.
More
A fẹ́ dúpẹ́ lọ́wọ́ Carol McLeod and Just Joy Ministries fún ìpèsè ètò yìí. Fún àlàyé díẹ̀ síi, jọwọ lọsí: www.justjoyministries.com