Ìmọ̀lára Mímọ́ - Èsì Látinú Bíbélì sí Ìpèníjà GbogboÀpẹrẹ
Ọkàn nínú àwọn ohun èlò tó ṣe kókó láti fi kọ́ èmi tó jinlẹ̀ ni fí fi ọkàn sìn nínú ìjọ àti àjùmọ̀ṣe pẹ̀lú àwọn ẹlẹgbẹ́ onígbàgbọ́. Má ṣe kó àṣà àṣà burúkú à ń sá ní ilé ìjọsìn! Nótòótó, Ẹ̀mí Ọlọ́run wà ní ibikíbi tí ara Rẹ̀ bá wà, Yíò sì mú ẹ̀mí rẹ ní agbára síi bí o bá ṣe ń ṣe àwárí ayọ̀ tí ó wà nínú àjọ sìn. Ọlọ́run fẹ́ràn àwọn àpéjọ onígbàgbọ́ wọ́n sì jẹ́ ayọ̀ fún ọkàn Bàbá wa nígbàtí a bá pé jọ ní ilé fún àyájọ́ ọjọ́ ìjọ́sìn, kíkọ́ ọ̀rọ̀ Ọlọ́run ati àjọṣepọ̀. Kìí ṣe pé Ó fẹ́ ẹ nìkan - ṣùgbọ́n inú Rẹ̀ nígbàtí ó bá dùn mọ́ àwa náà!
Ìgbìmọ̀ ìgbé ayé ìjọ àti pípé jọ ní orúkọ Olúwa jẹ́ èròńgbà Rẹ̀ láti ọjọ́ tí Jésù ti padà dé ọ̀run. Ẹ̀mí Mímọ́ mọ̀ pé a ò ní le yè ní onígbàgbọ́ tó ń dá wà, ṣùgbọ́n a nílò àwọn ohun àmú-ṣagbára fún ìṣẹ́gun tí à ń rí gbà nígbàtí a bá ṣù papọ̀ nínú ìgbàgbó.
Má ṣe kó kéré iiṣẹ́ ìyanu tó ṣẹlẹ̀ ní inú rẹ nígbàtí o yàn láti darapọ̀ mọ́ àwọn onígbàgbọ́ míràn ní orúkọ Rẹ̀. Nígbàtí a bá wàásù ọ̀rọ̀ Ọlọ́run ... ìdàgbàsókè ń ṣẹlẹ̀. Nígbàtí a bá wọnú ìjọsìn àpapọ̀ ... àwọn èso ti ẹ̀mí nínú ayé ènìyàn a gba ajílẹ̀. Nígbàtí ò ún yọ ìdá mẹ́wàá àti ọrẹ ... agbára rẹ láti fi ipa tó làmììlaaka sílẹ̀ ń pọ̀ si. Nígbàtí o bá darapọ̀ nínú ìbáṣepọ̀ mímọ́ pẹ̀lú àwọn ọkùnrin àti obìnrin tí wọ́n ti yàn láti sin Ọlọ́run tọkàntọkàn proactively ... ìkorò ọkàn àti ìbínú wọn á palẹ̀ ẹrù wọn mọ́ ní b'ẹ̀rù b'ojo.
Kò sí ilé ìjọsìn kan tí ó pé nítorí kò sí ẹnikẹ́ni tí ó pé. Tí o bá rí ẹni tí ó ṣe ọ́ ní ibi nínú ijo, pinu láti rìn ní ọ̀nà ìdáríjì kí o sì súre fún ẹni tó ṣẹ̀ ọ́. Ọlọ́run Yóò bá ọ pàdé ní ilé ìjọsìn ní ọ̀nà tí ó nítumọ̀ ju ibòmíràn lọ. Lí lọ sí ilé ìjọsìn kìí ṣe òfin ṣùgbọ́n ó jẹ́ ìpinnu tí ó nítumọ̀ tí yíò sì ṣe ọ́ ní àǹfààní fún òní àti ọjọ́ ọ̀la rẹ! Mọ lè fi dá ọ lójú!

Ìwé mímọ́
Nípa Ìpèsè yìí
Ọlọ́run dá ọ Ó sì fi ọ sí àyè tí o wà ní irú àkókò yìí, to love the unlovable, bii àlàáfíà nínú rúkè rúdò, kí o sì fi ayọ̀ tí kò ṣeé dẹ́kun nínú ìṣẹ̀lẹ̀ gbogbo. À ti ṣe bẹ́ẹ̀ lè jọ pé kò ṣeéṣẹ, ṣùgbọ́n o le è ṣeé tí o bá kọ́ oun tí Bíbélì sọ nípa àwọn ìmọ̀lára ọkàn rẹ gẹ́gẹ́ bí ènìyàn àti bí o tilè ṣàkóso wọn. Ètò ẹ̀kọ́ yìí dá lórí àwọn ohun tí a kò kà sí àti nígbà míràn awon ohun ìdojúkọ tí kìí ṣe lásán tí à ń bá pàdé lojojúmọ́, ó sì fún wa ní ìtọ́kasí ẹsẹ̀ Bíbélì láti ṣàkóso ìmọ̀lára wa ní ọ̀nà bíi ti Ọlọ́run.
More
A fẹ́ dúpẹ́ lọ́wọ́ Carol McLeod and Just Joy Ministries fún ìpèsè ètò yìí. Fún àlàyé díẹ̀ síi, jọwọ lọsí: www.justjoyministries.com