Wá Àyè Fún Ohun tó Ṣe Kókó: Ìhùwàsí Ẹ̀mí Márùn-ún Fún Àkókò Lẹ́ńtìÀpẹrẹ

Make Space for What Matters: 5 Spiritual Habits for Lent

Ọjọ́ 7 nínú 7

Ìkìlò Nípa Ìsesí Èmí

Kí Jesu to bèrè isé ìránse Re, fúnra ara Rè ní ó dá lo sí aginjù fún ogoji ojó. Àsìkó yí ní ó fí gbaradì láti múra ìdojúko àwon ìdánwo tí èsù fí kóó l'ójú tí ó sí bósí inú ìpè tí Olórun ní fún. Àgbékalè ìsesí èmí tí ó pé báyi ní ó le rànwá lówó láti sé bí on sé sé gégé bé é

Bi á bá sé ñsúnmó Olórun ní ojojúmó sí í nípa ìséra eni, ohun tí á ñse ní àkókò yí ní yíò mówa l'ára nípa akitiyan wa ní ojojúmó àti l'ósòsè pèlú

Bí nwon bá sì tí ñmó wà l'ára, á ó rí wípé ìgbé aiyé wa ñyàtò nítorípé á ñse wón. À ñgbá Olórun l'áyè láti sé àyípadà okàn wa, nípa báyi ògo Rè á sí farahàn nínú aiyé wa sí ìgbé aiyé tí ó ní ìrètí nínú Olùgbàlà

Sùgbón nígbàtí á bá ñse àwon ñkan wònyí, e jékí á fí s'ókàn pé ìsesí èmí fúnra wón kò tàn síbè rárá. Ibití á ñlo gangan ní láti ní ìbásepò tí ó móyánlórí pèlú Olórun. Òrò Olórun fí dáwalójú pé ìgbóran sàn ju ebo lo. Eléyi túmò sí wípé when kì á fí ohunkúhun rúbo àti láti fí ojú gbogbo l'élè pèlú ìrèlè- kíìsí sé èyítí a ñfí íyèméjì sé àgbékálè rè. Bákan na ìsesí èmí á maa sé àfikún nígbàtí ìgbóran tí o jinlè nínú ìfé Olórun bá jeyo.

Nítorínã bí á tí sé ñgbaradì fún ojó ìsimi àjínde, é jékí á ránrawa létí pé Olórun kò fé kì á dàgbà nínú èmí fúnra wà. E jékí á gbìyànjú láti wá s'íwájú Rè ní àìpé, nítorípé agbára Olórun ní ó ñso wá dí pipe nínú àìlera wà gbogbo

Ọjọ́ 6

Nípa Ìpèsè yìí

Make Space for What Matters: 5 Spiritual Habits for Lent

Lẹ́ńtì: àkókò ìyẹaraẹniwò àti ìrònúpìwàdà fún ogójì ọjọ́ gbáko. Èròngbà tó dára ni, àmọ́ báwo ní àkókò Lẹ́ńtì ṣe ma ń rí lára? Ní ọjọ́ méje tó ḿbọ̀, ṣe àwárí àwọn ìhùwàsí márùn-ún ti ẹ̀mí tí o lè bẹ̀rẹ̀ ní àkókò àwẹ̀ yí láti ràn ẹ́ lọ́wọ́ fún ìpèsè sílẹ̀ ọkàn rẹ fún ọjọ́ Àìkú ti Àjíǹde—àti lẹ́yìn rẹ̀.

More

YouVersion ló ṣe ìṣẹ̀dá àti ìpèsè ojúlówó ètò Bíbélì yí.