Wá Àyè Fún Ohun tó Ṣe Kókó: Ìhùwàsí Ẹ̀mí Márùn-ún Fún Àkókò Lẹ́ńtìÀpẹrẹ
Àwọn Ìwà Témi: Ìwà Òlàwó
Kíni ohun ìní é tó séyèbíyè jù lo? O lè jẹ ohun tó ni ìyè lórí jù tí o ni, bí ilè tí o tí ṣiṣe fún ní ojó ayé è láti ra. O tun lè jé àwòrán fọto ní àkókò àkànṣe pèlú enìkan tí o féràn. O lè jé èbùn tó ni ìtúmọ látodó òré kan.
Ìníyelórí tí a gbé lè “àwon ohun ìní” wa ní láti se pèlú àwọn èrò ìmólárá wa. Bí a ṣe yàn lati lo àwọn ohun tí a morìrì jù fi àwọn ohun tó jé wa lógún hàn.
ikú Jésù lórí ìgi àgbélèbú jé oòkan lára àpẹẹrẹ ìwà òlàwó Ọlọrun tó tóbi jù lọ. Bó tilẹ̀ jẹ O mò pé a kò lè san pàdà fún Òun láì, Ọlọrun kò dáwọ dúró láti jòwó ìṣúra tó séyèbíyè jù lo— Ọmọ Rè kan ṣoṣo—fún wa. Àtìpé nípasẹ ìṣe ìrúbo, O ṣàfihàn bí ìwà ọ̀láwo se rí: tinútinú yọ̀ǹda ohun tí a ní kí ẹlòmíràn lè tẹ síwájú, kódà o máa fa ìrora nínú gbogbo e.
O kò ní láti máa fúnni lówó nìkan láti máa se ìwà òlàwó. Gbígbé ìgbé ayé òlàwó túmọ sí gbígbà pé Ọlọ́run lè ṣe ohunkóhun Tó fé se nipasẹ awọn èbun Tó ti fún wa. Nígbà tí o bá gbà Ọlọrun láàyè láti fúnni nípasẹ e, tí o sí bólà fún Ùn pẹlú òlàwó é, o máa fà é súnmọ Olórun. Ìwà òlàwó flows ọkàn tó gbékèlé ati se ìdúpé sí Ọlọrun, àti pé nígbà tí o bá gbẹkẹlé Ọlórun pẹ̀lú ohun tí o ní, O máa bèrè sini fún ọ sí.
Ṣiṣé ìwà yìí máa ràn é léti pé kìí ṣe iwọ lọ ń darí, àmó o mo Eni tó ń darí —àti pé O lè pèsè gbogbo áìní rẹ.
Gbé Ìgbésẹ: Oòkan lára iṣé ìyánú Jésù tó lokiki jù lọ Wé wẹ mó lilọ ànfààní jù lọ nínú ìṣù àkàrà díẹ̀ àti ẹja àti ti ẹnìkan ní. Kílọ ní láti fúnni? Wa ibi kan tí o lè okòwò ohun tí o ní ni àwọn ònà kan. Bèrè pèlú kékeré, tàbí go big. Sa bèrè.
Ìwé mímọ́
Nípa Ìpèsè yìí
Lẹ́ńtì: àkókò ìyẹaraẹniwò àti ìrònúpìwàdà fún ogójì ọjọ́ gbáko. Èròngbà tó dára ni, àmọ́ báwo ní àkókò Lẹ́ńtì ṣe ma ń rí lára? Ní ọjọ́ méje tó ḿbọ̀, ṣe àwárí àwọn ìhùwàsí márùn-ún ti ẹ̀mí tí o lè bẹ̀rẹ̀ ní àkókò àwẹ̀ yí láti ràn ẹ́ lọ́wọ́ fún ìpèsè sílẹ̀ ọkàn rẹ fún ọjọ́ Àìkú ti Àjíǹde—àti lẹ́yìn rẹ̀.
More