Bẹ̀rẹ̀ L'ọ́tunÀpẹrẹ
Aláàánú ará Samáríà
Jẹ́ kí n gbìyànjú àti ṣe àtúnsọ ìtàn kan ni ọ̀nà tí yóò túbọ̀ tán ìmọ́lẹ̀ síi:
Ará Filipínò tí ó ń rìn ìrìn aájò láti ìlú Mánílà lọ sí ìlú Ánjẹ́lìs. Wọ́n tí jàá lólè, lùú, wọ́n si tí gba aṣọ lọ́rùn rẹ̀. Àlùfáà àti Olùsọ́àgùntán kọjá lọ. Kò sí èyí tí ó dúró nínu àwọn méjèèjì láti ràn ará Filipínò yìí lọ́wọ́. Ìbí ni mo tí mọ̀ wípé ẹ̀sìn kò ní gbà ọ!
Nígbà náà ni arákùnrin ìlú Amerika kan ti o jẹ ọmọ ọgọ́ta ọdún tí ó ní àrùn HIV pelu egbò lẹ́nu kọjá. Ó bojú àánú wo ará Filipínò tí ó wà nínú ọ̀gbun yìí, ó sì ràn á lọ́wọ́. - Ọkùnrin wo nínú wọn lo lè bá tan nínú wón?– arákùnrin ìlú Amẹ́ríkà tí ó ní àárun kogboogun tí a mọ sì Éèdì tàbí arákùnrin Filipínò tí ó wà nínú ọ̀gbun?
Àwọn ará Júù a máa fí ojú tẹ́mbẹ́lú àwọn ará Samáríà – àwọn aláìmọ́, ènìyàn lásán làsàn, ìkejì ajá aláìsàn. Ní ti àṣà, ará Samáríà jẹ́ ẹnì tí a kò leè lérò wípé yóò rán ara Júù lọ́wọ́.
Nítòótọ́, bí ọkùnrin inú ọ̀gbún ni bá ní ìmí kánkán nínú, ó ṣeé ṣe kí ó sọ fún ará Samáríà pé, “Rárá! Má fi ọwọ́ kan mi! Mo lè tọ́jú ará mi…” Ohun tí kò ní fẹ́ rárá ní wípé kí arákùnrin Samáríà fọwọ́ kan a.
Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìgbà ni ànfàní fún iranlọwọ a ṣí silẹ, sùgbọ́n gẹ́gẹ́ bí Júù onìgbéraga, wọn a kọ iranlọwọ ara Samáríà tí ó lè gbà wọ́n.
Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìgbà ni Ọlọ́run a máà ṣíṣe ni ọ̀nà áìrotẹ́lẹ̀ nípasẹ̀ àwọn ènìyàn tí a kò lérò rẹ sii.
Kò pẹ́ púpọ̀ tí a fi rí òye wípé ohun tí ó kú agbejọ́rò náà kú ní ìmọ̀lára pe: Èmi ni Júù aláìnírètí tí ó wà nínú ọ̀gbun!
I am the hopeless Jew in the ditch! Gbogbo ìlà kàkà mi láti ṣé rere kí n lè ní ìyè àìnípẹ̀kun dabi àkísà ẹlẹ́gbin! Ń kó lè dáa tó! Kò sí ìrètí fún mi! Èmi ti a ti lù dojú ikú, ti a ti já l'olè, tí a sì ti gbà aṣọ lára rẹ̀.
Bí enikeni kò bá rìn s'ásìkò láti gba mi, Mo gbé tán!
Sátánì wá jalè, láti pá, àti láti parun, ṣùgbọ́n Jésù wà kí a lè ní ìyè kí a sì níi lọ́pọ̀lọpọ̀!
Ìrètí kan ṣoṣo fún agbẹjọ́rò yìí láti ní ìyè àìnípẹ̀kun – ìgbàgbọ́ nínu Jésù Kristi ti Násárétì yìí. Jésù yìí tí yóò kú lórí igi àgbélébùú. Ǹjẹ́ o tilè mọ wípé a kà ẹni ti o ku lórí àgbélébùú gẹ́gẹ́ bí ẹni tí a ti gégùn-ún fun? Nitorina, kini Olùgbàlà ṣe lè dìde láti inú àgbélébùú tí èègún wà lórí rẹ?
♥ Ó nílò Jésù, Olùgbàlà ara Samáríà tí yóò má gbé inú rẹ tí yóò sì má rán ọ lọ́wọ́ láti fẹ́ràn ọmọnìkejì rẹ gẹ́gẹ́ bí ara re.
Ìpèńijà:
(1) Képe Jésù lónìí fún ìgbàlà. Ó ń dúró de ọ́ láti jéwọ́ wípé ó wà ní ipò aláìnírànwọ́ àti aláìnírẹtí gẹ́gẹ́ bí ọkùnrin ínu ọ̀gbun ni. O to tọ ọ́ wá, ó sì ti náwó ìrànwọ́ sí ọ ṣùgbọ́n ó ń kọ ìrànlọ́wọ́ Rẹ̀. Òní ni ọjọ́ ìgbàlà rẹ! Képeẹ̀ẹ́! Jésù Ọmọ Dáfídì fi àánú gba mi! "Enikẹ́ni ti o ba pè orukọ Oluwa, a o gbà a là”. (Ìṣe àwọn Àpọ́sítélì 2:21)
(2) Képee Jésù lọnìí fún ìsinmi. "Ẹ wá sọ́dọ̀ mi gbogbo ẹ̀nyin ti nṣiṣẹ́, tí a sì di ẹrù wúwo le lori, emi o si fi isimi fun nyin...... Oóò rí ìsinmi fún ọkàn Rẹ́. (Matt. 11:28-30)
Jẹ́ kí ó dà ọtí wáìnì àti òróró ìwẹ̀nùmọ́ àti ìwòsàn sínú rẹ. Jẹ́kí ó mú ọ̀ wá síbi ìsinmi– kí ó mú ọ dùbúlẹ̀ ni pápá oko tútù.
(3) Jésù lọnìí kí ó sì yóò dá ara rẹ láti sìn í àti láti gbọ́ ìpè rẹ̀.
“Ní tòótọ́, Ìkórè pọ̀, ṣùgbọ́n àwọn alágbàṣe ko to nkan: nítorí náà ẹ bẹ̀ Olúwa ìkórè, ki o le rán awọn alágbàṣe sinu ikore rẹ̀.
(Lúùkù 10:2-3)

Nípa Ìpèsè yìí
Ọdún Tuntun. Ọjọ́ Tuntun. Ọlọ́run ṣ'ẹ̀dá gbogbo ìsípòpadà yìí láti rán wá l'étí pé Òun ni Ọlọ́run Ìbẹ̀rẹ̀ Ohun Tuntun. Bí ó bá jẹ́ pé Ọlọ́run fí ọ̀rọ̀ dá ayé, Ó lè s'ọ̀rọ̀ sí òkùnkùn ayé rẹ, kí Ó ṣ'ẹ̀dá ìbẹ̀rẹ̀ ọ̀tun fún ọ. Ṣé o kò sàì f'ẹ́ràn ìbẹ̀rẹ̀ ọ̀tun! Gẹ́gẹ́ bíi ìlànà ẹ̀kọ́ yìí! Máa bá wá kálọ!
More
A fẹ́ dúpẹ́ lọ́wọ́ Ògbéni Boris Joaquin, Ààrẹ àti Gíwá Àgbà fún Breakthrough Leadership Management Consultancy. Òun ni olùkọ́ àgbà àti olùdánilẹ́kọ̀ọ́ tó mú yányán jùlọ nínú ẹ̀kọ́ ìdarí àti àwọn ẹ̀kọ́ ìgbáyé-gbádùn ní ìlú Philippines. Òun pẹ̀lú ìyàwó rẹ̀ Michelle Joaquin, ni wọ́n jọ ṣ'ètò ìlànà ẹ̀kọ́ yìí. Fún àlàyé kíkún, jọ̀wọ́ kàn sí http://www.theprojectpurpose.com/