Bẹ̀rẹ̀ L'ọ́tunÀpẹrẹ
Olùgbàlà Ará Samáríà
Níyìn ní òkodoro òrò tó dájú: Otá tó burú jù lọ ti ẹni tó ń rì sínu omi ni ará é. Níwòn bi wọn bá ní òkun tó láti máa tà omi kiri nínú omi, má ṣe sún mọ wọ́n. Wón wà ní ipò ìpayà wón máa gbá é mú wón o si fá a e kìí èyín méjèèjì rì sínu omi. Kán ṣe sùúrù títí dìgbà tí okun rẹ̀ ti fẹ́rẹ̀ẹ́ tán pátápátá. Nígbà náà ni wón má fún é láàyè láti gbà wọ́n là. Bákan náà ni fún ẹnikẹ́ni tó bá nílò Olùgbàlà gidi gàn nínú ayé wón.
Kà Lúùkù
10:25-37
lẹ́ẹ̀kan sí i. Ìbéèrè ni: “Kíni mo ní láti ṣe kín jogún ìyè àìnípẹkun?” Se Jésù kan sò pé jé“ álàdúgbò réré” yóò sì ni ìgbàlà? Dà bí olórí Kátólìkì? Rárá o, a ko lè dáwà láre nípa pipa ofin mó (Kà Ìwé Róòmù 3:20). Kókó pàtàkì èkó Jesu ní láti tẹpẹlẹ mó àwọn olùgbó òrò Rè síhà ìparí òrò tí kò ṣeé yẹ sílè pé ìrètí kàn ṣoṣo tí wón ní fún ìgbàlà ní Olùgbàlà.
“E jẹ́ pípé, gẹ́gẹ́ bí Baba yín tí ń bẹ ní ọ̀run ṣe jẹ́ pípé.
(Mátilìú 5:48)
“Jésù wí fún un pé, “Èmi ni àjíǹde àti ìyè: ẹni tí ó bá gbà mí gbọ́, bí ó tilẹ̀ kú, yóò yè
(Jòhánù 11:25)
“Èmi ni ọ̀nà, òtítọ́ àti ìyè: kò sí ẹnikẹ́ni tí ó lè wá sọ́dọ̀ Bàbá, bí kò ṣe nípasẹ̀ mi..” (Jòhánù 14:6)
Ní Lúùkù 10: 27 sọ wípé féràn Olórun kí o sí féràn ènìyàn. Kíni fiféran áládúgbò dá bí? Fífi ẹlòmíì ṣáájú ará ẹni, ìwà ìrúbo tó yàtò sí àṣà àti ṣẹ́ Ọnà àti làákàyè.
““Lọ, kí o ṣe bẹ́ẹ̀ gẹ́gẹ́!”.” (Lúùkù 10:37) fẹ́rẹ̀ẹ́ túmọ sí máa ṣe èyí láìsí ìjà fara. Irú ìfé álàdúgbò Olórun bí wa – ti a bá dáwà láre nípa ofin. Tani eni tó fi àànú hàn? “Àwon elésìn” bíi Àlùfáà, ọmọ Léfì?
Ẹsìn é kò lè gbà o le! Ẹni tí a kò lè rò, ará Samáríà, ló wá jé Olùgbàlà.
Njé o tí nílò ìrànlọ́wọ́ nínú kòtò ri? Se o tí ké àwọn òrò tó jomo èyí si Olùgbàlà Samáríà nítorí o mò, Òun ní ìrètí é tó kéyìn?
“Jésù, Ọmọ Dáfídì, sàànú fún mi!” Afóju Bártìmíū
(Máàkù 10:47)
“Olórun, Iwọ ní Olórun mi; Máa wá Yín tókàn tókàn; ọkàn mi pòùngbẹ fún Yín, ará mi fá sí Yín ní ilè gbígbe níbi tí kò sí omi.”
(Orin Dáfídì 63:1-2)
Ṣe o mò ẹnikẹ́ni tí o ti kò láti gbà Jésù Kristi nítorí Kìí se ìdáhùn sí àwọn àìní tí ará àti àìní rámpẹ́? Mòlẹ́bí tàbí ọ̀ré tí o ń ti fí ìfé hàn sí fún ojó típé. Ọ ṣe lọ àkókó nísìsiyìí láti gbàdúrà fún un.
Bí ẹnìkan tó ń kọjá lọ ní àfonífojì tutù, to ṣókùnkùn pẹlu ìsáná lówó. Bí ọ tí é gbìyànjú, gbogbo nńkan tí tutù láti dáná sun. Àmó nígbà tí o bá gbàdúrà, aféfé Èmí máa bèrè sí fe yóò sí gbe àfonífojì to tutù. Lójijì ìyípadà máa ṣẹlẹ̀! Inà náà máa bèrè sí ní jo ni ọkàn ọkùnrin àti obìnrin tó wá làyíká – wón yóò sí tari é sí àwọn mìíràn – títí gbogbo àfonífojì náà má kún pèlú Olórun! Èyí ní kókó ádùrá.

Nípa Ìpèsè yìí
Ọdún Tuntun. Ọjọ́ Tuntun. Ọlọ́run ṣ'ẹ̀dá gbogbo ìsípòpadà yìí láti rán wá l'étí pé Òun ni Ọlọ́run Ìbẹ̀rẹ̀ Ohun Tuntun. Bí ó bá jẹ́ pé Ọlọ́run fí ọ̀rọ̀ dá ayé, Ó lè s'ọ̀rọ̀ sí òkùnkùn ayé rẹ, kí Ó ṣ'ẹ̀dá ìbẹ̀rẹ̀ ọ̀tun fún ọ. Ṣé o kò sàì f'ẹ́ràn ìbẹ̀rẹ̀ ọ̀tun! Gẹ́gẹ́ bíi ìlànà ẹ̀kọ́ yìí! Máa bá wá kálọ!
More
A fẹ́ dúpẹ́ lọ́wọ́ Ògbéni Boris Joaquin, Ààrẹ àti Gíwá Àgbà fún Breakthrough Leadership Management Consultancy. Òun ni olùkọ́ àgbà àti olùdánilẹ́kọ̀ọ́ tó mú yányán jùlọ nínú ẹ̀kọ́ ìdarí àti àwọn ẹ̀kọ́ ìgbáyé-gbádùn ní ìlú Philippines. Òun pẹ̀lú ìyàwó rẹ̀ Michelle Joaquin, ni wọ́n jọ ṣ'ètò ìlànà ẹ̀kọ́ yìí. Fún àlàyé kíkún, jọ̀wọ́ kàn sí http://www.theprojectpurpose.com/