Òpin Ìgbéra-à-miga Látọwọ́ Kyle IdlemanÀpẹrẹ

The End Of Me By Kyle Idleman

Ọjọ́ 3 nínú 7

S'ọ̀fọ̀ láti Dunnú

Wọn a máa sọ pé bi àlá ní ìgbésí aiyé wa sé rí, sùgbón tí ó bá jé béè òpòlópò nkan ní o lè tí íbè jáde. Ìdánílojú wà pé a tí mo die jú bí ó tí ye lo. Nkan tí a nwo nípe ìgbàmíràn wà tí a bá ngbé aiyé tí o ní idíwòn, a maa nrí ìdojúko òkèsóro Òpin a sí báwa lójijì nígbàtí àlá bá wá sí ìparí.

Bí ó sé nsisé nìyí. Àwon ònà ìyánú tí ìjìyà fí àyè gbàwá nínú èmí wà láti mó àti láti ní ìrírí ìbùkún Olórun nípa àlàfíà àti wíwá òjúrere rè. Láìsí ìjìyà ó sòrò fun wà láti mó ìtúrá rè. lnú òfò ní a tí lè ní ìrírí ìbùkún àti òjúrere Olórun.

Gégébí Eugene Peterson sé gbé kale nínú àkosílè rè láti inú ìwé Mímó (Message)Matteu5:4 bi o tí sé àgékúrú rè "O jé alábùkúnfún nígbàtí o bá pàdánù ohun tí o jé òwón fun o. Nígbàna ní ohun tí o jé òwón fun o yio to moo"

Ní ìparí ohun gbogbo o ní àyè láti ní ìrírí wíwá òjúrere Olórun ní ònà tí ìwo Koni télè. Bóyá o tí gbá àwon ohun ìyánú kan tí o sí pàdánù wón. Sùgbón kòsí ìgbàmóra tí o dabí tí òdò adániwáyé wá.

Nígbàkúgbà ní òpò ènìyàn maa ngbàdúrà fun ìyípadà tí a lé fí ojú rí tí o jé tí òde, nígbàtí Olórun bìkítà nípa tí ìyípadà tí inú tí a kò lè fí ojú rí. Òpò ènìyàn ní o ngbàdúrà fun ohun tí o jé ìfé okàn wón, àkíyèsí wón síwájú sií ní wípé ohun tí wón sé aláìní ní Olórun nfi fún won gégébí ìdáhùn àdúrà wón.

Òfò míràn wà tí o jé atúbòtán èsè nínú ara àti ìgbé aiyé wa. Irú òfò àkókó jé ókùnfà nípásè ìparun láti inú wá-èsè tí o nfà wàhálà sórí wá, lórí àwon tí a féràn, àti ìgbé aiyé wá. Nínú ìwé Mímó ní a tí rí àsopò lãrín òfò lórí èsè-onírûrú èsè-àti ìbùkún Olórun. Israeli s'òfò púpò gégébí orílè èdè, wón sí gbá ìbùkún Olórun gégébí orílè èdè

Nítorínà e jékí o ye wá. A ó subú sínú èsè gégébí énìkòkan. A sí tún lóra síbè láti dojúko òfò. Gbogbo wá ní o wà ní ipò yí. E jékí á mo dájú pé nínú ìsiyèmejì wa l'ati s'òfò èsè wá, bee lí a ñse ìdádúró ìbùkún Olórun. Kò sí ònà fún wá láti de ibi ìbùkún yí láìjépé àkókó jékí òfò kì o saaju rè

Bí o bá tile dojúko ní ìgbésí aiyé re lóní-olòní pèlú àsìkò ojúlówó òfò? Bi o bá sí lol àkókó díè láti sé àsàrò, gbàdúrà, àti ìbìnújé láti fí èsè sílè nínú aiyé re.

Saaju, kì o to ronú nípa gbogbo ìyen,ronú nípe eléyi: Yio yí o padà, yio sí sé ìsodòtun ìwòye ré lórí ará rè àti ìgbé aiyé rè ní ònà tí o jé ìyàlénu. Nípa bee, o tí nyán láti rí àwon nkan ní ojú ìwòye Kristi láti inú jáde, àtipé eléyi kò lè sé fun o láìjépé o ngbíyànjú dîedîe láti dàbí Kristi

O jìnà rere sí "Ojó òní yio dára fún o" gégébí ìwàásù tí a maa ñse nígbàkúgbà. Mo wòye pé kò fí bé tònà lo títí, sùgbón o dabí on tí o wá ní ìbámu pèlú òtító, àti Ipa ònà pajìn, tí o sí Kun fún ayò tí Olórun fí fún wá. Ìwo yio rín l'arin àfonífojì, sùgbón mó sé ìlérí fún o pé ìwo nìkan kí yio dá rín

Ìwé mímọ́

Ọjọ́ 2Ọjọ́ 4

Nípa Ìpèsè yìí

The End Of Me By Kyle Idleman

A fa ètò yí yọ látinú iṣẹ́ àkànṣe tó tẹ̀lé ìwé Kyle Idle "Not A Fan," a pè ọ́ láti wá pa ìgbéraga tì, nítorí lẹ́yìn èyí ni o lè tẹ̀lé ìlànà àtinúdá ti Jésù.

More

A fẹ́ dúpẹ́ lọ́wọ́ Kyle Idleman àti David C Cook fún ìpèsè ètò yìí. Fún àlàyé síwájú sí, Jọ̀wọ́ lọ sí: www.dccpromo.com/the_end_of_me/

Awọn Ètò tó Jẹmọ́ọ