Ẹ̀mí Mímọ́: Ǹjẹ́ A Gba Iná Jẹ Àbí A Se Ìdáàbòbò Kí á má baà Gba Iná Jẹ?Àpẹrẹ

Holy Spirit: Are We Flammable Or Fireproof?

Ọjọ́ 6 nínú 7

Ojúlówó Àmì ìfòróró Yàn Rẹ

A tí dá o lónà ọtò, Ọlórun tí fi àmì òróró yan é àti yàn fun ète Rè àti fún ìgbà àti àkókò tí rè. “Gégé bí ojó e, béè náà ni òkun rè” (Diutarónómì 33:25). Dipò kí o má ṣàníyàn ohun tí o kò ní, Kíyèsi lórí ohun tó ni, jáde pèlú ìgbàgbọ kí o sí wò Ọlọrun sísè nipasẹ rẹ. Ní ojó Pẹ́ńtíkọ́sì, 120 ko bèbè fún ìlòpo méjì àmì òróró. Jòwó kíyèsi: KÒ SÍ ẸNIKẸ́NI TÓ KÚRÒ NÍNÚ IYÀRÁ ÒKÈ PÈLÚ INÁ MÉJÌ LÓRÍ WON. Oòkan “ dúró sórí Oòkan kan wón” (Iṣẹ Àwọn Àpọsítélì 2:3). Amò iná dúró fún odindi iná Ọlórun— ase re, àgbàrá àti and glory.

Nígbà ti mo bá rìnrìn àjò kárí ayé, won máa sábà béèrè lówó mi, “ Jòwó gbàdúrà fún mi; Mo fé àmì òróró yín.” ìbéèrè mi sí won nìyí? “Njé o ró pé tí mo bá fún ọ ní àmì òróró mi, èmi yíò lọ sílé làìní àmì òróró? Rárá kò ríbe.” Àmó níhin ní àṣírí nlá: Tí o bá gbà àmi òróró Reinhard Bonnke’s, o máa di èdà tí Bonnke. Jé kín so fún e:Mi ko fé èdà àmì òróró láti inú èdà mìíràn— àtìpé Olórun kò fé béè fún o.

Ti o bá fé mo ìwà Olórun, kan sáyẹwò ìsẹ̀dá. Àwọn ènìyàn tó wà láyé lé ní bílíọ̀nù méje àti àbọ̀, kò sí ìkankan tí òǹtẹ̀ ìka ọwọ́ wọn rí bákannáà, àti kò sí ewé méji lára igi tó ní irísí kanna. Kíni di? Nítorí Olórun kìí ṣe pidánpidán— Asèdá Ni. O n ṣèdá OJÚLÓWÓ nìkan, kìí sisẹ́ ẹ̀rọ idán. Iná lórí è yen jé tiwò nìkan tó jẹ pé a àmì orúkọ e sí. A dìídì ṣe fún ọ, a tí ṣe fún ìwọ̀ nìkan.Kò ní bá ẹnikẹ́ni mu. Kò sí enikéni lórí ayé tó máa sin Ọlọrun gééle bí ìwo n se sin! O yàtò— béè náà ni àmì òróró re!


Ọjọ́ 5Ọjọ́ 7

Nípa Ìpèsè yìí

Holy Spirit: Are We Flammable Or Fireproof?

Agbára àgbàyanu, tó ń jí òkú dìde ḿbẹ nínú rẹ. Ajíhìnrere Reinhard Bonnke ti ṣe àkọsílẹ̀ àwọn ẹ̀kọ́ tó nípọn nípa Ẹ̀mí Mímọ́ fún ọ àti wípé ó kọ àwọn Kókó Àgbàyanu nípa Agbára Ẹ̀mí Mímọ́. Ẹ̀kọ́ Ọlọ́jọ́ Méje yìí ma mú ọ ronú nípa Ẹ̀mí Mímọ́ àti wípé ó máa ru ọ́ sókè láti ní ìgbàgbọ́ nínú agbára Ẹ̀mí náà tó ń gbé nínú rẹ.

More

A fẹ́ dúpẹ́ lọ́wọ́ ẹgbẹ́ CfaN Kristi Fún Gbogbo Àgbáyé fún ìpèsè ètò yí. Fún àlàyé síwájú síi, jọ̀wọ́ lọ sí: https://shopus.cfan.org/collections/reinhard-bonnke/products/holy-spirit-are-we-flammable-or-fireproof-english