Jésù: àsíá Ìṣẹ́gun waÀpẹrẹ
Nínú ìwé Jẹnẹsisi, satani dọn Efa wo nípa ṣíṣe lòdì sí Ọrọ Ọlọrun ati ètò Rẹ, ìfèsì rẹ sí fá ẹsẹ àti ikú wá sínú aiye. Nínú ìwé Samueli keji Dáfídì yàn láti dúró ní ilé "ní àkókò tí àwọn ọba lọ jagun", tí o sí rán àwọn míràn lọ dipò rẹ̀. Bí Dáfídì ba wà níbití Ọlọrun pé sí, kòní dá nìkan wà lórí òrùlé láti rí Bátísébà. Yíyọrísí rẹ nipé ìwà àgbèrè àti ìpànìyàn wọ inú ìtàn ìgbésí ayé Dáfídì. Bẹ gẹgẹ, nígbàtí Ẹ̀mi Mímọ darí Jésù lọ sí aginjù nínú ìwé Matiu ori kẹrin, satani gbìyànjú láti dọn Ọmọ Ọlọrun fúnra rẹ wo nípa títọka sí ìwé Mímọ
Ọ̀tá ní o ñsisẹ́ nínú wa láti jẹ kí a ṣẹ sí Ọlọrun, ètò Rẹ, àti èròngbà Rẹ fúnwa. Tí satani bá dẹkùn fúnwa nínú ìbáraẹnisọ̀rọ̀, èyí jẹ́ ọnà tí o ñyọ̀ tí o sí le mú rúdurùdu àti ìrora wá sí ìgbé ayé wa. Ṣugbọn Jésù mọ bí o tí ṣe rí láti ní ìrírí Ìdánwò láti ṣe lòdì sí Ọlọrun-ni òdodo, O tí lá gbogbo irú Ìdánwò tí a ní kọjá- O sí tí ṣe ọnà fúnwa láti kọ tí kí a sí rìn ní òmìnira. Nígbàtí Jésù sàn gbèsè ẹsẹ wa lórí àgbélébu, O fọ agbára ọta kuro lórí ènìyàn. Nítorí ìrúbọ Rẹ, a kò tún sí labẹ àṣẹ satani mọ!
O ṣe pàtàkì láti ṣakiyesi pé rínrin nínú ìṣẹgun Jésù lórí idẹwo gbà àfọkàntẹ̀ tí o lọ́rìnrìn ní ọdọ wa. A níláti ni lọkàn pé ọta yíò gbìyànjú láti gbá ipinlẹ àtijọ padà ni ìgbé ayé wa ki a sì múra gírí láti wá lojufo, gbígbé àwọn ẹṣọ ro láti dáàbò bò ìgbésí ayé òmìnira wa nínú Jésù, kí a sí béèrè fún ìrànlọ́wọ́ Ọlọrun nínú idẹwo, kí a sí yí ara wa ká pẹlu awọn enia Ọlọrun tí yíò mú wa jihin isẹ wa. Àpọsítélì Pọọlù sọ nínú ìwé Efesu ori kẹfà pé a níláti gbé ihamọra Ọlọrun wọ, kí a bàá lè dojú ìjà kọ àwọn àrékérekè èṣù
Bí a ṣe ñtẹ̀síwájú nínú ọsẹ Ajinde yi, ẹ jẹki a rán ara wa létí pé Jésù tí gbá agbára kúrò lọwọ ọta wa nínú aiyé. Fi Efesu 6:10-18 gbàdúrà ki o sí gbé ihamọra Ọlọrun wọ ni ọjọ gbogbo. Dúpẹ lọwọ Ọlọrun agbára tí O fí fúnwa láti gbé ní òmìnira kúrò nínú idẹwo, kí o sí bèèrè lọwọ Rẹ̀ bóyá àwọn ibìkan tún wà tí ìtanijí rẹ kú diẹ kí ó tó tí o sí fẹ àmójútó tí ó péye. Òun yíò rán ọ lọwọ láti ṣe àmúyẹ ibi tí o ní àlébù àti láti fún ọ ní agbára láti dúró ṣinṣin láti lè dojú ìjà kọ ọta. Nínú ìṣẹgun Jésù idẹwo kò ní borí wa
width="100%" src="https://d233bqaih2ivzn.cloudfront.net/daymedia/CACHE/images/originals/2019/04/12/Youversion_Easter_Day_6/c5ea004261cf8733aa1a5f2fc55891d1.jpg" />Victory Over Temptation
We don’t need anyone to remind us that temptation is real—never before has so much of the world been so readily available at the click of a button. But do we ever stop to think about the specific ways satan tries to tempt us? We need to understand how temptation works, so we can better defend against it.
In Genesis, satan tempted Eve by questioning God’s Word and His motives, and her response brought sin and death into the world. In 2 Samuel, King David chose to stay at home during “the time when kings go off to war,” sending others to fight in his place. If David had been where God had called him to be, he never would have been alone on the rooftop to see Bathsheba. As a result, we see infidelity and murder introduced to David’s story. And when the Spirit led Jesus into the wilderness in Matthew 4, satan tried to tempt the Son of God Himself by quoting Scripture.
The enemy is constantly working to make us question God’s Word, His plan, and His heart for us. If satan can trap us in this conversation, it’s a slippery slope that will introduce chaos and pain into our lives. But Jesus knows what it’s like to experience the temptation to question God - in fact, He’s gone through every kind of temptation we experience - and He’s made a way for us to reject it and walk in freedom. When Jesus paid the debt of our sin on the cross, He broke the power of the enemy off mankind. Because of His sacrifice, we are no longer subject to satan’s authority!
It’s important to note that walking in Jesus’ victory over temptation takes great intentionality on our part. We need to acknowledge daily that the enemy will try to take back his old territory in our lives and respond by staying alert, building up safeguards to protect our life of freedom in Jesus, asking God for help in the face of temptation, and surrounding ourselves with Godly friends who will hold us accountable. The apostle Paul said in Ephesians 6 that we need to actively put on the armor of God so that we will be able to stand against the devil’s schemes.
As we continue this Easter week, remind yourself that Jesus has rid the enemy of his power in your life. Pray through Ephesians 6:10-18 and put on His armor every day. Thank God for giving you the strength to live in freedom from temptation, and ask Him if there are any areas where your alertness level needs to increase. He will help you identify where you’re weak and empower you to take your stand against the enemy. In Jesus’ victory, you will not be overcome!
Download today's image here.
Nípa Ìpèsè yìí
Nígbà tí a bá ń ṣe ayẹyẹ ajinde, à ń ṣe ayẹyẹ ìṣẹ́gun tí ó ga jùlọ nínú ìtàn. Nípa ikú àti ajinde Jésù', ó borí agbára ẹ̀ṣẹ̀ àti isà òkú títí láí, àti gbogbo ohun àbájáde wọn, ó sì yàn láti pín ìṣẹ́gun náà pẹ̀lú wa. Ní ọ̀sẹ̀ ayẹyẹ yii, jẹ́ kí á wọ inú díẹ̀ nínú àwọn odi agbára tí ó ṣẹ́gun, ṣe àṣàrò lóríi ìjà tí ó jà fún wa, kí o sì yìín gẹ́gẹ́bíi àsíá ìṣẹ́gun wa.
More