Jésù: àsíá Ìṣẹ́gun waÀpẹrẹ

Jesus: Our Banner of Victory

Ọjọ́ 4 nínú 7

Ìṣẹgun Lórí Ìbẹrù

Ní aiyé òde òní, tí ó kún fún àwọn ìròyìn búburú tí à nkà tí à sì ńgbọ lojojumọ, ó rọrun láti mú irẹwẹsi dé bá wa pẹlu ìbẹrù. A bẹrù ohùn tí a kò mọ tàbí àjálù, irora àti àdánù, ohùn tí a kò ní láti mú wá ṣe àṣeyọrí. Ṣugbọn nígbàtí Olùgbàlà wa tí kò ní ẹbi lọ sórí igi àgbélèbú láti sàn gbèsè ẹsẹ wa, Ó fí ifẹ alailẹgbẹ hàn fún wa. Agbára ifẹ yẹ ṣẹgun ohùn gbogbo tó rọ̀ mọ́ ẹ̀ṣẹ̀ àti òkùnkùn ní aiyé, ìbẹrù sí jẹ òkan gbógì níbẹ pẹlu.

Ìwé Jòhánù kínní 4:18 sọ fúnwa pé "ifẹ pípé a máà lé ẹrù jáde". Nípa fífi ifẹ tí ó pegedé hàn lórí igi àgbélébu, Jésù gba ìsẹ́gun lórí ẹ̀rù. Òun pé wà láti jẹ alábápín ìṣẹ́gun náà. Ó fẹ kí á gbé ní àlàáfíà ninu àyà, èrò, àti ọkàn wa pẹlu. Ṣugbọn ó kú síwalọ́wọ́ láti gbà àti láti rìn nínú agbára ìsẹ́gun ìfẹ́ Rẹ̀. Nínú ìwé Róòmù 8:38, àpọsítélì Pọọlù sọ pé ó dá òun lójú wípé kòsí ohun tí ó lè yà wá kúrò nínú ìfẹ́ Ọlọrun. Àwa pẹlu, ní ànfàní ìgbọ́kànlé tàbí ìfọkàntẹ̀ tí ó lọ́rìnrìn nínú ìfẹ tí Ọlọrun ní fúnwa kí á sí dúró nínú àlàáfíà tí ìfẹ́ yẹ pèsè. Bí àkókò kàn bá wa tí a bá ní iyèméjì lórí ìfẹ tí Ọlọ́run ní síwa, gbogbo ohun tí a nilati ṣe ní kí á kọjú sí àgbélèbú.

Nígbàkúgbà tí ẹrù bá wá sí ọkàn wa, á ní ojúṣe láti ṣe, jẹki àkànṣe ìṣẹgun ifẹ Jésù wá sí ìrántí wa kí á sí gbagbọ pé Òún tí ṣẹgun fún àlàáfíà wa. Nígbàtí ó bá dàbí ẹnipe gbogbo nkan dojuru nínú aiyé wa, ẹ jẹki á dúró ṣinṣin lórí otitọ pé ìbẹrù kòní agbára lórí wa. Gbá àlàfíà láyè kí á sí tẹsiwaju ní ifọkanbalẹ pé ifẹ Rẹ dáàbò bò wá!

%" src="https://d233bqaih2ivzn.cloudfront.net/daymedia/CACHE/images/originals/2019/04/12/Youversion_Easter_Day_4/61df7d1f1625bd5cc56b6c90d6982155.jpg" />

Victory Over Fear 

In our world today, bombarded with news and surrounded by what seems to be an endless flow of bad reports, it’s easy to become overwhelmed by fear. We’re afraid of the unknown, afraid of pain and loss, afraid we don’t have what it takes to succeed. But when our blameless Savior took on the cross to pay for our sin, He showed us perfect love. The power of that love defeated all the side effects of sin and darkness in the world, including fear.

1 John 4:18 tells us that “perfect love casts out fear.” Through His ultimate display of love on the cross, Jesus claimed victory over fear, and He invites us to share in that victory. He wants us to live with peace in our mind, heart, and spirit. But it’s up to us to receive and walk in the victorious power of His love. In Romans 8:38, the apostle Paul said he was convinced that nothing could separate us from the love of God. We, too, have the opportunity to be unshakeably confident in God’s love for us and abide in the peace provided by that love. If you ever have a moment where you question the extent of God’s love for you, all you have to do is look to the cross.

When fear comes knocking, you have a choice to make: Let it overtake you, or remember Jesus’ victorious act of love and choose to believe that He has won the battle for your peace. When everything seems to be going wrong in your world, stand firm on the truth that fear has no power over you. Claim His peace, and walk forward in confidence that you are fully covered by His love!

Download today's image here.

Ọjọ́ 3Ọjọ́ 5

Nípa Ìpèsè yìí

Jesus: Our Banner of Victory

Nígbà tí a bá ń ṣe ayẹyẹ ajinde, à ń ṣe ayẹyẹ ìṣẹ́gun tí ó ga jùlọ nínú ìtàn. Nípa ikú àti ajinde Jésù', ó borí agbára ẹ̀ṣẹ̀ àti isà òkú títí láí, àti gbogbo ohun àbájáde wọn, ó sì yàn láti pín ìṣẹ́gun náà pẹ̀lú wa. Ní ọ̀sẹ̀ ayẹyẹ yii, jẹ́ kí á wọ inú díẹ̀ nínú àwọn odi agbára tí ó ṣẹ́gun, ṣe àṣàrò lóríi ìjà tí ó jà fún wa, kí o sì yìín gẹ́gẹ́bíi àsíá ìṣẹ́gun wa.

More

A fẹ́ láti dúpẹ́ lọ́wọ́ ọ ìjọ ti àwọn ilẹ̀ gíga fún pípèsè ètò yí. Fún ìsọfúnni síi, jọ̀wọ́ ṣe àbẹ̀wò:https://www.churchofthehighlands.com