Rin Ìrìn-Àjò Rẹ Láì Sí Ẹrú WúwoÀpẹrẹ

Èrèdí Ìrìn-àjò tó Fúyẹ́?
Kílódé tí a kò le tẹ̀síwájú láti máa gbé bí a ṣe ńgbé tẹ́lẹ̀? Kí n'ìdí tó fí yẹ ká jáwọ́ nínú gbógbó nǹkan wọ̀nyí kí a sì rín ìrìn àjò tó fúyẹ́?
Nítorí óré-ọ̀fẹ́ tà fún wà láti gbé àyé òmìnírá.
Nítorí ìgbéyàwó jẹ́ ifárájìn títí láí.
Nítorí ọ̀pọ̀ àwọn ọ́mọ́ wa yío dá òbí áwọ̀n kán.
Nítorí Ẹ́lẹ́dà óhún gbógbó ní ámọ̀nà wá.
Nítòri ọ̀kánkán nínú rẹ̀ kò jẹ́ tíwá.
Nítòri ẹ́lòmiran n fárápá ó sí nrí iwosan, pẹ̀lú.
Nítòri Ó kọ́kọ́ d'áríjì wa.
Nítòri ìtìjú jẹ́ àsán.
Nítòri ohun tí a ní tó wà.
Nítòri Ó tó fún wà.
Nítòri igbádùn ńlá ló jẹ́ fún wa.
Nítòri yío rọrùn láti tún yárà sí ípè Ọlọ́run.
Nítòri ìrìn ayérayé jínnà gán.
Nítòri à bí Jésù.
Nítòri ìdí yí ní Jésù fì kú.
Nítòri à jí Jésù dìde, Ó sí wí fún wà pé kà lọ̀ j'ìhìnréré Rẹ̀ fún gbógbó ènìyàn!
Jason, rín ìrìn-àjò tó fúyẹ́ nítorí — Jésù
Gbadura: O dárà, Ọ̀lọ́rùn, jẹ́ kí á jọ ṣe èyí. Jọ̀wọ́ fún mí ní agbára láti má ṣé ìyọ̀ndá. Mò fẹ́ kí Ò jé Adarí ayé mí. Mó fí gbógbó rẹ̀ gbẹ́kẹ̀lé Ọ̀. Àmín.
Àkọ́sílẹ̀ síwájú sí nípa fífi wàhálà sílẹ̀ àti gbígbékẹ̀le Ọ̀lọ́rùn .
Nípa Ìpèsè yìí

Ní àkókò pọ̀pọ̀sìnsìn ọ́dún Kérésì, ọ̀pọ̀lọpọ̀ wa ló máa ń fajúro nítorí wàhálà àti àníyàn tó jẹmọ́ ìbáṣepọ̀ pẹ̀lú ẹbí, làálàá ìṣúná, ìpinnu ìdágìrì àti ìjákulẹ̀ nípa àwọn ìrètí wa. Wàyì o, gbé ìgbésẹ. Mí kanlẹ̀. Bẹ̀rẹ̀ ètò Bíbélì Life.Church yí láti ní òye wípé ẹrù náà tó ń rìn wá mọ́lẹ̀ lè jẹ́ èyí tí Ọlọ́run kò rán wa láti gbé rárá. A ò bá jọ̀wọ́ ẹrù wúwo yìí. Jẹ́ kí a rin ìrìn àjò tó fúyẹ́.
More