Mí Ìdí Tẹ̀mí Sínu Ìgbéyàwó RèÀpẹrẹ

Breathe Spiritual Passion Into Your Marriage

Ọjọ́ 2 nínú 7

“Ó ń wá ayè to n bò”Béèrè lowo ara è: nínu ìgbéyàwó mi, ìgbà melo ni mó kó sínú ọ̀fìn ijà lori àwon ohun to jé pé, ni ìparí, wón ko ṣe pàtàkì rara? Melo nínú ìṣòro ìgbéyàwó ló lè yanjú ti tọkọtaya ba wulẹ̀ kà ìwàásù lori Gun lẹẹkan lósù papò?
Èyí kì í ṣe láti tẹ́ńbẹ́lú àwon ohun Ilẹ̀-ayé—kosi ìdí láti ṣe yén—o jé láti gbé àwon ohun órun ga. Jonathan Edwards kọ̀wé bí akéwì: “Àwon bàbá àti àwon màmá, àwon ọkọ, àwon aya tabi àwon omo, tabi ìbákẹ́gbẹ́pọ̀ pẹ̀lú àwon òrè ayé, ṣùgbọ́n wón jé òjìji; ṣùgbọ́n ìgbádùn Olórun ni kókó inú e. Àwon èyí jé àmọ́ ìtànyanran to fọnka, ṣùgbọ́n Olórun ni òòrùn. Àwon èyí jé àmọ́ odò; ṣùgbọ́n Olórun ni ìsun omi. Àwon èyí jé àmọ́ ìkán, ṣùgbọ́n Olórun ni òkun.”
Gbogbo èyí tumosi pé a ní-lo láti sise lori sàfiyèsí wa, àgbàyanu wa ohun to gbà wa lọ́kàn; àìjẹ́ bẹ́ẹ̀, a le mu gbogbo sàfiyèsí lori àwon ohun to kere (ṣùgbọ́n sise pàtàkì) sapá—gbígbígbìyànjú láti sunwọ̀n sí ijumọsọrọpọ wa, ko n bẹ̀rẹ̀ sini fi ìnáwó wa ni ètò, mu eré ìfẹ́ wa tutù àti ìmóríyá, áti bébé lo. A ní-lo láti rántí pé àwon èyí kì í ṣe ohun ti ayé àtipe wón kì í ṣe òpina. Sebi, bí Edwards rán wa létí, “Ti ayè wa ko ba kì í ṣe ìrìn àjò síhà órun, wón jé ìrìn àjò síhà órun àpáàdì.”tí ó ba fé ni òtítò láti gbé èyí, so àsoyé pèlú oko tabi aya rè àti/tabi àwùjọ àwọn òrè rè lóṣooṣù. E béèrè lowo ara yin: “Báwo ni ìrètí órun n se nipa lórí ònà tá à ń gba nifé ara wa, ònà tá à ń gba se tító àwon omo wa, ònà tá à ń gba ná owó wa, àti ònà tá à ń gba sàfiyèsí si àkókò wa?”
Báwo le n se gbé ìgbésí ayé lojoojúmọ́ iwo àti aya tabi oko rè ni ìrètí órun?
Ti o ba ṣeé ṣe fún o láti mu èrò ọkàn ayérayé e, bàwo ni èyí ma se le ṣàkóbá fun ìgbésí ayé ojoojúmọ́ rè
Ọjọ́ 1Ọjọ́ 3

Nípa Ìpèsè yìí

Breathe Spiritual Passion Into Your Marriage

A mu láti ìwé tuntun rè " Ifé Ayègígùn," Gary Thomas sọ̀rọ̀ sínu àwon ìdí ayérayé ti ìgbéyàwó. Kọ̀ọ́ practical ohun èlò láti ìrànlọ́wọ́ siṣẹ́ ọnà ìgbéyàwó rè sínu ìbáṣepò onímìísí, to n tànkálẹ̀ ìgbé-ayé tẹ̀mí si àwọn ẹlòmíràn.

More

A yòó fé láti dúpe lowo David C Cook fún ipese ètò yii. Fun ìsọfúnni síwájú sí, Jọ̀ọ́ bè eyii wò: http://www.dccpromo.com/a_lifelong_love/