Mí Ìdí Tẹ̀mí Sínu Ìgbéyàwó RèÀpẹrẹ

Breathe Spiritual Passion Into Your Marriage

Ọjọ́ 6 nínú 7

“Ti ṣe ìgbéyàwó moonki ”

Se kìí ṣe òótọ́ pé opo àríyànjiyàn ìgbéyàwó je àbájáde láti ìjákulè pèlú oko àbí aya wa? A fé jé kí wọn je nǹkan tàbí se nǹkan tàbí mú nǹkan àtipe wọn kò se tàbí wọn kìí ṣe, a káàánú arawa. A fé kí wọn nífẹ̀ẹ́ wa gégé bí Olórun se nífẹ̀ẹ́ wa. A retí pé kí wọn kan mò ígbà tí a ni ojó to le; láti mò pé a n pa iró nígbà tí a ba sowipé, “Máa da ara è láàmú. Kò kii se bàbàrà. Mi kò ní-lò ohunkohun to ṣe pàtàkì”; láti mò wipé a ní-lò wón láti ni lágbára tàbí fẹ́lẹ́fẹ́lẹ́, láti juwọ́ sílẹ̀ tàbí láti mú ìdúró, nítorí ohun ti a ní-lò wón láti se niyẹn. Ti wón ba nífẹ̀ẹ́ wa, wón yoo mò, sebi?

Ki a jé aláìlábòsí: Njé ó ko ronú tàbí ní lára nígbà mìíràn?

Àtipe ó mọ̀ pé o jé ẹrù ìnira to soro fun tọkọtaya ènìyàn, sebi?

Ṣùgbọ́n Kí ló màa se ti mo bá wá “ìgbéyàwó tí àlùfáà ajẹ́jẹ̀ẹ́ ìnìkàngbé”? Kí ló máa ṣe ti mo ba pinnu wipé mo máa gbára lé Olórun nìkan, ni retí fun ohunkóhun láti òdò aya mi sùgbón gbára lé Olórun pátá fun gbogbo àìní mi, títí kan ìmọ̀lára àti àìní àjọṣe?

Lẹ́yìn náà dípò ikórìíra si ohun ti aya mi kì í se, èmi yóò wá pọ̀ lápọ̀jù (ni ònà to dara) nípase gbogbo ohun kekere ti o nse. Èmi yóò kún fún ìmoore dípò ikórìíra.

Nje èyí kì í se déédéé ìdàkejì ohun tó ń ṣẹlẹ̀ in ìgbéyàwó? Nígbà tí o n fé enìkan àtipe o se ohun to dára fún ó, o ronú pé: O màa dára o! Ti mo bá ṣègbéyàwó pèlú e àtipe òun kó ni dé bèbè pàtó nípa fififúnni èbùn, o ro pé: èyí ni gbogbo ohun to rà fún mi? Ehen?

Ìdí nìyẹn tí mó fi fé “ìgbéyàwó moonki,” àwon àǹfààní to wá láti ṣègbéyàwó pèlú obìnrin onìwà-bi-Ọlórun, súgbón pèlú ìwà moonki, ni retí fun ohunkóhun, ni igbára lé Olórun, àtipe so wíwà ojúlówó ìmoore fún ohunkohun ti aya mi yan láti bù kún mi pèlú.

* Ṣe o ri iwa rẹ bí èyí to kún fún ìmoore, tàbí kún pèlú ikórìíra? Báwo ni nini “ ìgbéyàwó moonki”se jé ki ìbáṣepò rè dára sí pèlú oko tàbí aya rè?

Ọjọ́ 5Ọjọ́ 7

Nípa Ìpèsè yìí

Breathe Spiritual Passion Into Your Marriage

A mu láti ìwé tuntun rè " Ifé Ayègígùn," Gary Thomas sọ̀rọ̀ sínu àwon ìdí ayérayé ti ìgbéyàwó. Kọ̀ọ́ practical ohun èlò láti ìrànlọ́wọ́ siṣẹ́ ọnà ìgbéyàwó rè sínu ìbáṣepò onímìísí, to n tànkálẹ̀ ìgbé-ayé tẹ̀mí si àwọn ẹlòmíràn.

More

A yòó fé láti dúpe lowo David C Cook fún ipese ètò yii. Fun ìsọfúnni síwájú sí, Jọ̀ọ́ bè eyii wò: http://www.dccpromo.com/a_lifelong_love/