Mí Ìdí Tẹ̀mí Sínu Ìgbéyàwó RèÀpẹrẹ

Breathe Spiritual Passion Into Your Marriage

Ọjọ́ 1 nínú 7

“Olórun gẹ́gẹ́ bí Bàbá oko tabi aya-" O wà fẹ́rẹ̀ẹ́ bí ìkìlọ̀, àti ká sòótọ́, mo ní-lò oókan nìgbá náà. Mo jé oko ọ̀dọ́kùnrin, áti láàárín àkókò àdúrà to gbóná janjan, Mo rí i pé Olórun sọ fún mi ní tààràtà gan-an wípé lisa kì í ṣe ìyàwó mi lasan, súgbòn ó jé ọmọbìnrin Rè pèlú àtipe mo ní láti tójú rè bẹ́ẹ̀ gẹ́gẹ́.
Éyí jé àsìkò ìṣípayá fummi, átipe ipá ìjìnlẹ̀ òye yi dàgbà sí nígbà ti mo ní áwon ọmọ tèmi. Ti o bá fé láti wa lori apá rere mi, kàn dára si oókan lara àwon ọmọ mi.
ìjíròrò láàárín elẹ́rìí ti o bá fé mú mi bínú, kọjá sí ọmọ mi. Burú sí wón. Ìfúnpá mi ma ga sókè. Ní pàápàá tiwón ba dárúkọ rè nítorí ma gba kàkà bẹ́ẹ̀ kí o se rádaràda pèlú mi jù pèlú oókan lara omo mi.
Nítorí náà, nígbàti mo rí i pé mo ṣègbéyàwó pèlú ọmọbìnrin ’Olórun, átipe èyín ọbìnrin, ṣègbéyàwó pèlú àwon ọmọkùnrin Olórun—gbogbohun nípa bí mo ṣe wo igbéyàwó yípadà. Olórun ni ẹ̀dùn ọkàn nípa ìyàwó mi—ọmọbìnrin Rè—ní pàápàá ònà mímọ́ jù lọ àti ònà ítara jù bí mo ṣe ni ẹ̀dùn ọkàn nípa àwon ọmọbìnrin mi. Lójijì, igbéyàwó kí se nípa emi níkan mo àti ẹlòmíràn; o je pàápàá ìbáṣepò pèlú ítara olùfìfẹ́hàn ènì ké̩ta. Mo rí i pé oókan lara lájorí ìrísí ìjọsìn mi jálẹ̀ gbogbo ọjọ́ ayé mi ma bọlá fún Olórun nípase sise itọ́jú ọbìnrin to ma fi ígba gbogbo ma jé, ní okàn àtọ̀runwá Rè, “omọbìnrin kékeré Rè."
A nma gbó nígbà mìíran àwon pasito ṣàṣàrò lórí ipò jíjẹ́ bàbá tí Olórun, ẹ̀kọ́ ìsìn àgbàyanu àti òtító. Súgbòn ti o ba fé yí igbéyàwó rè padà, nawọ́ àfiwé yí àti lo àkókò die n sàsàro nípa Olórun gégé bí Bàbá oko tabi aya. Nítorí nígbà tí o ba ṣègbéyàwó pèlú onígbàgbọ́, O jé.
Se ó tile rò pé oko tabi aya rè gégé bí ọmọkùnrin/ọmọbìnrin Olórun? Báwo ní èyí se yí ìbáṣepò rè padà (pèlú nínu ìse àti íhùwàsi) pèlú oko/aya

Ìwé mímọ́

Day 2

Nípa Ìpèsè yìí

Breathe Spiritual Passion Into Your Marriage

A mu láti ìwé tuntun rè " Ifé Ayègígùn," Gary Thomas sọ̀rọ̀ sínu àwon ìdí ayérayé ti ìgbéyàwó. Kọ̀ọ́ practical ohun èlò láti ìrànlọ́wọ́ siṣẹ́ ọnà ìgbéyàwó rè sínu ìbáṣepò onímìísí, to n tànkálẹ̀ ìgbé-ayé tẹ̀mí si àwọn ẹlòmíràn.

More

A yòó fé láti dúpe lowo David C Cook fún ipese ètò yii. Fun ìsọfúnni síwájú sí, Jọ̀ọ́ bè eyii wò: http://www.dccpromo.com/a_lifelong_love/