Mí Ìdí Tẹ̀mí Sínu Ìgbéyàwó RèÀpẹrẹ
“E mã wá ìjoba Olórun na”
Ti iṣẹ́ pàtàkì wa láti ọ̀dọ̀ Kristi ni láti “wá ijoba Olórun na,” báwo ni ìgbéyàwó to nàṣeyọrí, èyí tín bọlá fún Olórun kò ní ni ààmì nípase iṣẹ́ pàtàkì? A kó sọ fún wa láti wá ni ákókò ìgbéyàwó tímọ́tímọ́, ìgbé-ayé alayò,àwon omo tón ṣègbọràn, tàbí ohunkóhun mìíràn. Jésù sọ fún wa láti wá ni ákókò ohun kan, àti ohun kan péré: Ijoba Rè àti òdodo Rè(àwon òrò méji yìí túmò àti fìdígbòdí ara wón, dá ìlépa kan to wópò). Ìgbéyàwó alàṣeyọrí kó wa satileyin nípase ìlépa ìjoba nìkan, súgbòn ni opo ònà ni ìlépa jé ohun to pọn dandan fún ìfẹ́ onígbòónára lẹ́yìn àjose tímótímó.
Ayé láìsí ète yìí, àtipe ìgbéyàwó láìsí ìdí yìí, yóò pàdánù opo didán gbinrin rè. “A ni òùngbẹ fún èyí lojọ́ òní: ifọwọ́ sowọ́ pọ̀ lapapó, ìdàpọ̀, ń ṣiṣẹ́ bí ẹgbẹ́ àwon to n gun àpáta, gòkè lónà góńgó ohun táa fojú sọ́nà fún, àti nígbà naa rọ̀ mọ́ araawọn ni òpin ojọ́ naa. Olórun ti gbìn òùngbẹ yí jinlè nínú gbogbo tọkọtaya tiwón ti ṣègbéyàwó.Ó ju òùngbẹ fun ipò kìíní nínú ìdíje lo.Ó ju òùngbẹ láti sèdá ayé tuntun lo.Ó jé òùngbẹ kéta, òùngbẹ láti se ohun pàtàkì lapapò. Ni ìbámu sí òrò Olórun, àwa dara pọ̀ láti se iyàtọ̀. Àwa ṣègbéyàwó fun iṣẹ́ pàtàkì kan.”
Wíwà ni"ìgbéyàwó fun iṣẹ́ pàtàkì kan” lè sọ agbára opọlọpọ ìgbéyàwó dọ̀tun nínú èyí tí ó jé pé àwon tọkọtaya ronú pé àwon jìyà láti owo àìní ìbámu; ìfura mi ní wipé opọ awọn tọkọtaya yí pàápàá jìyà láti owo àìní ìdí. Àwon òrò ti Jésù fífún ẹ́nì kọ̀ọ̀kan ní Matthew 6:33 jé kódà bóyá otítò ní ìgbéyàwó. Nígbà tí a bá gbé ayé wa fúnni, a rí i. Nígbà tí o bá darí àfiyèsí wa níta ìgbéyàwó wa, a mú ki ìgbéyàwó wa gún régé sí i.
<>*Sé ìgbéyàwó rè jé oókan pèlú iṣẹ́ pàtàkì? Báwo ni ìwo àti oko tabi aya rè lè túbò gbé ìgbésí ayé iṣẹ́ pàtàkì gégé bí tọkọtaya ni ẹ́kùn-ún-rẹrẹ?Ìwé mímọ́
Nípa Ìpèsè yìí
A mu láti ìwé tuntun rè " Ifé Ayègígùn," Gary Thomas sọ̀rọ̀ sínu àwon ìdí ayérayé ti ìgbéyàwó. Kọ̀ọ́ practical ohun èlò láti ìrànlọ́wọ́ siṣẹ́ ọnà ìgbéyàwó rè sínu ìbáṣepò onímìísí, to n tànkálẹ̀ ìgbé-ayé tẹ̀mí si àwọn ẹlòmíràn.
More