Mí Ìdí Tẹ̀mí Sínu Ìgbéyàwó RèÀpẹrẹ

Breathe Spiritual Passion Into Your Marriage

Ọjọ́ 7 nínú 7

“Yàtọ̀ sáwọn ìyókù”

Ẹ jẹ́ kí fi àsọjáde láti àlùfáà ọ̀rúndún-kọkàndínlógún Horace Bushnell ni èdè ti igbéyàwó: “Kósi tọkọtaya tiwón tí ṣègbéyàwó ti a pè láti jé èmìíran. Olórun ní àwon ètò fún tọkọtaya tiwón tí ṣègbéyàwó gégé bí Ó ní tọkọtaya; àti, nítorí náà, Kó béèrè lae pé kí wón se wíwọ̀n ayé wón nípa tọkọtaya ki tọkọtaya mìíran.”

E juwọ́ oókan lara ààbọ̀ tọkọtaya to ṣàrà ọ̀tọ̀ sílẹ̀. Kosi tọkọtaya mìíran to ni ẹ̀bùn yín, àwon àìlera yín, ìtàn yín, akínkanjú yín, àwon omo yín, ìpè yín. Òmìnira ńlá wà ni itẹ́wọ́gba ìdánimọ̀ tọkọtaya wa gégé bí o se jé: A lè lágbára ni apá eyìí,ni àìlera ni iyén,wa níjàǹbá nibí, àìṣeé dá lu níbẹ̀, títayọ lọ́lá ni eyìí, sábà ṣubú ni iyén, súgbòn a jé tọkọtaya to ṣàrà ọ̀tọ̀ ti a pè jáde látowó Olórun láti se ìmúṣẹ ìdí ìpè wa to sàrà ọ̀tọ̀ ní ayè yi.

wani ìtùnú pèlú ìtàn rè, ìdánimọ̀ yín gégé bí tọkọtaya.Ni ídánilójú rè. Máse safiwé è. Wa ni ìgbàgbọ́ sí ìran to ṣàrà ọ̀tọ̀ ti Olórun ti fún yín (àtipe iyén jé òrò ìsodipúpò). Olórun kó ní-lò tọkọtaya mìíràn gégé bí oókan ti Ó tí dá tẹ́lẹ̀. Ó siṣẹ́ ìṣẹ̀dá púpò jú bẹ́ẹ̀ lo. Kàkà bẹ́ẹ̀, Ó fé àgbéjáde àtipe láti bù kún tọkọtaya to ṣàrà ọ̀tọ̀ èyí to jé èyín.

* Àwon tọkọtaya wo ni èyín safiwé ara yín pèlú? Ǹjẹ́ è ní ígbàgbọ́ pé Olórun gbé èyín méjèèjì sori ìrìn àjò to sàrà ọ̀tọ̀ fún ìdí Rè? Báwo le nṣe gbé èyí si?

Ǹjẹ́ ó gbádùn ètò kíkà yí? Ti o ba ribe, wolé láti jèrè èkún rẹ́rẹ́ iwé yiihere

Ọjọ́ 6

Nípa Ìpèsè yìí

Breathe Spiritual Passion Into Your Marriage

A mu láti ìwé tuntun rè " Ifé Ayègígùn," Gary Thomas sọ̀rọ̀ sínu àwon ìdí ayérayé ti ìgbéyàwó. Kọ̀ọ́ practical ohun èlò láti ìrànlọ́wọ́ siṣẹ́ ọnà ìgbéyàwó rè sínu ìbáṣepò onímìísí, to n tànkálẹ̀ ìgbé-ayé tẹ̀mí si àwọn ẹlòmíràn.

More

A yòó fé láti dúpe lowo David C Cook fún ipese ètò yii. Fun ìsọfúnni síwájú sí, Jọ̀ọ́ bè eyii wò: http://www.dccpromo.com/a_lifelong_love/