Mí Ìdí Tẹ̀mí Sínu Ìgbéyàwó RèÀpẹrẹ
“Fífìfẹ́ hàn sí èni ti kò ṣeé fẹ́ràn”
Èrè wa ma tóbi, Jésù so wipè, kií ṣeé ígbà ti a ba féràn àwon ènìyàn to féràn wa pada, ṣùgbọ́n nígbà ti a ba féràn “àwon aláìmoore àti àwon ẹ̀ní búburú.”gègè bí Olórun ń ṣe sé.
Ti ó ba ti fé oko tabi aya to jé oníwà-bí-Ọlọ́run jùlo, onínúrere jùlọ, ton fún ní jùlo àti ironú jinlè oko tabi aya tó ń gbé ilè áyé rí, ìyen ma jè èrè rè. Kò sí àfikún ìyìn ní àwon ọ̀run fún jijé igbádùn igbéyàwó jù ọ̀pọ̀ lọ. Nítorí náà ó ma ní àìmọye ọdún tó ma jé igbádùn dáadáa, nígbà tí ẹlòmíràn leé ma tọ́jú iya fún ayérayé.
Ti, fún àpẹẹrẹ, oko tabi aya rè foju tẹmbẹlu rè, ó le mawa mọrírì lori ayè yìí, sùgbón ojó a dé—Jésù ṣe lérí e!—nígbà tí ó bá rí Bàbá ọkọ tabi aya rẹ̀ tí òrun ní ojúkojú yóò si sọ si ó pé, “Ó féràn ọmọkùnrin Mi (tabi ọmọbìnrin) dáradára, Bó tilẹ̀ jẹ́ pé mo mó pé kó lóye ó láéláé bí wón ṣe bùkún fún un láti gbé ó ni iyàwó. Nìsinsìnyí, Jẹ́ kí fihàn è bí ñ mon ṣe lo gbogbo ayérayé mi mimuérè wá fún àwon to féràn nínu orúko Mi. Gbà èrè rè, wonu ìsimi rè!”
Ó rí bí a ṣe gbà gbọ́ pé ni ojò náà ìyípadà bí a ṣe túmọ̀ ohun ti ojò to dára níhìn-ín àti nísinsìnyí? A ma wá àǹfààní láti féràn, sìn ín, sàkíyèsí, níṣìírí, àti fi ìmọrírì han, kàkà bẹ́ẹ̀ nípa wíwà Júù lọ́kàn pèlú bí oko tabi aya wa ñ se féràn, ñ se sìnsín, ñ se àkíyèsí, ñ se íṣìírí, àti sise ìmọrírì si wa. Èyí mu íṣìírí fún àwon lara yin ti wón foju tembelua. E Jẹ́ kí a jẹ́ aláìlábòsí: àwon die lara òmùgọ̀ lọ́kọ tàbí aya yin. Mi ò ni lọ́kàn láti sọ̀rọ̀ àbùkù, súgbòn Bíbélì sowípé àwon òmùgọ̀ mbé, sebi? Ó dà bíi si mi, ẹnì kan gbódò gbé wón ní ìyàwó. Bóyá ó wá gbé oókan. Láti ojú ìwòye áyé, ìgbé-ayé òfìfo niyen. Láti ojú ìwòye ayérayé ó ni àǹfààní láti gbé ara rè sòkè fún amóríyá pàápàá ìmúṣẹ ìjíròrò ní àga ìjokòó ìdájọ́ tí Kristi.
* Báwo ni àwon àyọkà wọ̀nyí se mu amóríyá fún ó láti féran oko tabi aya rè síbẹ̀ nìgbà tí o lè? Báwo ni ẹ́kọ̀ọ́ yìí se ní ipa ní ọ̀nà tí ó ń gba gbé ìgbé-ayé ójoojúmọ́ rè pèlú oko tabi aya rè?
Ìwé mímọ́
Nípa Ìpèsè yìí
A mu láti ìwé tuntun rè " Ifé Ayègígùn," Gary Thomas sọ̀rọ̀ sínu àwon ìdí ayérayé ti ìgbéyàwó. Kọ̀ọ́ practical ohun èlò láti ìrànlọ́wọ́ siṣẹ́ ọnà ìgbéyàwó rè sínu ìbáṣepò onímìísí, to n tànkálẹ̀ ìgbé-ayé tẹ̀mí si àwọn ẹlòmíràn.
More