Mí Ìdí Tẹ̀mí Sínu Ìgbéyàwó RèÀpẹrẹ
“Igbára lé Àtọ̀runwá”
Ti ìgbéyàwó rè àti ebí ba dà bí àwàdà tàbí dà bí ẹni pé wón wa lenubodè ìdàrúdàpọ̀, kì í ṣe nǹkan kan wipé Olórun kò i tí rí i tàbí kò dáńgájíá láti rà eni padà. Ópọ̀lọpọ̀ ẹ̀kọ́ kristeni lòní wa nípa gbibèrú àwon èbùn"wa" sisunwọ̀n sí i, táléntí"wa",láti dé ọ̀dọ̀ góńgó"wa", síbẹ̀ ọpọ̀lọpọ̀ ẹ̀kọ́ àti àwòkọ́ṣe Jésù wa nípa jijuwọ́ sílẹ̀ si isé Èmí Mímó. E jé kí a gbà ìgbéyàwó láyè láti kó wa láti gbẹ́kẹ̀lẹ́ Èmí Mímó yìí. O tí jẹ̀rí ara rẹ̀. Ti a ba fé láti yí ìgbéyàwó wa padà, a gbódò kó ògo tí Igbára lé Àtọ̀runwá.
Olórun kóò ni pé láé láti se ohunkohun làìfún wa ni èyí to pondandan kí a baà lè pari isé náa. ó lè máje gbogbo ohun ti a rò pé a ní-lò, súgbòn yóò jé gbogbo ohun tí a ní-lò. Èyí ko tumo láti wí pé isé náa yóò rọrùn. Súgbòn Olórun ṣe lérí nípasè Isaiah, “Ó fún áwon ton sàárẹ̀ ni agbára, áti si èyí to se àìní ipá Ó se àlékún agbára é” (Isa. 40:29 NASB).
Mase kojá lori èrò yìí, nítorí ó ṣe pàtàkì:Isaiah 40:29 rò pé Olórun yóò pè wa si onírúurú isé fún èyí tí a se àìní agbára tó pò lori ara wa.
"Àsírí,” nígbà náà, sí ìgbéyàwó mímó lóòtító ni ènìyàn gan an, Olórun ṣe lérí Èmí Mímó. Nítorí Olórun jé irú Olórun ìbáṣepò (Ó rán Omo Rè láti bá àìní wa fün ìgbàlà pàdé), kò yẹ ko yà wá lénu pé Ó bá àìní wa pàdé fūn ìyípadà nípasè rirán ara Rè nínú ènìyàn tí Èmí Mímó Rè.
Níwọ̀n bí ìgbéyàwó ba jé oókan lara ìse ìjosín to jinlẹ̀ tí áwon onígbàgbó méjì le pín, Kò sé see láti sègbéyàwó ni ònà mímó láìṣi Èmí Mímó tó ń ṣiṣẹ́ ni ayé wá, ó n ràn wá lọ́wọ́ láti ni óye ohun to tumosì láti féràn, o sì fún wá ni agbára láti féràn, o n dáwa lebi nígbà tí a ba kùnà láti nifé, o so okàn wá dọ̀tun nígbà tí a ba n sàárẹ̀ nínú ìfé, átipe o n se didà ìrètí sílẹ̀ nígbà tí a ba rẹ̀wẹ̀sì nínú ìfé.
* Ǹjẹ́ o gbára lé Èmí Mímó láti fún o àti ìgbéyàwó rè lókun? Kí ni ipò pàtó níbi ti o se àìní agbára, súgbón a fún o lókun látọwọ́ Èmí Mímó?
Ìwé mímọ́
Nípa Ìpèsè yìí
A mu láti ìwé tuntun rè " Ifé Ayègígùn," Gary Thomas sọ̀rọ̀ sínu àwon ìdí ayérayé ti ìgbéyàwó. Kọ̀ọ́ practical ohun èlò láti ìrànlọ́wọ́ siṣẹ́ ọnà ìgbéyàwó rè sínu ìbáṣepò onímìísí, to n tànkálẹ̀ ìgbé-ayé tẹ̀mí si àwọn ẹlòmíràn.
More